02/05/2024
*****TOP OF THE CLASS 004*****
******TANI OLORUN MI, TANI EMI******
MOKI GBOGBO WA KU ASALE NINU ILE YII, IWAJU NI AO MAA LO (AMIN) TI ABA WO AKOLE TO WA NI OKE YII IBEERE NI, O WA JE IBEERE MEJI, O YE KI A SE NI OTOOTO NI SUGBON MO FE FI OKO KAN PA EYE MEJI NI, IBEERE MEJEEJI YII YIO JE KI AWON NKAN TI MO TI NSO LATI EYIN WA KO TUNBO YEWA DAADAA, MO TI KOKO SO WIPE OPOLOPO ENIYAN NI KO DA OLORUN TO NSIN MO, NITORI WIPE ELOMIRAN RO WIPE O A TO DA AYE ATI ORUN NI OUN NSIN SUGBON ESU NI OPOLOPO WON NSIN, MAA SE ALAYE RE FUN WA DAADAA O YA JE KA GBA IBI WOLE, KOKO BERE LOWO ARA WIPE TANI MI ??? NITORI WIPE ELOMIRAN KO DA ARA RE MO IYEN LO JE KI IDAAMU PO FUN-UN NINU AYE, BAWO WA LO SE FE DARA RE MO, JEKI A GBA IBI IBEERE YEN WOLE WIPE TANI MI ?, NKAN TI MO NGBIYANJU LATI SE NI WIPE MOFE KI IWO FUNRARE DA OLORUN RE MO LATI ARA IWO GAN, BEERE WIPE TANI MI? TI O BA WA MO ESI FUN IBEERE YII, TUN BEERE WIPE IRU EMI WO LO NGBE INU MI? SE EMI RERE NI TABI EMI ESU, DANDAN NI KI O MO IRU EMI TO NGBE INU RE, SUGBON ENI TI KO BA TUN MO IRU EMI TO NGBE INU RE O TUN BEERE LOWO ARA RE WIPE IRU IWA WO LOWA LOWO MI?? SE IWA RERE NI TABI IWA BUBURU??? DANDAN NI KI O MO IWA ARA RE😁 TO BA JE IWA RERE NI O NHU TI O JE 90% TI O SI JE WIPE IWA RERE YII INU OKAN RE LO TI NWA LATI MAA SE RERE, TI KII SE WIPE NITORI OWO TABI KARIMI, TI O SI NI ERI OKAN EMI RERE LO NGBE INU RE, OLORUN AWON olorun NI OLORUN RE DANDAN SINI KI O WA ONA TI O MAA GBA SUN MO OLORUN RE, SUGBON TI O BA JE WIPE OKAN RE KO FE LATI SUN MO OLORUN YII A JE SE WIPE OLORUN MIRAN NI OLORUN RE, KII SE GBOGBO ENI TI NHU IWA RERE NI ENIYAN OLORUN, KII SE GBOGBO ENI TI NHU IWA RERE NI EMI RERE NGBE INU RE, SUGBON TI O BA WA JE WIPE IWA BUBURU LO POJU LOWO RE TI IWO NAA SI MO BEE, EMI OKUNKUN EMI BUBURU EMI TI KO GBA TI OLORUN LO NGBE INU RE, EMI YII NAA LO MAA N TI E SI OPOLOPO AWON IWA BUBURU YII, EMI YII LO MAA NJE KI INU MAA BI E SI ENI TI NSE RERE, EMI YII LO MAA NJE KI O SADEDE KORIRA (HATE) ENI TI KO SE E, EMI YII LO MAA NJE KI O MAA SEPE FUN ENI TI KO SE E, SEBI IWO NAA MO WIPE IWO KII FORIJIN ENIYAN RARA EMI YII LOFA, BOYA WOLI NI E, TABI ALFA, TI IRU IWA YII BAWA LOWO RE, EMI BUBURU EMI OKUNKUN LO NGBE INU RE, OLORUN OKUNKUN OLORUN AWON IWIN ATI OLORUN AWON ALJAN-NU, OLORUN AWON OSO ATI AJE NI OLORUN RE, ENI TI ORUKO RE NJE LUCIFER, LUCIFER YII NAA LO NJE SATANI, KILO FA TI O FI JE WIPE LUCIFANI ORUKO RE TI O TUN WA NJE SATANI ?? ORO PO NIBE AO MAA SO IYEN NI OJO MIRAN, GBOGBO IWO TI O JE WIPE O KAN NFI ORUKO OLORUN ALLAH ENI TI TUN NJE JEHOVA BOJU NI IWA RE KO DARA, EMI IKA LO NGBE INU RE OLORUN OKUNKUN SATANI NI OLORUN RE OUN NAA SI NI O NJOSIN FUN O, se e nfi okan bami lo bayi?? GBOGBO EDA ENIYAN TO BA TI FERAN LATI MAA HUWA IKA, BI KI WON O TA ALORE TO WA LORI OKE LOFA, BI KI WON MAA SEPE FUN AWON OMO IJO, ALFA TO FERAN LATI MAA SA FIRAKU, SATANI NI OLORUN YIN, OUN NAA SI NI E NSIN, GBOGBO EMI TI EMI SATANI BA NGBE INU RE WON KII FERAN AWON ENIYAN OLORUN, GBOGBO IWO TI O MAA FI OLORUN ENIKAN GBA ADURA O JE SORA RE DAADAA NJE IWO MO OLORUN TI ENI NAA NSIN?? OPOLOPO ENIYAN TI EYIN NWO GEGE BI ENIYAN OLORUN NI WON KII SE ENIYAN OLORUN RARA AWON NAA SI MO WIPE AWON KII SE ENIYAN OLORUN, KI O TO LEE GBADUN OLORUN RE, DANDAN NI KI O MO ORUKO TI OLORUN RE NJE BEENI EMINI MO SO BEE FUN E,
NJE IWO MO ORUKO TI OLORUN RE NJE IWO MO ORUKO OLORUN RE ???? o ya comment,