Yoruba dun lede tv

Yoruba dun lede tv yoruba dun lede, yoruba dun lọrọ.
ẹwa wa lede wa. Ede wa niyi wa.

28/08/2023

Ẹkáàrọ̀ o ẹ́yin olòlúfẹ́ wa.
Kíni àńpè ní Ẹ̀BÌTÌ ní èdè gẹ̀ẹ́sì?

17/07/2023

Àáyá (the colobus monkey)
Òwe lẹṣin ọ̀rọ̀; Àáyá o gọ bi ka fa niru.
Alaye lẹkunrẹrẹ ti n hàn gedegbe loju opo YouTube.https://youtu.be/P2nvNGtsg9M

17/05/2023

Idẹ ( brass).
Ọ̀kan nínú àwọn ohun àlùmọ́nì tí afí n ṣẹ̀sọ́ ara. Àlàyé lẹ́kùńrẹ́rẹ́ wa nínú fọ́nrán yìí, tí ó sì ń hàn gedegbe lójú òpó YouTube.https://youtu.be/N7bbGHa32mg.

29/04/2023

Káà, àlàyé lẹ́kùńrẹ́rẹ́...

27/04/2023
Ẹni tí án gbéyàwó bọ̀ wá bá...Ìtumò rẹ àti ìdàkejì rẹ ...Ìdàkejì Òwe ojú ewé kẹfà ti hàn gedegbe loju opo YouTube.https:...
17/04/2023

Ẹni tí án gbéyàwó bọ̀ wá bá...
Ìtumò rẹ àti ìdàkejì rẹ ...
Ìdàkejì Òwe ojú ewé kẹfà ti hàn gedegbe loju opo YouTube.
https://youtu.be/6NOzEuT7kTo.

another set of contradictory proverb is explain in this video, watch and enjoy. Don't forget to subscribe 😘.

Akọni kìí gbadà lẹ́yìn! Bẹ́ẹ̀ni, sùgbón tí ogun bá di líle. Mọ̀jà mọ̀sá niyì akíkanjú..Ìdàkejì Òwe ojú ewé keje ti hàn g...
13/04/2023

Akọni kìí gbadà lẹ́yìn! Bẹ́ẹ̀ni, sùgbón tí ogun bá di líle. Mọ̀jà mọ̀sá niyì akíkanjú..
Ìdàkejì Òwe ojú ewé keje ti hàn gedegbe loju opo YouTube

This seventh episode explain another set of contradictory proverb. Akọni kii gbada lẹyin.( A true warrior doesn't get attack from the back).

Àáyá... Colobus monkey
07/03/2023

Àáyá... Colobus monkey

Òwe lẹṣin ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ lẹṣin òwe... tọ́rọ̀ bá sọnù, òwe la ó fi wa.
04/03/2023

Òwe lẹṣin ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ lẹṣin òwe... tọ́rọ̀ bá sọnù, òwe la ó fi wa.

Ìmọ́tótó borí àrùn mọlẹ̀, bọ́yẹ́ ti ḿborí ooruÀrùn ìwọ̀sí tinú ẹ̀gbin là wáIná ni ḿborí aṣọ ẹlẹ́gbin...
24/02/2023

Ìmọ́tótó borí àrùn mọlẹ̀, bọ́yẹ́ ti ḿborí ooru
Àrùn ìwọ̀sí tinú ẹ̀gbin là wá
Iná ni ḿborí aṣọ ẹlẹ́gbin...

15/02/2023

*A kì í ti ojú oníka mẹ́sàn án kà á*
Ọpẹ́ pàtàkì lọ́wọ́ Ọlọ́run ọba fún àṣeyọrí iṣẹ yìí. Ìdàkejì Òwe ojú ewé kẹwàá tí ń hàn gedegbe lójú òpó YouTube.
https://youtu.be/KxbMvE_UOig.

01/02/2023

Bí òwe bá jọ tẹni tá ò bàlè sọ̀rọ̀ ẹ̀rù ìjà ló ń ba ni, ṣùgbọ́n lápá Kejì yìyọ ẹkùn tojo kọ́...
Ìdàkejì Òwe ojú ewé kẹsán-án tín han gedegbe loju opo YouTube
https://youtu.be/GwPr9ocVByw.
Ẹkú àmójúbá....

23/01/2023

Ojú olójú kòjọ ojú ẹni, bakanna ojú kàn ní bímọ, igba ojú níí wò ó.
Ìdàkejì Òwe ojú ewé kẹjọ ti hàn gedegbe loju opo YouTube.
https://youtu.be/s5YAU4U3AAE.
Ẹdakun, ẹyin ololufẹ wa ebawa like, share ki ẹ sì comment sí Fidio yìí. Ẹjọ e bawa follow page wa tuntun lori Facebook.

Address

Nasr City
Cairo

Telephone

+201151337521

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yoruba dun lede tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Yoruba dun lede tv:

Videos

Share

Category