13/06/2023
MO JÚBÀ AKÓDÁ AYÉ
Mo júba aseda oòrun
Mo juba Eledumare
Obángíjì, oba ògo, oba oníbuore
Ìbà re elédua
Mo júbà gbogbo ònkòwé gbogbo ayé
Mo juba eyin akowe-akéwi nílè yii pátápátá..
Orúko mi ni olabode Philip ( ònkòwé òdómokùnrin)..
Ekábo