Pepe Ariya TV

Pepe Ariya TV Advertise your product's or services on our program. For mor information, contact Abiodun Adesina on

12/03/2024

EYIN OLOSELU ATI IJOBA IPINLE NI ILE YORUBA ... EWU NBE LOKO LONGE O!!! EJE KA FURA O.

Afefe Iroyin kan n fe pe awon adihamora-ogun n ko ara won jo si inu igbo kan lagbegbe kan ni Ipinle Oyo. Igbo naa ni o so Ijoba Ibile Ogo-Oluwa, Surulere, ati Ibile Guusu- Ogbomoso po ni ipinle-Oyo.

Ati pe awon Adihamora-ogun naa n po sii lojoojumo ninu igbo naa. Ohun ti o se wa ni kayefi ni pe a*o omo oloogun Ile yii ni won n lo. (They are using Nigeria Army Uniform). Akiyesi ti eni se alabapade won so ni pe won foju jo awon ajagunta lati Orile-ede miran bii Nije, Mali, ati bebe lo. (ie they look like Machinery from Niger Republic, Mali, etc). Oko-ofurufu (Helicopiter) ni o nko won wa, bee lonko ounje, ohun ija oloro, ati awon nkan miran wa fun won nibe pelu.

Enikan to se Ode-Oyin kaakiri ni o sesi lu ja odo won ninu igbo naa, ti won si kilo fun pe ko gbodo s’ode wa si ibe moo lai. Won tile so fun pe awon wa sibe lati wakusa ni. (they claimed to be Miner, but they are not, for they are always in Nigeria Army Uniform).

A dara ki awon eso-alaabo gbe igbese ki inu igbo yii to di bawo nla fun awon onisunmomi, tabi awon ajinigbe bii ti awon ibomiran ni orile-ede yi. Ijafara lewu o!

Let's forward this message to our different watshap group until it reaches any of our leaders that has interest of the masses in mind like Oyo state Governor and all Peace Lovers.
E gbiyanju lati fi sowo si ori ikanni miiran t**i ti yoo fi de odo awon Ijoba ati awon olufe alaafia lagbegbe naa.
As copied!

Se looto ni isele Yi n sele nínú Igbo ti won juwe re ni ipinle Oyo Yi?

A nfe ki Awon agbofinro to pimpin isele yi.
Ile Yoruba ko ni di bubba fun awon Oni sunmomi o.

11/03/2024

Orin owe !
Ilu owe !!!
Lowe Lowe nilu Agidigbo !!!

Iwo ni mo nbawi, mo rano nise si Awon eeyan re,
Ki ODI le gboro lase ma nso loju Omo re.

Adisokan re ti poju lagbaja,
Gbogbo araye loo ti mun gẹgẹ bi ota re,
Gbogbo eeyan loso,
Gbogbo eeyan laje loju re,
Eeyan kankan ko nii se iru eyi, ko boju rere Olorun pade,

Here !
Wonfe pami o,
Hee, won ran Oogun si Awon Omo mi, ema je ki lagbaja Mon ibi ti mowa, !
O Waa sare t**i,
Isoro re si ntele o leyin,
Ile Alufa elebo, Ile Alufa oloogun, Ibe lo nsare ka,
Owo toye koo fi se rere, gbogbo re ni won ti feree gba tan, bee kosi isinmi kankan fun o,
Lojoojumo ni won npoko ibanuje fun o,
Ebo losan, etutu Loru, bee igbesi aye re ko Dan monran.
A powe powe,
A soju Abe Niko,
Sibesibe, oro Olorun ko ye o,
O nkirun looto, Sugbon ebo ati etutu lo nda gbogbo ise re nu niwaju Olorun.

Boba wue koo gbo,
Adisokan ati ebo sise kole je koo roju rere Olorun!!!

Dipo mimu gbogbo aye lota,
Oso ni lagbaja,
Aje ni tamedo, Iwo kose wo eyin wo,
Wo ese too da ni Koro toju eda kankan ko to,
Eyi too da Taye ri o too kagidi bori,
Olorun Eleda re loo da ese Yi si latara Awon eniyan,
Ese re lo nke tantan Lori re,
Ese lo so ijiya kale lati odo Oluwa Olorun re,
Boose se nsope lagbaja lo nse o, o tun ti nsafikun ibinu Olorun Lori re,
Boo se Nyan Awon eeyan Lodi,
Ibinu Olorun nposi Lori re,

Olorun Allahu lo da Osó,
Olorun Allahu lo da Aje,
Bi Iwo naa se wa koboko,
Too fi nna Omo re nigba toba se o,
Pasan lasan ni oso,
Koboko taa fi nse ibawi lawon aje,
Olorun lo nfi won na o,
Abi Iwo ti ri ibi ti egba ti gbera nile to wa nbani na Omo ti a ko fi na ri,
Egba ko lee funra re fi Ara re na enikeni,
Kilo wa se o to nberu egba?
Iwo kose beru eni to nfi egba na eeyan, too wa nberu egba lasan,
Se opolo re si nsise,
Se laakaye re si wa lalaafia?
Eetiri too fi wa nhuwa bi afofungbemun?

Boose nberu oso ati aje,
Ise Owo re lo buru Jojo,
O tise nkan itufu,
Loo se nkiye si ehinkule !

Booba fee gunle're niwaju Olorun re,
Imonran Yi ni koo gba:-
Ma moso maje Mon,
Ese re ni koo jewo fun Olorun re,
Koo wa tuuba peregede niwaju Olorun re,
Iro too pa pa fawon Omo re tito gee,
Iro too fi tu gbogbo ebi ka nile oko re,
Eyi too fi ba Ile baba re je,
Nitori asiri kan too Fe dowobo monle,
Wo iye agbada iro too ti ya kaakiri aye, boose ndagbada iro bo otito,
Bee lagbada nfaya, otito sa nyoju wota saa ni.
Abosi too se si oko, eyi too se SEBI oko re, eyi too se fun ore,
Jẹwọ aisododo re fun Olorun,
Ma se omii Mon,
Satunse si ona re,
Ile onile too tuka, nitori pe o fee di alase Lori won,
Se oti gbagbe pe, obinrin kii di BAÁLÉ lagbo Ile,
Mo ju lagbaja lo,
Emi loye ki nwa nipo ase,
Haa !
Ko le see se,
Boya nkan Yi naa lo fee se nile oko re, too fi ba Ile ola je?
O ma se o.

Bi eeyan kan ba nko e ni nkan miran yaro si eko eyi ti mo nko e Yi,
Ma dawon lohun,
Won fee so e dibii tiwon ni o,
Dabi Moti da,
Onile koriko toni konile dingi o bo SITA, kiwon dijo maa ju oko lu Ara won.

Oma se o,
O fami t**i ka sa le dijo maa yojule elebo ka, moni laa ko saaye,

Bee lotun fee fami bodi kajo maa dite Awon eeyan kaakiri, Mio gba,

O ni oso ni lagbaja, aje ni tamedo ma de odo re Mon, mo rerin muse, nitori Moti mo pe oro Olorun ko lapa laye re.

Mo gbiyanju t**i lati fi oro Olorun yee, ko ma gbo,
Kinlode ti emi ti Mio ki nsooguni ko sa fun toso taje?

O npemi ni adéjàá,
Lojo ti Moti ndeja,
Kokooko lara ota mi nle,

Ko Mon pe Amin Olorun nijinle Ife
O nbami sota,
O nfoko oro gbanko gba nko ranse,
Ko monpe, Oluwa ni alatileyin mi.

Looto ,
Bi emi tile nrin
Ni afonifoji ojiji Iku,
Emi ki yo beru ibi kankan,
Nitori Olorun nbe pelu mi.

Boose nbami sota,
Olorun Allahu lo nba binu,
Kosi si eni to le binu Olorun,
Ti yo latubotan ire.

Tori pe mo nife re, ni mose nbae soro yi, kiise pe koo ma baa Lemi kiiri laburu Mon, tabi koo ma baa ta ofa oro to nbe lowo re Simi.
Booba ro pe o ndogbon bewa ni, ayongaasi re, olopolo dudu afofungbemun 😛😁🤣

Oya bere lakotun, koo ma baa gunle're niwaju Olorun,
Koo le Baye Awon Omo re je koo to kuro Lori Ile.

Ebami gbe de etigbo re!
Boya yoo tie tun munra si ise laabi re
Ki oore temi le maa posi,
Boya yo ronu wo pa Iwa ibi da,
Kole baa doloriire.

Abere oro ni mo fi gunwon nidi,
Boba koju sio ta
Boba keyin sio ta,
Boba kuwo nikan, tun ero Ara a re pa.

Pon- UN laa se Okan
Bole soje ko soje,
Bole seje ko seje.

Amin Olorun nijinle Ife 😁😁

Eni ti mo farati tobi ju taye rorun lo.
Iyen like ki ngbominira kuro lowo toso taje toloogun Ika,
Eni to ni agbara ni mo feyin ti,
Emi ko beru Omo ole to npera re ni nkan gidi.

O feree Yeo na, nigba ti Iku ba Waa peo pe irin Ajo pada lo sile ti ya,
Nigba naa ni Ao si iwe akosile gbogbo bi ose lo aye re fun o,
Nigba naa Loro Yi yoo Yeo kedere,
Lojo imon amondaju,
Iba San koo Mon otito nisisiyi,
Ki O le roju rere Eleda re.

Moti Jise fun o,
Oro Yi yo si di ibalejo fun o,
Bi Iwo koba gbagbo nínú oro yi.
O maa dide laarin Awon alaimonkan,
Awon ope to Tako oro Olorun.

Igba die loku fun e Lori Ile,
Ojo ati pada sile ti feree pe.
Repent NOW ❗
🤣🤣🤣😁😁😁😁🤪🤪🤪

Let us be our brother's keeper !!!A Call for Action: Addressing the Neglect of Our Community's Roads (IBA, IFELODUN LOCA...
09/03/2024

Let us be our brother's keeper !!!

A Call for Action: Addressing the Neglect of Our Community's Roads (IBA, IFELODUN LOCAL GOVERNMENT)*

Dear Concerned body,

I am writing on behalf of the concerned residents of my beloved community (IBA) to express our deep disappointment and frustration with the current state of the roads leading to our town. As you are well aware, these roads have been neglected for far too long, and their condition is an utter disgrace. The roads are riddled with potholes, uneven surfaces, and a general lack of maintenance that makes traveling a treacherous and uncomfortable experience for all who rely on them.

The deteriorating state of our roads is not only an inconvenience but also poses serious safety risks for motorists and pedestrians alike. Moreover, these bad roads hinder economic growth and negatively impact the overall quality of life in our community.

It is disheartening that such an essential aspect of our infrastructure has been ignored, despite its critical importance to our daily lives.
As our elected Governor, Senator, House of Rep. And House of assembly you have a responsibility to ensure that our community's needs are addressed. We implore you to take immediate action to rectify the neglect of our roads and provide the necessary funding.

We understand that addressing this issue may require significant investment and planning. However, we believe that the benefits of improved roads, including increased safety, enhanced economic opportunities, and an overall better quality of life for our residents, far outweigh the costs.
In conclusion, we urge you to prioritize the repair and maintenance of our community's roads and to allocate the necessary resources to ensure their long-term sustainability. We trust that you will take this matter seriously and act swiftly to remedy the situation. We look forward to working with you to improve the wellbeing of our community and ensure that our voices are heard.

Sincerely,
Concerned indigene of IBA.

*Mobikita fun ilu mi ✍️*

As copied from Mr Lanre's post on WhatsApp.

26/02/2024

Ọdun 1966 ni wọn bi Herbert Onyewumbu Wigwe, niluu Port Harcourt, nipinlẹ Rivers.

26/02/2024

Ni bayii ti Sunday Igboho ti pada si Naijiria, inu mi dun, okan mi bale, emi naa le f'ayo pada wale bayii - Ojogbon Banji Akintoye f'oro ranse lati ilu Kutonu l'orile-ede Benin Republic

26/02/2024

Gege ti wọn gbe lori awọn mẹrin yii tẹlẹ ni pe awọn orileede yooku ko nii ba wọn dowopọ yala lẹka eto irin ajo, okoowo tabi eto ọrọ aje.

21/02/2024

It sounds like an insult but it's an undiluted truth ❗

*TRUMP HAS SPOKEN AGAIN. JUST THE TRUTH*

"DONALD TRUMP'S SPEECH ON "RISE UP AFRICANS".

*They are good in nothing else but making noise, dancing, marrying many wives, alcoholism, witchcraft, indulging in s*x, pretending in church, jealousy, fighting and complaining of bad leadership; but, yet refuse to take a decisive action and protest to remove the brigands from position of power.*

*Let us all accept the fact that the black man is a symbol of poverty, mental inferiority, laziness and emotional incompetence.To make the matter worse, he can do everything possible to defend his stupidity. Give them money for development and they will fight and create hatred and enmity for themselves. Drill oil wells for them and they will not have peace all the days of their life.*
*See, for instance, what's happening in Nigeria (a Country blessed with abundant resources), Southern Sudan, Malawi, DRC just to mention at few.*
*"This proves to anybody including a stupid fool that Africans do not know what they want. isn't that plausible"?*
*"They are like monkeys looking for already ripping banana all over the world!!!.*

*Therefore that the white man is created to rule the black man, Africans will always have day dreams.*
*And here is the creature (black man) that lacks foresight but only sees what is near him and still fails to know what to do"*
*A black man is stupid to the extent that he cannot plan for his life beyond a year. Therefore how can they develop and live longer.*

*"Corruption in the west (And China) is a big abomination, but in Africa, it's so huge that it is slowly becoming an acceptable way of life!!!.*(Shame, isn't it?)

*They sing and rejoice to their corrupt political leaders.They worship their scandal-ridden religious leaders like their gods. Lest you forget, these so called Africans are praising, dancing and praying for the people that have impoverished them,and who comes to hide their loot here.*

*Then which fool argues that the black man is not born a beggar, grows a beggar, looks a beggar, falls sick as a beggar and dies a beggar. this has been proven beyond rea*oning.*
*I wonder why even up to now most Africans still go to school by force, and those who are at school are are just drug addicts who don't know what took them there. This is a pregnant stupidity in Africa. The body of Africans is a very fertile ground for all diseases in the world because they don't fear even HIV/AIDS.*
*This leaves me with a question: Are our eyes created the same with those Africans? I hear there are still cultures in Africa that prohibit them from using latrines which is very annoying.*

*"They cried for independence but have failed to rule themselves". For sure being African is a very untreatable disease that even prayers are not enough.*
*They have minerals but they cannot do anything with it. Therefore let us (whites) go to Africa and pick what we can pick and leave what is of no use. Poverty is a disease to the whites, but to the blacks it is very normal.*

*"Look at what is currently going on in Nigeria National Assembly. Legislators amending the constitution to favor themselves at the expense of two (200) million Nigerians.

*"Majority of these legislators are treasury looters who are intellectually barren but using the ill gotten wealth to oppress the citizens of that great country".*

*"What a shame"!*
*Black people with black sense. The worst tragedy in Africa is that if you dare stand up and speak up for what's right, you may end up regretting.*
*"The few wise and open-minded Africans who have tried to educate these fools about civilization have met the worst.They have been pushed hard on the wall, they have been silenced and others have been killed".*
*Before I finish, let me tell Africans that before you jump and call me a racist, an anti-blacks or whatever term you may wish to use against me,1st tackle runaway corruption, dreadful terrorism, tribalism, poverty, unemployment, diseases, illiteracy, ignorance, and inequality, that have put your whole continent on the verge of collapse".*
*"Hate me or love me, I don't care.I know this is the plain truth which will never see the light of the day to the cowards that are afraid to be told as it is".*

*By- Donald .J. Trump.*

*PLEASE SHARE WITH EVERY AFRICAN AND POLITICAL LEADERS SO THAT AFRICA IN OWN TIME WILL EMERGE AN INDUSTRALISED CONTINENT TO PUT THE TRUMPS AND WHITE SUPREMACIST TO SHAME.*

*IF YOU READ THIS AND YOU ARE NOT CHALLENGED AS A HUMAN YOU ARE A BORN FOOL!*

18/02/2024

Won ni Gomina ti ipinle Boronu, Gomina Zulumu kede aawe olojo kan lati fi wa ojutu si isoro Nigeria ❓

Hee !
Awon eeyan ni Baba kan ti se irue ri ni Nigeria to pe gbogbo Alaafaa Jo, e maa sadua ki Olorun ka isoro Nigeria kuro nile,
But it's a sorry case, Ase Baba Yi han an ni isoro Nigeria,
Olohun ba gbo igbe MEKUNNU lati ori ite mimo re wa,
Loba pale Baba Yi mon,
Gbogbo Owo Nigeria to jiko pamon kaakiri aye, afefe ba nfe a*o to fi boo monle kaakiri, Oun naa ko roorun sun nínú ahamo Olorun, loba nfi ranse sile diedie.

Haa ododo Loro Olorun Allah,
Ijagudu lati ko oro aye Yi Jo,
Yoo le o kuro loju ona Olorun,
Bibeli ni :-
Asiwere nko oro Jo lai Mon eni ti yo na !
Bi baba Yi ba Mo pe oju Iku ti sun Mon eti Ile Oun, koba ma jig egbelegbe Owo to jiko,
Owo Omo Ajo na !
Iya re lomo adaje,
Opo eeyan loti na nínú Owo ti Baba jiko,
Loju aye re ati nigba ti ko si laye Mon,
Bonus lasan lowo re je fun awon to nna, biwon ba se aye 're,
Alaafia ni funwon,
Anagbe si ni gbogbo Owo too na funwon tiwon nna ni tiwon,
Iwo loo jiya Lori dukia to kojo laiberu Olorun Oba to seda re,
Here !
Ojo isiro !
Ojo ekun !!
Ojo isiro !
Ojo Eru jeje !!
Ojo isiro !
Ojo ipayinkeke!!

Mo danuduro Lori oro Baba Sèyídà to ki Ara re Mon nkan ebo,

Gomina wa
Ola wa
Gomina Zulumu
Se kiise pe oro Yi fee fara Pera?

Aawe melo ni Zulumu gba fun Nigeria towa npase aawe ojo kan fun gbogbo eniyan?
Ti MEKUNNU ba gbaawe ojo kan fun alaafia Nigeria, ibinu Olorun yo sokale sori opolopo oloselu Nigeria, nitori pe Awon ni isoro Nigeria, pupo nínú won lo nta eje eniyan sile, ibinu Olorun si nbe Lori ilu tabi ileto tiwon ba nta eje alaise sile.

Leyin aawe Yi, opolopo oloselu toje ota Olorun ni yo fara kasa bi MEKUNNU ba le gbaawe pelu adura pe ki Olorun ka isoro Nigeria kuro nile.
Oga wa !
Ola wa !!
Se eyin kosi nínú isoro Nigeria ?
Koro o ma baa dabi Sèyídà, to ki Ara re Mon ebo,
Tori ti mo feran Gomina Zulumu,
Ololufe Awon eeyan re ni,
Sugbon Kaa dogbon te Ara wa nínú,
Ookun kiikun koninu mon Mon inú Ara re,
Ni mo se nbeere pe,
Se eyin ko saa si nínú Awon ota MEKUNNU?
Beeba wa nínú won two lee wi funwa, eyin e saa dogbon lo formula dooji e😁😁😁
E Yaa kede aawe Arugbo fawon eeyan, dipo aawe eyi tee kede tele,😂😂😂
Nitori pe,
Awon life Kabiru o se enikookan o!
Olorun kosi Fe Iku else,
Bikose pe ko ronu piwada.

Eyin Adari wa!
Eyin ti Oba Aseda Yan ni Olori,
Eni to Yan yin nreti abo lodo yin,
Boti Wu kope to,
Yoo pada dabi iseju kan loju wa ni,
E si maa pada jise nle,

Boba koju sio ta!
Boba keyin sio yin nibon!!
Boba kuwo nikan,
Yaa tun ero Ara re pe !!
Boba buru tan,
Iwo nikan nio kù.

Just a word of advice ❗❗❗

02/02/2024
30/01/2024
30/01/2024
19/01/2024

NEWS RELEASE

OSUN GOVT RELEASES WHITE PAPERS ON CHIEFTAINCY COMMITTEE, ASSET RECOVERY, CONTRACT AMONG OTHERS

● APPROVES TASK FORCE ON RECOVERY OF GOVERNMENT VEHICLES

OSOGBO- 18/01/2024- Osunstate.gov.ng

Osun State government has today released six white papers, five on various committees which investigated issues raised by the executive orders issued by His Excellency, Senator (Dr.) Ademola Jackson Nurudeen Adeleke at the inception of the administration in November 2022, as well as White paper on Education Summit.

The White Papers earlier approved by the State Executuve Council were finally ratified after further review by a special committee chaired by Governor Adeleke in line with the Governor's promise to ensure due process, indepth consultation and compliance with the rule of law.

Among the white papers approved include those of Committees on Chieftaincy Matters, Contracts/MOU/Agreements review Committee, Solid Minerals Committee, Assets Inventory and Recovery Committee, Staff Audit /Appointments/ Promotions review Committee, as well as white paper on Education Summit.

On the report on the chieftaincy matters chaired by Honourable Bunmi Jenyo, the white paper overwhelmingly priotized compliance with legal requirements as a basis for final decisions.

By the report of the White Paper, all previous steps taken in relation to the installation of Aree of Iree and Owa of Igbajo stands nullified. And that all inclusive selection process (es) for a new Aree of Iree and Owa of Igbajo, respectively, should commence immediately.

Specifically on Aree of Iree Chieftaincy, the substantive chiefs are enjoined to withdraw their suit before the Court so as to allow for commencement of the selection process denovo in line with due process and tradition.

And on the stool of Owa of Igbajo the White Paper nullified the previous selection process which produced Prince Gboyega Famodun and directed an all inclusive selection process for a new Owa nominee.

On the disputed Akirun stool, the White Paper directed that the parties await the outcome of the case before the Court of Appeal. And that the stool remain vacant.

On other disputed kingship stools, the white paper further recommended compliance with the requirements of the law as in the Alawo stool where the government accepted the committee recommendation that the government should await the outcome of the pending suit before the Supreme Court.

The Government has directed the setting up of a task force for the recovery of government vehicles carted away by officials of the Gboyega Oyetola administration.

Meanwhile, the State Government has also directed the Ministry of Information and Public Enlightenment to publish the six white papers in the official government gazette.

Members of the public interested in acquiring and possessing copies of the white papers should approach the Ministry of Information and Public Enlightenment, State Secretariat, Osogbo.

Signed
Oluomo Kolapo Alimi,
Honourable Commissioner for Information and Public Enlightenment.

As copied

18/01/2024

Ọga agba UCH, Jesse Abiodun Otegbayo sọ fun BBC pe eeyan mẹtala ni awọn adoola ẹmi gbe digbadigba wa si ọdọ awọn lẹyin iṣẹlẹ naa.

18/01/2024

Super Eagles “no gree” fún Ivory Coast ní bí wọ́n dójú tàwọn ẹlẹ́gàn àti aronipin; àjànàkú Ivory Coast jẹ koríko

18/01/2024

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

18/01/2024
18/01/2024

Ede mẹjọ ọtọọtọ ni Adedeji Odulesi le sọ lọwọlọwọ bayii.

18/01/2024
😥😥😥😥😥😥😥😥Fori jinwa Olorun wa!!!
18/01/2024

😥😥😥😥😥😥😥😥
Fori jinwa Olorun wa!!!

Ọmọkunrin yii ni: Mo padanu ẹgbọn mi nibi iṣẹlẹ ibugbamu Ibadan, niṣe ni ifun rẹ fọn sita!

18/01/2024

O sele! Wolii Elijah Ayodele fee ko mosalaasi nla l'Ekoo

*O l'oun yoo yonda re patapata fun awon Musulumi

*O ni, Olorun ko ni esin kankan to yan l'aayo

18/01/2024
18/01/2024

Nigba ti BBC News Yoruba ṣabẹwo si ilu Oke-Ọdẹ lori iṣẹlẹ laabi ọhun, awọn ti iṣẹlẹ naa ṣoju wọn ṣalaye pe ni nnkan bi ago mẹfa abọ ọjọ Iṣẹgun ni awọn adigunjale ya wọ ilu Oke-Ọdẹ ti wọn si n rọjo ibọn.

17/01/2024

Nigba to n ba awọn eeyan sọrọ nibi ayẹyẹ naa, Ọba Frederik ti oju rẹ leroro fun omije sọ fawọn eeyan pe oun maa jẹ ọba ti yoo so awọn eeyan pọ fun ọjọ iwaju.

17/01/2024
17/01/2024

Nnkan bii agogo mẹjọ alẹ ku iṣẹju diẹ ni iṣẹlẹ naa waye lọjọ Iṣẹgun.

17/01/2024

O sele! Ofin odun 1999 ti a n lo ni Naijiria yii ko s'ise mo o, e je ka pada si t'odun 1960

*Oloye Bisi Akande f'ariwo bo enu

17/01/2024

Obinrin kan sọ wi pe lojiji lawọn ọmọ oun sare wọle, ti ilẹ si mi t**i nigba ti ibugbamu ọhun ṣẹlẹ.

17/01/2024

Àwòrán agbègbè Adeyi Avenue, Bodija nílùú Ibadan ṣáájú àti lẹ́yìn ìbúgbàmù tó wáyé lálẹ́ ọjọ́ Ìṣẹ́gun.
Google Earth/ James Igbasan

17/01/2024
17/01/2024

Address

Osogbo

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Pepe Ariya TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Pepe Ariya TV:

Videos

Share


Other Broadcasting & media production in Osogbo

Show All