Atọka Iroyin Magazine

Atọka Iroyin Magazine A Yoruba weekly magazine that covers politics,crime, entertainment, sports, culture and general News

22/11/2024

Emi naa ni idojukọ o,Kunle Afod sọrọ sita

Oṣerekunrin Adeniyi Johnson ni, ẹ gbagbe Bobrisky toripe o ti ba tiẹ lọ. emi Niyirisky de si i yin lọrun bayii
18/11/2024

Oṣerekunrin Adeniyi Johnson ni, ẹ gbagbe Bobrisky toripe o ti ba tiẹ lọ. emi Niyirisky de si i yin lọrun bayii

11/11/2024

Lẹyin iku alaga kansu Onigbongbo l'Ekoo, Sanwo-Olu ṣebura fun igbakeji alaga tẹlẹ, Ọnarebu Hassan Olufunkẹ Rekia ko maa ba iṣẹ lọ

Iru kileyi! Baale ile para ẹ, iyawo atọmọ rẹ nitori Trump to wọle l”Amẹrika
11/11/2024

Iru kileyi! Baale ile para ẹ, iyawo atọmọ rẹ nitori Trump to wọle l”Amẹrika

KA BI ALUBỌSA ṢE LE JẸ MAJELE FUN Ẹ
11/11/2024

KA BI ALUBỌSA ṢE LE JẸ MAJELE FUN Ẹ

Ọmọ iya ayu ni alubọsa , okun kan naa niwọn to waye, bi iṣẹ rẹ ṣe pọ to, o tun le fa ijamba fun ni bi eeyan ko ba mọ. Alubọsa t...

ONII NI AYẸYẸ ỌJỌỌBI ORIKADUN AGBA OṢERE NNI, MONSURU ỌBADINA FALA, Ẹ JẸ KA BA ALAYỌ YỌ
11/11/2024

ONII NI AYẸYẸ ỌJỌỌBI ORIKADUN AGBA OṢERE NNI, MONSURU ỌBADINA FALA, Ẹ JẸ KA BA ALAYỌ YỌ

Sinmi ati maa riran buruku si Tinubu,Guru Mahara Ji ṣekilọ fun Primate Ayọdele
08/11/2024

Sinmi ati maa riran buruku si Tinubu,Guru Mahara Ji ṣekilọ fun Primate Ayọdele

Olori awọn ọmọ ogun orileede Naijiria, Jẹnẹra Taoreed Abiodun Lagbaja,jade laye lẹni ọdun mẹrindinlọgọta
06/11/2024

Olori awọn ọmọ ogun orileede Naijiria, Jẹnẹra Taoreed Abiodun Lagbaja,jade laye lẹni ọdun mẹrindinlọgọta

05/11/2024

ÌRÒYÌN

1. Ìgbà díẹ̀ ló kù, a ma tó borí ìṣòro wa Tinubu

2. Ìgbésẹ̀ akin tí Tinubu máa bẹ̀rẹ̀ sí i mú ìgbà ọ̀tun bá oríléèdè yìí- Edun

3. Àarẹ pàṣẹ pé kí wọ́n tú àwọn ọ̀dọ́ tọ́wọ́ tẹ̀ lásìkò ìfẹ̀hónúhàn ìtako ìṣèjọba rẹ̀ sílẹ̀

4. Rògbòdìyán ìpínlẹ̀ Rivers n tẹ̀síwájú

5. Ẹ dẹ́kun láti máa sọ̀rọ̀ sáwọn aláṣẹ, Sultan fohùn ránṣẹ́ sọ́mọ Nàìjíríà

6. Ẹ máa ṣètò ìtura fún oríléèdè aláwọ̀ dúdú, Tinubu pàrokò ránṣẹ́ sílẹ́ Gẹ̀ẹ́sì

7. Iyanrìn ni wọ́n fi ṣèpìlẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú APGA, kò lè dúró- Umeadi

8. APC sí Atiku: Nnkan tẹgbẹ òṣèlú PDP bàjẹ́ ni Tinubu n túnṣe

9. EFCC fòfin gbé Okowa, wọn lo lẹ́jọ́ọ́ jẹ́

10. Bianca Ojukwu ṣèlérí láti ṣe àtìlẹyìn fún Tinubu

11.Mínísítà fún iṣẹ́ òde ní, Bílíọ̀nù Òjìlé lọ́ọ̀dúnrún náírà ni Nàíjíríà ma nílò láti tún àwọn afáárá ṣe

01/11/2024

O gbero

Ajọ EFCC ni, lootọ ni Idris Okunẹyẹ tawọn eeyan mọsi Bobrisky ti wa nikawọ wa, o lẹjọ jẹ.Orisun aworan yii:Lindaikejiblo...
01/11/2024

Ajọ EFCC ni, lootọ ni Idris Okunẹyẹ tawọn eeyan mọsi Bobrisky ti wa nikawọ wa, o lẹjọ jẹ.

Orisun aworan yii:Lindaikejiblog

Ile to dawo n'Ibadan,ọmọ marun ati ọmọọmọ mẹrin ni baba arugbo yii padanu. Ao nii ṣofo alẹ o
01/11/2024

Ile to dawo n'Ibadan,ọmọ marun ati ọmọọmọ mẹrin ni baba arugbo yii padanu. Ao nii ṣofo alẹ o

Iku pada rẹyin Agbako
31/10/2024

Iku pada rẹyin Agbako

Ọgagun Ọlasunkanmi Oluyede ni Aarẹ Tinubu yan lati dele de Ọgagun Lagbaja
30/10/2024

Ọgagun Ọlasunkanmi Oluyede ni Aarẹ Tinubu yan lati dele de Ọgagun Lagbaja

Ijọ Ridiimu jawe gbele ẹ fun pasitọ AdeBello,wọn lo n bawọn ọmọdekunrin ijọ laṣepọAdeBello: Irọ ni o, idanilẹkọọ nimo n ...
30/10/2024

Ijọ Ridiimu jawe gbele ẹ fun pasitọ AdeBello,wọn lo n bawọn ọmọdekunrin ijọ laṣepọ
AdeBello: Irọ ni o, idanilẹkọọ nimo n ṣe fawọn ọmọ yẹn o

Awọn ara igbahun da,Ta lo mọ orukọ agba oṣelu yii?
30/10/2024

Awọn ara igbahun da,Ta lo mọ orukọ agba oṣelu yii?

19/10/2024

Orúkọ ẹranko lédè òyìnbó àti Yorùbá

Lion – Kìnnìùn

Lizard - Aláǹgbá

Camel - Ràkúnmí

Donkey –Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́

Elephant - Erin

Wolf – Ajá igbó

Hedgehog –Túrùkú

Snake- Ejò

Cat - Olóńgbò

Horse - Ẹşin

Goat – Ewúrẹ́

Sheep – Àgùtàn

Ram - Àgbò

Deer - Èsúró

Monkey - Ọ̀bọ

Leopard – Àmọ̀tẹ́kùn

Tiger - Ẹkùn

Guinea pig - Ẹmọ́

Hamster - Asín

Dog - Ajá

Rabbit - Ehoro

Hare – Ehoro igbo

Tortoise –Ìjàpá; ahun

Fox – Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀

Grasscutter -Ọ̀yà

Buffalo - Ẹfọ̀n

Squirrel - Ọkẹ́rẹ́

Snail -Ìgbín

Fish -Ẹja

Wall gecko - Ọmọọ́lé

Turtle – Ahun odò

Lobster/prawn/crayfish - edè

Chameleon - Ọ̀gà

Iguana – Àǹtà

Hippopotamus – Erinmilókun; Erin-odò

Crocodile - Ọ̀nì

Alligator - Ẹlẹ́gungùn

Ki lorukọ eso yii?
02/10/2024

Ki lorukọ eso yii?

Address

Lagos

Telephone

+2348134048858

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Atọka Iroyin Magazine posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Atọka Iroyin Magazine:

Videos

Share


Other News & Media Websites in Lagos

Show All