ALORE

ALORE ALORE is a bi-lingual online Magazine that tells and reports facts about YORUBA culture; tradition and all other aspects of news reportorial...

ALORE is a BI-LINGUAL online Magazine that reports facts; entertainment; Politics; Crime, Metro news, Culture, Fashion; and all other aspects of news reportorial

03/04/2024

Wòlíì Faleyimu tun jade lẹẹkan sí i

02/04/2024

Barrytide ọmọ Alhaji Agba jáde tan o, bẹẹ ló sọ àṣírí nlá to kọ́ lọwọ Barusaati

Ilé-iṣẹ́ ALÓRE TV ki ninla nínú àwọn amuludun ti wọn n ṣe ayẹyẹ ọjọ-ibi loni-in, gbajumọ Olorin, Alhaja Mariam Akiiki àt...
01/04/2024

Ilé-iṣẹ́ ALÓRE TV ki ninla nínú àwọn amuludun ti wọn n ṣe ayẹyẹ ọjọ-ibi loni-in, gbajumọ Olorin, Alhaja Mariam Akiiki àti gbajugbaja sọrọsọrọ-pèdèpèdè, Dókítà Yọmi Matẹ Ifankaleluyah

30/03/2024

Wàási Sheikh Muyideen Abdul Yekeen niyi lojo ti Alhaja Asani ṣe ìtọrẹ àánú fawon opo ninu aawe Ramadan l'Ekoo

30/03/2024

Alhaja Kudiratu Asani ree o, lojo Ramadan Lecture e lEkoo

29/03/2024

Baba Gbelero tu aṣiri nla o, nipa ogun ayé ti won so pé o lè máa ba èèyàn ja

29/03/2024

Sikiru Ayinde Barrister ló ku o, ṣugbọn lójoójúmọ́ ni iṣẹ́ ọmọ Òdèé Sifawu n fẹ́ju si i!

29/03/2024

Wàhálà Gani Adams àti Sunday Igboho, àti bó ṣe kan Tayo Ayinde, Olori awon Osise ninu ijọba Babajide Sanwo Olu

24/03/2024

Sheik Lukman Musa Ọmọ Idunnu Delivers Lecture as Shaarẹ Community in Lagos holds annual Ramadan Treat ...live at Yaba, Lagos

21/03/2024

Èrò rẹpẹtẹ rèé níjọba ìbílẹ̀ Erékùṣù Èkó nibi ti Ọmọọba Taiwo Ajibade Oyekan ti ṣètò iranwọ onimilionu mewaa naira fún araalu... ayẹyẹ nínlá ni o!

21/03/2024

Orin Lefty Salami ni o!

Nigba ti àwon èèyan Èkó tun gbọ orin oloogbe Lefty Salami lẹẹkan sì i, bi wọn ṣe n jo, ni wọn n yọ gidigidi

20/03/2024

Oniluu Barrister nàá ti jáde o... asiri Nla ree latenu Samson Gíga, onisakara ọmọ Agbajelola

20/03/2024

Iyawo Prophet Sam Ojo naa jáde tan o.... bẹẹ ló sàlàyé bo ṣe diyawo Wòlíì táwọn èèyàn mọ kárí ayé

18/03/2024

Iṣẹ ajé ló gbé mí lọ sílùú Saudi... ṣugbọn ohùn ti oju ri rèé ki n too gba ominira

17/03/2024

Sheik Muritadha Baba-n-Bariga ló n sayeye o, Gbajumo olorin nní, Saoti Arewa ló n korin lowo

17/03/2024

Oriyomi ree o, toun naa korin lojo ti iyawo Ariyo Produsa tun rántí oko ẹ̀ lẹẹkan sí i

17/03/2024

Alhaja Aminat Akobi ọmọ, iyawo Ariyo Produsa ló n sayeye o...nise loju pé ti ẹsẹ pele daadaa

17/03/2024

Gbigba adura to wa ninu Osù Ramadan fún gbogbo ẹni to ba n fun ni lounjẹ àti mímú

16/03/2024

Nigba ti Olubadan ilẹ Ibadan, Oba Lekan Balogun tẹri gbaṣọ...

Olubadan Dies at 81Oyo State governor, ‘Seyi Makinde, on Thursday, announced the passage unto glory of the 42nd Olubadan...
14/03/2024

Olubadan Dies at 81

Oyo State governor, ‘Seyi Makinde, on Thursday, announced the passage unto glory of the 42nd Olubadan of Ibadanland, His Imperial Majesty, Oba Dr. Mohood Lekan Balogun, Alli Okunmade II.

The governor made this announcement in a statement on Thursday night, stating that Olubadan Balogun, joined his ancestors late Thursday evening at the University College Hospital (UCH), Ibadan.

Governor Makinde described Oba Dr. Balogun as an epitome of royal excellence and a great achiever, who made great marks on Ibadanland in just a little over two years of his reign.

He expressed his condolences to the Olubadan-in-Council, the Oyo State Traditional Council and the people of Ibadanland and Oyo State, praying to God to grant repose to the soul of the deceased monarch.

He said: “With total submission to the will of God, I announce the passing unto glory of our father, His Imperial Majesty, Oba Dr. Mohood Lekan Balogun, Alli Okunmade II, the 42nd Olubadan of Ibadanland.

“A mighty Iroko has fallen; Oba Dr. Balogun has joined the ancestors.

“In Kabiyesi, Ibadanland had a cosmopolitan and well-experienced Olubadan, who made indelible marks on the sands of history and achieved greatly within a short while.

“On behalf of the Government and good People of Oyo State, I condole with the immediate family of the Oba Dr. Balogun, the Olubadan-in-Council, the Oyo State Traditional Council and the people of Ibadanland.

“It is my prayer that God grants repose to the soul of our late monarch.”

Sulaimon Olanrewaju
Special Adviser (Media) to Oyo State Governor
March 14, 2024.

12/03/2024

Laarin Yomi Fabiyi àti Niyi Johnson ọkọ Seyi Ẹdun.. Obìnrin onitiata to bi ibeji fún un,.bo sè tun lọ ree o

11/03/2024

Awọn èèyàn yii sọ iriri nla ti wọn ni nigba ti wọn bá AL.WARIZ lọ sí Mecca fun iṣẹ Alalaaji

10/03/2024

Ìkìlọ ree o fún Sunday Igboho ati asiri ohun tí ìjọba Bola Tinubu wa se gan an fawon omo Naijiria

08/03/2024

Awọn Alálàájì tó bá ilééeṣẹ́ AL IRSAD TRAVELS AND TOURS lọ Saudi Arabia ti dé o, wọn ni, àṣepẹ́ làwọn ṣiṣẹ́ Umrah Hajj àwọn o!

08/03/2024

Yorùbá Nation ni o...awọn Fulani yìí tún ti dé o!

Wọn láwọn Fulani yìí tún ti bẹrẹ o, ni Sunday Igboho ba yari lẹẹkan sí i, bẹẹ ni Ọba Àlàyé yìí náà jáde tán pátápátá

07/03/2024

Wàhálà rẹpẹtẹ nílùú Ìbèṣè okun l'Ékòó... wọn sọ pé àwọn èèyàn yìí ló dẹ jàǹdùkú s'awọn ... bẹẹ lòkú sùn o!

05/03/2024

Awọn òṣeré tíátà Abeokuta láwọn yóò dun Yomi Fabiyi ninu o, bẹẹ ni Mercy Aigbe náà ṣèlérí rẹpẹtẹ

03/03/2024

Barry-showkey ọmọ Alhaji Agba tu àṣírí nla nipa 'kínni' ti Sule Alao Malaika lo ṣe ni fuji chamber

02/03/2024

Oke Arafa ree o niluu Mecca, nibi ti gbogbo Musulumi aye máa n péju si lásìkò iṣẹ hajj

02/03/2024

Oke Jabalitoro ree o ni Mecca

Address

39 Adebimpe Street
Lagos
234

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ALORE posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to ALORE:

Videos

Share

Category