14/02/2024
BERU AWON OJO MARUN WON'YI.
1. Beru Ojo Ola.
2. Beru Ojo Esan.
3. Beru Ojo Atubotan.
4. Beru Ojo iku.
5. Beru Ojo idajo.
BERU AWON ENIYAN MARUN.
1. Beru Eniyan ti o juu e lo.
2. Beru Eniyan ti o wa leyin e.
3. Beru Eniyan ti o ti ri tipetipe.
4. Beru Eniyan ti o sese pade
5. Beru Eniyan ti o mo iwole ati ijade re.
BERU OLORUN TORI OHUN MARUN YII.
1. Beru Olorun nitori Oun lo da o.
2. Beru Olorun nitori, Oun lo le se ohun gbogbo.
3. Beru Olorun nitori, Aseyohun ni Olorun.
4. Beru Olorun nitori kosi Ara ti ko le fi o da.
5. Beru Olorun nitori odo re lo ma pada si.
Nitori Awon nkan wonyi, kiyesi, ohun gbogbo ti o ba nse. Loni, nibi gbogbo ti o ba de, AANU Olorun a maa ba e lo... Amin Ni Oruko Jesu.
Perfection.......gloooory