11/04/2024
Kosi Nkanti odabi Ife 💕 besini bi Ife se dun tooo (as z sweet) benani otunkoro(so bitter) ninu Ara/okan/emin pelu nitori ounroro Ni Ife jee bi Eyan kobani akiyesi nipa Ife,osese ki iru Ife be koku bi eefin.
👉Mon Pataki Ife SI Ololufe re
👉Mon Nkanti Ololufe nfe ATI Nkanti konife SII
👉Monse afojudi si Ife ooo,nitori agbara ojo Ni Ife,kosi eniti kolegbe loo.
👉Mon Asiko ti Inu Ololufe re ma ndun ATI Igbati obafemi privacy,kise GBOGBO igba Ni Ololufe re yiomabae se tom-jerry kiri.
Di asiko Miran,I remain ur boy Baba Baba Ife