10/11/2023
FEYIKOGBON
Isele yi sele ninu Idile kan
O sele wipe awon
Baba ati iya yi ma n jade ni l'aro kutukutu bi
ago marun (5am) lati wa jije
mimu lo
ago mokanla oru (11am) ni won ma n wole pada
inu ile ti won ko
funra won ni won
ngbe, ti won si gba telant si ile won
Awon oko ati iyawo yi ko ri
aye fun awon
omo won , kosi ajumo soropo
l'arin awon ati
awon omo ti won bi
ise ! ise !!
ise !!! ni
won nfi ojojumo aye won se
eniti won fi
ile rent fun ni o ma bawon
mojuto awon
omo won
o wa sele wipe won ni
omobinrin kan , omo yen pe omo
17 years
ni odun yi , sugbon omo yi ko
gba eko ile lati
odo baba ati iya re
omobinrin yi bere
si nse nkan alejo (Mestration )
nigbati omo yi ri
Nkan alejo re , o sofun iyawo
ayalegbe won
wipe oun ri eje loju ara oun ,,
hunmm ,,,,
iyawo ayalegbe yi so fun oko re
wipe omo
lanlord awon ti awon n mojuto ri
n kan
Alejo re ,,, oko arabinrin yi wa pe
omo Yii
wipe ,, ti o ba tun ti ri Mestration
re ni igba
mi ,, ki o ma mu awon pad eje
yen wa fun
oun ,, omo ti koti ni iriri aye , rii
omo yi ba
sope oun ti gbo ,,,, nigbati o di
osu ti o tele
omo yii bere si ni lo mu n kan
osu re fun
ayalegbe baba re ,, Baba ati iya
omo yi ti
won je Lanlord man yi ko mo
ohun to n sele
Afemoju ni won ti ma jade ,, oru
Oganjo ni
won ma wole ,, k'ama fa oro gun
bi omo yi
se bere Aisan niyen o , won bere
si ni gbe
kiri , omo yi bere si ni ru o bere
si ni gbe ,,
won o mo koko Aisan to nse
omo yi ,, omo
17 years
Awon obi omo yi wa
gbe omo yi
de ile iwosan kan ,, nibe ni omo
yi ti wa
jewo fun awon obi re wipe , oko
eniti o ma se
toju awon nigbati awon obi oun bati lo
ibi ise ma
n gba Nkan alejo oun lowo oun ,,,
Lesekese ni omoyi dagbere faye
Baba ati
iya omo yi wa n bi ara won lere
wipe ,,,, se
omo yi ti nse Menstruation ni ?? ,
eyin obi gidi
to n ka oro yi ,, se o ye ko ribe
sha? Se ti
baba koba tie mo wipe omo oun
ti nse nkan Alejo
se koye ki iya omo naa
mo? ,,,
Aye oni fi orowa se arikogbon aburu 🙏