Bikeartv

Bikeartv Bikear TV is a new age entertainment channel dedicated to providing family-friendly content

News Coverage, Mass Communication, Radio and Television productions, Advertising and Marketing

https://youtu.be/s2aTjoT8N0s Ojo nla lojo ti Ebora Alaso funfun le mi nitori Eran Oya
01/05/2024

https://youtu.be/s2aTjoT8N0s Ojo nla lojo ti Ebora Alaso funfun le mi nitori Eran Oya

Baba mi fun mi ni agbara Asiri bibo to daju, Osole Ati Asiri ti won nfi nda Oja kale

ỌMỌNÍLÉỌmọnílé jẹ́ aláìlegbẹ láàárín àwọn alangba ìyókù. Èyí ni nípa àbùdá wọn, ipò wọn, igbe ayéwọn, bí wọn tí ń jẹun, ...
04/12/2023

ỌMỌNÍLÉ
Ọmọnílé jẹ́ aláìlegbẹ láàárín àwọn alangba ìyókù. Èyí ni nípa àbùdá wọn, ipò wọn, igbe ayé
wọn, bí wọn tí ń jẹun, bí wọn tí máa ń dún, idapo àti bí wọn ṣe máa ń bá ara wọn sọrọ̀ lèyí tí ó
sì yàtọ̀ síra wọn. Ọmọnílé jẹ́ ọkan lára ẹranko afàyà fà tó wà lórílẹ èdè àgbáyé àyàfi
Antarctica.
Wọn ní àwọn ẹyà ara tí ó ṣe pàtàkì kan èyí tí ń ṣe ìrànwọ fún àtiye wọn àti láti yaago fún àwọn
apanijẹ tàbí apanirun.
Àwọn ọmọnílé ni ìrù tí ń ṣe àǹfààní tó sì ń ràn wọn lọwọ́ láti gùn ẹka, bẹẹ̀ ni ìrù yìí dúró bíi
tanki epo fún wọn èyí tí wọn máa ń tọju ọra sí. Fún ìdí èyí, ọmọnílé o kìí jẹ kí ìrù wọn ó ṣòfò, wọn
a máa padà wá máa jẹ ìrù wọn tí ó bá gé tí anfaani rẹ bá wà. Bákan náà ni ìrù yìí mú kí ó rọrùn
fún wọn láti ba tàbí parẹ mọ agbegbe ti wọn bá wà. Wọn ni agbára láti gé ìrù ara wọn èyí ni lati jẹ
kí apanije tàbí apanirun rò wípé ọwọ́ ti tẹ wọn. Ìrù wọn tó gé yìí ni apanirun yóò fi rò wípé àwọn
tí borí wọn, èyí tí yóò sì fún àwọn ọmọnílé yìí láàyè láti sá lọ.
Irun àìfojuri tó wà ní ẹsẹ̀ àwọn ọmọnílé jẹ́ èyí tó fara mọ ojú ilẹ̀ tí wọn bá ń tẹ, tó sì fún
wọn ní ànfààní láti lè gun àwọn ibi tó dán pàápàá jùlọ orí àjà pẹlú irọrun láìjabọ.
Àwọn ọmọnílé o ní awọ ìbòjú èyí tí ó leè mú wọn ṣẹju, ńṣe ni wọn máa ń lá awọ fẹlẹ tó wà lórí
ojú wọn láti leè nu ojú wọn kì ó leè wá ní mímọ́ tónítóní atipe, kí ojú yìí leè ní omi kí ó má bàa
gbẹ furufuru.
Alẹ́ ni ọpọ nínú wọn sáábà máa ń ṣọdẹ nítorí agbára ìríran wọn tó ju téèyàn lọ lọnà bíi
ọtadinlewaa-le-looodurun. (350). Ọmọnílé féràn láti máa jẹ àwọn kòkòrò bíi aáyán, alantakun,
eṣinṣin, ekolo, ìdin tàbí ẹlẹtẹ.
A lè rí àwọn ọmọnílé ni àwọn àgbègbè bíi inú igbó, aginjù, àmọ́ níbi tí àwọn èèyàn bá ń gbé
ní ọmọnílé feran láti máa gbé ju nítorí oúnjẹ tí wọn máa ń rí jẹ. Wọn a máa dún tàbí hàn yálà láti
dáàbò bo agbègbè wọn ní tàbí tí abo wọn ba n wá akọ láti ni àjọṣepo.
Nǹkan ọmọkùnrin méjì ni akọ ọmọnílé máa ń ní, èyí tí ó bá sì wuu ni ó leè kí bọ ojú ara abo,
wọn a sì tún máa kí méjèèjì bọ ojú ara abo leekan náà nígbà mìíràn tí wọn ba fẹ́ . Àtèyìn ni akọ
ọmọnílé ti máa ń gun abo tí wọn ba fẹ ní àjọṣepo. Bẹẹ̀ ni abo ọmọnílé máa ń tọju atọ sínú ara
Temitope Beatrice

ALAGEMOAlagemo je ọkan nínú àwọn ẹranko tó wu ni jùlọ ní ìjọba ẹranko afàyàfà. Ó jẹ́ ẹranko tí wọnmọ̀ gẹgẹ́ bí èyí tí ó ...
02/12/2023

ALAGEMO
Alagemo je ọkan nínú àwọn ẹranko tó wu ni jùlọ ní ìjọba ẹranko afàyàfà. Ó jẹ́ ẹranko tí wọn
mọ̀ gẹgẹ́ bí èyí tí ó ní agbára láti yí àwọ padà. Ìrísí rẹ̀ jẹ́ èyí tí ó lágbára. Ó jẹ́ ẹranko
aláwọ̀ tẹẹrẹ tí ó sì ní ojú dídán tí ó leè fi rí gbogbo ohun tí ó wà ní àyíká a rẹ, níwájú, lẹyìn, tí kò
sì sí ohun kan tó pamọ́ fún irú ojú tí ó ní yìí. Alagemo jẹ́ kòkòrò ní pàtàkì ní ìṣèdá pẹlú ahón
gígùn tí ó jẹ́ ohun ìjà wọn láti mú ohunkóhun tí wọn fẹ́ jẹ. Ó jẹ́ ẹranko tí ó máa ń ní sùúrù
fún ohun ọdẹ wọn, kí wọn leè lo ahón ẹmọ wọn yìí láì tasé, tí ó fi jẹ́ pé, kò sí irú ohun tí ó bá ti
lẹ mọ́ ahọn yìí láti jẹ fún wọn tí ó tún le è jáde. Ẹranko yìí jé èyí tí ń mú ní rántí bí ayé ṣe wá ní
àìdọgba.
Àwọn nǹkan tí alagemo fi ń ṣe oúnjẹ ni àwọn kòkòrò bíi: ìrẹ̀ , Ẹlétẹ , eṣinsin, itù,, ekòló,
labalábá, alantakun àti bẹẹ bẹẹ lọ. Àmọ́ nnkan ti alagemo fi ń ṣe oúnjẹ yàtò síra wọn. Èyí dá
lórí tàbí níiṣe pẹlú irú ohun tí ó fẹ́ ìwọn rẹ̀ àti ibùgbé wọn.
A lè ka alagemo sí àwọn ẹranko ìgbẹ́ tí wọn máa ń gbé ní agbègbè ibi tí a gbé bí wọn bíi inú
igbó, aginjù, àti àwọn ìlú ẹdá abàmì mìíràn. A lè rí alagemo ni àwọn àgbègbè bíi Áfríkà,
Madagascar, Asia, àti díẹ̀ nínú apákan tí Gúsù ni Europe.
Ẹ jẹ́ kí á wo díẹ̀ nínú àbùdá tí alagemo ni
1. Ó jé ẹranko tí ó máa ń yí àwọ padà
2. Wọn ní àwọn ojú tí ó leè gbé pẹlu irọrun, èyí tí ó fún wọn ní ìwòye bíi otalelooodunrun
(360degree) Iríran láiyira padà
3. Àwọn ẹranko yìí ni ìrù kan tí ó jẹ́ pé nígbàkúùgbà tí wọn ba fẹ́ dimọ àwọn èka, irú yìí ni ó
máa ń ṣe iranlọwọ fún wọn láti lọ káàkiri àwọn igi àti ohun mìíràn èyí tí a lè fi kà wọn mọ́ ọga
nínú àwọn gungi-gungi
4. Alagemo ní àwọn ẹsẹ àmọja pẹlú ìka ẹsẹ tí ó lẹ papọ̀ , èyí tí ó fún wọn ní ààyè láti di àwọn
èka igi mú àti ojú ilẹ̀ mìíràn pẹlú ààbò tí ó péye fún wọn
5. Alagemo ní ahọn gígùn pẹlu itọ ẹmọ èyí tí wón máa ń lò láti mú àwọn kòkòrò kí kòkòrò tí wọn
fẹ́ pa jẹ
6. Wọn ní àbùdá yíyọ rìn, èyí tí kò ní fún àwọn ọdẹ ni àǹfààní láti rí wọn tàbí funra láti sá lọ
Èyí ni díẹ̀ tí a lè sọ nípa alagemo. Kò tán síbẹ̀ o, nítorí ó kù! ó kù! báyìí nibon ń ro. Ẹ tún
pàdé wa ní ìkànnì yìí lórí ètò ògbójú ọdẹ lọsẹ tó ń bọ. A gbáà ládúra pé ojú tẹ fi ń wò wá ò ní fọ,
bẹẹ̀ letí tẹ fi ń gbọ́ wa ò ní di. A ó máa lọ a sì máa de, tí a bá sì ń de, ẹyin naa là ó máa dé bá
láṣẹ Eledumare. Ire ó.
Ogundulu Beatrice Temitope
Bikear TV

I have reached 8K followers! Thank you for your continued support. I could not have done it without each of you. 🙏🤗🎉
24/11/2023

I have reached 8K followers! Thank you for your continued support. I could not have done it without each of you. 🙏🤗🎉

Ogboju OdeThroughout the history of the Yorubas, there have been many great warriors who have lived and passed on. Unfor...
26/08/2023

Ogboju Ode
Throughout the history of the Yorubas, there have been many great warriors who have lived and passed on. Unfortunately, due to lack of historical education in schools, particularly at the elementary level, many people do not know their founding fathers or how and when they settled in the land they found themselves in. It is crucial not to forget these brave men that paved the way for us today.

Preserving our cultural heritage is of utmost importance and should be highly encouraged. Witnessing individuals show th...
19/05/2023

Preserving our cultural heritage is of utmost importance and should be highly encouraged. Witnessing individuals show their support for their Obas in celebrating their gods and traditions brings me immense joy and pleasure. This act is not only beneficial for our current generation but also for generations to come. I commend the people of Ijero Ekiti for their unwavering love and dedication towards the 2023 Egungun ladunwo festival . It is through such efforts that we can ensure the preservation of our rich cultural heritage.

Preserving our cultural heritage is of utmost importance and should be highly encouraged. Witnessing individuals show their support for their Obas in celebrating their gods and traditions brings me immense joy and pleasure. This act is not only beneficial for our current generation but also for generations to come. I commend the people of Imesi Ekiti for their unwavering love and dedication towards the 2023 Egungun ladunwo festival. It is through such efforts that we can ensure the preservation of our rich cultural heritage. kudos to you all.

19/05/2023

Preserving our cultural heritage is of utmost importance and should be highly encouraged. Witnessing individuals show their support for their Obas in celebrating their gods and traditions brings me immense joy and pleasure. This act is not only beneficial for our current generation but also for generations to come. I commend the people of Imesi Ekiti for their unwavering love and dedication towards the 2023 Egungun ladunwo festival. It is through such efforts that we can ensure the preservation of our rich cultural heritage. kudos to you all.

13/04/2023
13/04/2023

Ogboju Ode|Mo yo Edun Ara ninu Alegba ti mopa|Ojo ti mokoju awon ogbontarigi Ole ni Oju aanu mi fo|Agbara ti Eledua fun mi koja oye enikeni, eni ba dan agbara wo lara mi yo dan tan

25/03/2023

Ogboju Ode| Asiri awon nkan ti ama fun Ogun ti Agbara Ota fi ndi asan|Ti ona fi nla fun wa|Orisa ti oto gboju le ni Ogun, Eni to ba moju re, kogbodo beru mo. nitori Asiwaju ati Olulana ni Ogun je

08/03/2023

Ogboju Ode:Iwin fi egba dara si emi ati ore mi lara|Opolopo ojo ni agbe lori Apata|Opolopo Oya loma npe ra won lodu. ogboju Ode gbodo ni Ogun to daju

08/03/2023

Ogboju Ode: Kosi Alagbara to le ba Iyawo Ogboju Ode sun lai fara pa,Eran ti ko ba ku nile, kole ku nigbo, Omode toba toju Agba nikan ni o pa eran nigbo

07/03/2023

Ogboju Ode|Eniyan yi pada di Igala ati Eran Ewuju lati damu wa ninu Aginju

09/02/2023

Ogboju Ode: Mo pade Iwin oloju kan lagbari |Iriri mi ninu Igbo Irunmole lagbara

26/12/2022

Ògbójú Ode|Owiwi eye Agba

Ògbójú Ode|Àwa Ode kò la ńṣe ogún fáwọn janduku
13/12/2022

Ògbójú Ode|Àwa Ode kò la ńṣe ogún fáwọn janduku

Oluode fe fi Ogun gba atokun eto, Opelope Iya monde.

Ogboju Ode: Nilu Ikirun, Iwin gbe Aja ati eran to mopa lo
11/12/2022

Ogboju Ode: Nilu Ikirun, Iwin gbe Aja ati eran to mopa lo

Ogboju Ode ni Egbo mi pelu, Koda Egbon mi bi omo to ni iru nidi bi eranko,

12/11/2022

Ogboju Ode| Ojo nla lojo ti mo segun Abami Irakunnungba ninu igbo

Address

Ayekale Road
Osogbo
230212

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Bikeartv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Bikeartv:

Videos

Share



You may also like