Iroyin Awikonko

Iroyin Awikonko ...fún ìgbélékè òtítọ́ àti àwíjàre E le kan si wa fun ipolowo oja tabi alaye lekunrere.

Iroyin Awikonko je iroyin abinibi Yoruba ti ori ero ayelujara, tawon eeyan n kan saara sii bi a se n mu awon iroyin olokan-o-jokan wa.

Aṣiri ọna abayọ
04/04/2024

Aṣiri ọna abayọ

Idris Ọlanrewaju Okuneye ti ẹ mọ si Bobrisky ti wa lahamọ wa lori ẹsun titapa si ofin owo NairaAjọ EFCC sọrọ www.awikonk...
04/04/2024

Idris Ọlanrewaju Okuneye ti ẹ mọ si Bobrisky ti wa lahamọ wa lori ẹsun titapa si ofin owo Naira

Ajọ EFCC sọrọ

www.awikonko.com.ng

Ẹgbẹ ọmọlẹyin Kristẹẹni, CAN fi oye Ọtun Aṣiwaju Onigbagbọ ta alaṣẹ Adron Homes lọrẹ (Fọto) https://ift.tt/9CnL56Q
04/04/2024

Ẹgbẹ ọmọlẹyin Kristẹẹni, CAN fi oye Ọtun Aṣiwaju Onigbagbọ ta alaṣẹ Adron Homes lọrẹ (Fọto) https://ift.tt/9CnL56Q

04/04/2024

Ipenija nla ni mo ba pade nibi eto ti mo n ṣe.
Mo ro pe gbogbo rẹ ti d'opin ni, ṣugbọn Ọlọrun tun ṣi n jẹwọ ara rẹ

Kasnaty Sugar 1 sọrọ, ilẹ kun

Ọwọ Amọtẹkun tẹ Babalọla to fi oruka igbadi ji iyale ile gbe l'Oṣogbo https://ift.tt/vj6fBem
03/04/2024

Ọwọ Amọtẹkun tẹ Babalọla to fi oruka igbadi ji iyale ile gbe l'Oṣogbo https://ift.tt/vj6fBem

Ẹ ṣọra ki wọn ma ba a fi yin ṣetutu aje o - ọga ọlọpaa ipinlẹ Ogun kilọ fawọn ọlọmọge to n ṣiṣẹ aṣẹwo https://ift.tt/0sV...
02/04/2024

Ẹ ṣọra ki wọn ma ba a fi yin ṣetutu aje o - ọga ọlọpaa ipinlẹ Ogun kilọ fawọn ọlọmọge to n ṣiṣẹ aṣẹwo https://ift.tt/0sVkZBR

Gbogbo agbegbe to wa nipinlẹ Kwara ni yoo jẹ igbadun omi ẹrọ igbalode lasiko yii - Ijọba https://ift.tt/uc2IP0d
02/04/2024

Gbogbo agbegbe to wa nipinlẹ Kwara ni yoo jẹ igbadun omi ẹrọ igbalode lasiko yii - Ijọba https://ift.tt/uc2IP0d

Alaṣẹ Adron Homes, Aarẹ EmmanuelKing lo n ṣọjọọbi lonii ọjọ keji, oṣu kẹrin https://ift.tt/SotvKJ2
02/04/2024

Alaṣẹ Adron Homes, Aarẹ EmmanuelKing lo n ṣọjọọbi lonii ọjọ keji, oṣu kẹrin https://ift.tt/SotvKJ2

Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq ti ìpínlẹ̀ Kwara ṣàbẹ̀wò ààfin Oloro tiluu Oro, Aláyélúwà Ọba Oba Abdul-Rafiu Ajiboye Oyel...
25/03/2024

Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq ti ìpínlẹ̀ Kwara ṣàbẹ̀wò ààfin Oloro tiluu Oro, Aláyélúwà Ọba Oba Abdul-Rafiu Ajiboye Oyelaran to aa niluu Oro, ìjọba ìbílẹ̀ Irẹpọdun lónìí ọjọ́ Ajé.

www.awikonko.com.ng

Nitori ki n le jogun dukia iyawo mi ni mo ṣe fẹẹ fi majele pa danu - Ibrahim jẹwọ https://ift.tt/A8hSfZB
25/03/2024

Nitori ki n le jogun dukia iyawo mi ni mo ṣe fẹẹ fi majele pa danu - Ibrahim jẹwọ https://ift.tt/A8hSfZB

Aṣọ ni Gbenga jigbe l'Ado Ekiti, ki adajọ to ju sẹwọn pẹlu iṣẹ aṣekara https://ift.tt/x4J6DPe
25/03/2024

Aṣọ ni Gbenga jigbe l'Ado Ekiti, ki adajọ to ju sẹwọn pẹlu iṣẹ aṣekara https://ift.tt/x4J6DPe

Ọwọ Amọtẹkun tẹ Taofeek, ọmọ ọdun mẹrindinlọgbọn lori ẹsun ijinigbe l'Oṣogbo https://ift.tt/YlcXUm8
25/03/2024

Ọwọ Amọtẹkun tẹ Taofeek, ọmọ ọdun mẹrindinlọgbọn lori ẹsun ijinigbe l'Oṣogbo https://ift.tt/YlcXUm8

Ọjọgbọn Adaramaja di alakoso ẹgbẹ awọn alaga SUBEB ni Naijiria https://ift.tt/oBOTpiW
25/03/2024

Ọjọgbọn Adaramaja di alakoso ẹgbẹ awọn alaga SUBEB ni Naijiria https://ift.tt/oBOTpiW

Ẹ gbọ na, ta lo rẹwa julọ ninu awọn oṣerebinrin mẹrin wọnyii?Bukunmi OluwashinaAdebimpe AdedimejiWumi Toriọla Funmi Awẹl...
22/03/2024

Ẹ gbọ na, ta lo rẹwa julọ ninu awọn oṣerebinrin mẹrin wọnyii?

Bukunmi Oluwashina
Adebimpe Adedimeji
Wumi Toriọla
Funmi Awẹlẹwa

Ẹgbẹ oṣiṣẹ Naijiria lo ni ẹgbẹ oṣelu Labour - Awọn alakoso https://ift.tt/9CDgAYU
21/03/2024

Ẹgbẹ oṣiṣẹ Naijiria lo ni ẹgbẹ oṣelu Labour - Awọn alakoso https://ift.tt/9CDgAYU

Aisan iba Lassa tun pa ogun eeyan nipinlẹ mẹrindinlogun laarin ọsẹ kan - NCDC https://ift.tt/PTwvmYu
21/03/2024

Aisan iba Lassa tun pa ogun eeyan nipinlẹ mẹrindinlogun laarin ọsẹ kan - NCDC https://ift.tt/PTwvmYu

Oluwo tiluu Iwo, Ọba Emperor Abdulrasheed Adewale Akanbi Telu 1 ṣe iranti ayẹyẹ igbeyawo oun pẹlu oloro rẹ.O gbe oriyin ...
20/03/2024

Oluwo tiluu Iwo, Ọba Emperor Abdulrasheed Adewale Akanbi Telu 1 ṣe iranti ayẹyẹ igbeyawo oun pẹlu oloro rẹ.

O gbe oriyin fun olori naa, bẹẹ lo tun dupẹ fun aduroti.

K'ade pẹ lori, ki bata pẹ lẹsẹ, Ilu Iwo ko nii tu l'aṣẹ Edumare.

www.awikonko.com.ng

“Iya to bi mi lọmọ lo kọkọ dalẹ mi, ọmọ ọdun meji ni mo wa to ti gbe mi ju silẹ lọ” – Oṣerebinrin Bimbọ Ademoyewww.awiko...
20/03/2024

“Iya to bi mi lọmọ lo kọkọ dalẹ mi, ọmọ ọdun meji ni mo wa to ti gbe mi ju silẹ lọ” – Oṣerebinrin Bimbọ Ademoye

www.awikonko.com.ng

Address

35, Nawair-ud-deen Road, Isabo
Abeokuta

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iroyin Awikonko posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Iroyin Awikonko:

Videos

Share