A fadurajagun segun tv

A fadurajagun segun tv adura loungba agbara ko

Permanently closed.
11/01/2024

Watch, follow, and discover more trending content.

25/12/2023
14/12/2023

OLOHUN MI JEKI ANU RE TETE WA MI RI OOO

يا رب يا الله olohun mi jeki anu re wa pelu mi ati gbogbo eyin  ololufe mi
14/12/2023

يا رب يا الله olohun mi jeki anu re wa pelu mi ati gbogbo eyin ololufe mi

13/12/2023
Iwo ti oun so oro mi layida mura si ki omon so to ri bi otin se ibaje.mi ni olohun gbe mi ga
30/11/2023

Iwo ti oun so oro mi layida mura si ki omon so to ri bi otin se ibaje.mi ni olohun gbe mi ga

22/11/2023

يا الله يا هويامن لاهو ا لاهو يا من لااله الا هو
Olohun mi jekin ga ju ota mi.lo ki olohun mi wo ola alikurianu

IWO OMO IYA MI LOKURIN ATI OBIRIN SUN MON BI KI OWA GBO ORO KEKERE KAN TI YIO SE O NI AHFANI     MO FE.KI OSORE FUN AWON...
10/11/2023

IWO OMO IYA MI LOKURIN ATI OBIRIN SUN MON BI KI OWA GBO ORO KEKERE KAN TI YIO SE O NI AHFANI
MO FE.KI OSORE FUN AWON EDA MEJI KAN NI NU AYE AWON EDA MEJI YI WON NI ORE LOWO BE NA SI NI WON NI ABURU LOWO TELE MI KALO OMO IYA MI

ALAKOKO .NI ORE ORE LEPA NI ORE SI LE SO NI DI OLORI RE
ONA TI ORE LEGBA PE NI
ORE TI OBA TIN SO ORO RE FUN TI OTUN WA GBO ORO TI OSO FUN NI IBO MI IRU ORE BE OLE PA NI
TA BI ORE TI OGBE O LESE TI OSO ASISE RE IRU OSE BE SO RE FUN OLE PA OO
TA BI ORE TI OSO GBOGBO TI INU RE FUN TI OUN SI FI ORO PAMON FUN OO SO RA FUN OLE PA OO ORE TI OBAUN LO SI IRIN AJO TI IWO YIO SO FUN PE ORE MI MON LO IRIN AJO TI.OUN BA SI LO KO NI SO FUN OO SORA FUN OLEPA O OMO IYA MI SO RE FUN ORE TI IWO.KO MON ISE TIN SE SO RE.FUN ORE TI.OMON IBI TON GBE SORE FUN ORE TI OMON IYA ATI BABARE SORE FUN ORE TI OMON AWON EYAN RE KANKAN OMO IYA.MI SO RE FUN ORE TI KO NI IYA WO TA BI OMO IWO OMO IYA MI OLOGBON OLOYE NI ORO MI LEYE OO

IBERE MI RE LABE ORO ISITI MI YI ..
SE ORE WA LAYE IRO ORE WO NI IWO JE

ELEKEJI NI OGA SI OMO SE OMO KEWU SI ALFA RE
LAYE TI AWA YI NA NI ATI RI OMO SE TI GBE OGA RE LESE IWO OGA SO RE FUN OMO SERE OO BENA SI NI IWO.ALFA.SORE FUN OMO KEHU RE TO RI NI AYE.TI AWA YI NA NI ATI RI OMO KEHU TIN GBE ALFA RE LESE GBOGBO IBI TI OBA TI RI PE OGA RE TI FE GA NI YIO MON WA ISUBU OGA.RE GBOGBO AYE TI OGA RE BA TIN GBA ISE TI OMU LO NI IGBA TIN KO ISE LOWO NI YIO MON LO SE IBAJE OGA RE LEYIN KI OLE GBA IYI NI IBE SE GBOGBO IWO OMO SE TI OSE IBAJE OGA RE KI OLE MON GBA IYI TI OWA KI OGA RE SUBU KI OWO SI MON GAN RAN TI OJO OLA RE BI OGA SE KO NI ISE TI OMON RAN TI PE OPOLO OGA RE NI OUNLO IMON OGA RE NI.OUN LO BI OTIN SE IBAJE OGA RE YI TI OGA RE KO MON SE MON TI.OGA RE WA DI ALAYI.MON SE MON LOJU RE LO.MON PE GBOGBO IMON TI OMON KI SE AGBARARE RARA OO BI OTI SE IBA JE OGA RE YEN OLOHUN RI OO

BI OGA RE KO BA MON SE MON LO NI TI ODI ELAYINON KAN MON
RATI PE OUN SI NI OGA RE OO OMO IYA MI KI OFI ORISE KI OFI ORUN SE FUN OMON EDA LAYE KODA KI OMON SE DADA SI WO.KI OSE RERE OGUN ODUN FUN WO KI OSE RERE OGBON ODUN FUN WO

NI OJO TI OBASE ASISE KEKERE KAN SI WON GBOGBO DADA TI.OSE YE NI WON YIO.GBAGBE SO RI ASISE IJOKAN TI OBA SE YE WON TI GBAGBE RERE TI OSE OOO

WO.OMO.IYA.MI OLOHUN NI KAN NI OBA TO PE KO SI ENI TI AO FE IDIRE TI AKO NI BA IGBE B
BI OBA NI OGA RE TO KO NI SE KO DA NI ENI OJOKAN BOWA TI WA TUN BA IWO MI.PADE LODO ELO.MI TI YIO JUTI OGA RE LO OOO OMO IYA.MI WOOO SO RA FUN WO KI OSI MON IRU ORO TI WA BAWON SO
OOO
MON FI IBI GIGARE HUN WON TI OBA FI HUN WO OLA BI WON YIO SE JAO BO NI WON YIO MON SAN OO KO DA BI OBA NI ASIRI KAN SO RA.LATI FUN WON TO RI WON NI IFE RE DENU OOO SORE FUN WON

KO SI ENI TO PE AFI OLOHUN MI NI KAN LOPE OOO TI KI SE ASISE OO OMO IYA.MI

TI OBA FI IBI TI OTI PA EJA HUN WON ONA BI WON YIO SE LE OO.KURO NI.ODO NI WON YIO.MON SAN OO

IBERE MI RE LABE ORO ISITI MI
SE OMO.SE WA ABI SE OMO KEHUN WA LAYE.MON

EMI.OMO YIN NA NI OO ALFA SURAJUDEEN OLUWALOGBON

ANU OLOHUN YIO MON WA PELU GBOGBO WA OOO

Address

Ondo

Telephone

+2347069446056

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when A fadurajagun segun tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to A fadurajagun segun tv:

Videos

Share

Category


Other TV Channels in Ondo

Show All

You may also like