Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV 08121124350

  • Home
  • Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV 08121124350

Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV 08121124350 Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV 08121124350, TV Channel, .

ỌNÀ ÀBÁYỌ SÍ FÍFÍ ÀRÀ KO ÒWÚ ÀLÀNTÁKÚN🕸🕸🕸Ti eniyan ba nfi ojú ko owu alantakun apere pe nkan rere  nbo wa fun eniyen ni ...
27/04/2024

ỌNÀ ÀBÁYỌ SÍ FÍFÍ ÀRÀ KO ÒWÚ ÀLÀNTÁKÚN🕸🕸🕸

Ti eniyan ba nfi ojú ko owu alantakun apere pe nkan rere nbo wa fun eniyen ni ti awon àgbàlagbà si fe di nkan na lowo lati ma raye wole ni, nitori eleyi tia ba gburo òòrè kàn sí ekeji kíá ma ṣe jeki inú dídùn yíò po lapoju dé ibi wipe ào má sare sọ sita toripe ti àwọn alagbara kan ba wa nibi tio ti so yen wọn lè bawa yi ore nà padà.

Ṣugbọn ide aye ni o ma nsele ju ti eniyan ba nfi oju ko jankariwo yálà lójú ọnà🛤, inú ilé🏠 tàbí ni ibikibi.

ỌNÀ ÀBÁYỌ☑☑☑
Oga gbigbe kan ao fi oga yi ko jankariwo ti oga na koni han ni ita mọ, ào gbé sínú apẹ pelu odidi atare Kàn ao jo papọ ao lọ kúnnà dàda ao fí fọ ẹkọ eléwé mú lẹkan nà. Yíò báwà lara mún lasẹ Èdùmàrè! Àmín Àṣẹ 🙏🙏🙏

ẸYỌNÙ ÁÀṢÍNÀ OWÓ 💰💰💰Epo Ọbọ tógbó Dàda ào jù sínú iná tí yíò pọn bí ẹyẹ nà, ao wà fí nkán yọ kúrò níbẹ ao wàfí sórí ọlọt...
23/01/2024

ẸYỌNÙ ÁÀṢÍNÀ OWÓ 💰💰💰

Epo Ọbọ tógbó Dàda ào jù sínú iná tí yíò pọn bí ẹyẹ nà, ao wà fí nkán yọ kúrò níbẹ ao wàfí sórí ọlọtá wà ao fí osún kàn lè lórí ao lọ papọ mọ àrà wọn tí yíò kúnnà Dàda ao fá sínú abọ ọlọmọrí kàn tiá bati lọtán ao dé pámọ

LÍLO RẸ
Ào bù diẹ tia bá fẹ lọ nínú rẹ níbẹ ao dá sínú abọ kàn ao bù èpò púpà síbí ìmúkọ méjì sí inúrẹ ao tún jó ẹyin òróró kàn sí tàbí ẹyin agric kàn ao ro pápọ ao gbé mú lẹkànnà.
Yíò báwà Lára mún lasẹ Èdùmàrè!
Àmín Àṣẹ!!!🙏🙏🙏

ÒGÚN ÌDÍ YÍYỌ (ORÓBÓ)Ewe Ogbè Orí Àkùkọ Àti Ewé Òmísínminsìn Pẹlẹbẹ ào lọ papọ ào dà sínú omí ọsán wẹwẹ tí ako fí omí lù...
21/05/2023

ÒGÚN ÌDÍ YÍYỌ (ORÓBÓ)
Ewe Ogbè Orí Àkùkọ Àti Ewé Òmísínminsìn Pẹlẹbẹ ào lọ papọ ào dà sínú omí ọsán wẹwẹ tí ako fí omí lù ao má mún ní gaasi k'ọkan.

Ewé Efinrin (Scent leaves) ao gbo sínú omí ào fí kafura pẹlẹbẹ (Camphor) sí ao má fí tanba (fífọ ORÓBÓ) na. Yíò báwà lára mún Làṣe Èdùmàrè! Àmín Àṣẹ 🙏🙏🙏

FÚN OBÌRIN TÍ NKÁN OṢÙ RẸ BÁ NLÁ MÍ               Ewé Làrá Púpá Tópọ Diẹ Ao Gbó Pẹlu Omi Agbọn Tópọ Diẹ Ao Ṣé Gbógbó Ṣàk...
25/01/2023

FÚN OBÌRIN TÍ NKÁN OṢÙ RẸ BÁ NLÁ MÍ

Ewé Làrá Púpá Tópọ Diẹ Ao Gbó Pẹlu Omi Agbọn Tópọ Diẹ Ao Ṣé Gbógbó Ṣàkítí Rẹ Dànù Ao Yọ Omi Agbọn Tíá Gbó Yí Sí Inú Íke Tàbí Ìgò Ọlọmọrí Kàn Ao Wà Bù Èpò Púpá Sí Ìnú Rẹ Obìrin Ná Yíò Má Yọ Mún Diẹ Diẹ. Yíò bá àrà Mún Ao Sí Gbọ Èsì Ayọ Làṣe Èdùmàrè! Àmín Àṣẹ!!!🙏

ÀTÚDÉ TÍ À FÍN MÚN ỌWỌ✋ÀIYÉ KÚRÒ LÁRÀÈèrù (ashes) ojú aró tia tètè bu ní ìdajì aifọhùn ní àgogo márùn ìdajì (5:00am)fẹ́r...
11/09/2022

ÀTÚDÉ TÍ À FÍN MÚN ỌWỌ✋ÀIYÉ KÚRÒ LÁRÀ

Èèrù (ashes) ojú aró tia tètè bu ní ìdajì aifọhùn ní àgogo márùn ìdajì (5:00am)fẹ́rẹ̀ ní ao ni ao bu èèrù yìí, èpò ọbọ diẹ àti àtà ìjọsìn diẹ ao gún àwọn èròjà Mẹtẹtá yí papọ mọ àrà wọn ao wà pò mọn ọṣẹ iwẹ ẹmẹtá péré. Ìdajì yẹn ná ní ao gún àwọn èròjà yẹn mọn ọṣẹ ọ, nítorípé àti gbọdọ gún tán kí àgó mẹfá (6:00am) òwúrò tó lù, ao tí gbọdọ wà èròjà yókú kalẹ láti àlẹ. Kahinkahin ẹyọkàn ní ào lò fí wẹ ọsẹ Mẹtẹtá yẹn

WÌWẸ RẸ
Ao wẹ ọṣẹ akọkọ ní àgó mẹfá aró, ao wẹ ọṣẹ ìkejì ní àgó méjìlá ọsán, ao wẹ ẹkẹta ní àgó mẹfá irọlẹ ao dáná sún kahinkahin tía fí wẹ yẹn ní oo. Yíò báwà làrà mún Làṣe Olòdùmàrè! Àmín Àṣẹ!🙏.

01/07/2022

ỌWỌ KÍ ÁWỌN ÀJẸ TÀBÍ ỌTÁ MÁ LÈ BÁ OGÚN JẸ MỌ ÈNÌYÀN LÁRÀ

Èsó lára pupà
Èpò Ọbọ
Odindi Atáré kàn
Ao kò gbogbo àwọn èròjà Mẹtẹtá yí sínú Àpẹ ìjóògún wà ao jo papọ ao lọ kùnnà dàdá ao rọ sínú ìgò fúnfún ao ma fí èpò pupà là ní ÀLÀLẸ sún.... Oṣe pàtàkì........ Yíò báwà làrà mún Làṣe Èdùmàrè! Àmín Àṣẹ!🙏

HAPPY DEMOCRACY DAY!!!R.I.P M.K.O ABIOLA KÁṢÍMÀWÒ.
12/06/2022

HAPPY DEMOCRACY DAY!!!
R.I.P M.K.O ABIOLA KÁṢÍMÀWÒ.

12/06/2022

IṢỌRÀ TÍ WỌ́N BÁ FÍ OGÚN DỌBÁLẸ FÚN WÀ KÒNÍ RÁN WÀ

Odindi Àkọ Alàngbà Àiyé kàn ao ge orí rẹ sọnu laye ao fí awọn àrà tó kù sínú Àpẹ ìjóògún wà pẹlú Odindi Atáré kàn ao jo papọ ao lo kùnnà dàdá ao wà fí sin gbẹrẹ Láti ẹyin ọrùn wà títí dé ìbàdí. Odaju a mọ ṣá Olòdùmàrè dájú jù lọ. Iṣẹ tí àwọn Ọba ìlú àtí èyán jankan jankan maùn nlo ní. Yíò báwà làrà mún Làṣe Edùmàre! Àmìn Àṣẹ!🙏.

NOTHING LAST FOREVER!!!This is the private bedroom of Alhaji Busari Adelakun in his home town in Lagelu Local Government...
22/05/2022

NOTHING LAST FOREVER!!!

This is the private bedroom of Alhaji Busari Adelakun in his home town in Lagelu Local Government area of Oyo State.

He was popularly known as "Eruobodo" ( the courageous one), was a Second Republic Politician in Ibadan.

The fear of Eruobodo was the beginning of wisdom in Oyo State then. He combined thuggery with politics and never hid his use of " juju".

In fact, he would boast and threaten to inflict his "juju" on opponents. He was feared. Even Uncle Bola Ige, then Governor of Old Oyo State, treated him with certain level of respect.

His fellow Commissioner in Oyo State suddenly died and Eruobodo was accused of killing him through metaphysical means and Eruobodo remorselessly retorted in Yoruba that he only tried him metaphysically without knowing that he was not a strong man in that area.

When he died in 1984 his bedroom was locked as nobody was bold enough to enter the bedroom. You can now see the occupants who entered without fear.

Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV Cares!!!

SEE HOW OVERTHINKING IS KILLING YOUOverthinking means to think too much about (something): to put too much time into thi...
22/05/2022

SEE HOW OVERTHINKING IS KILLING YOU

Overthinking means to think too much about (something): to put too much time into thinking about or analyzing (something) in a way that is more harmful than helpful.

Overthinkers may have trouble distinguishing between the fear of making a mistake, which leads to overthinking to the point where they make no decision, and a deep feeling that something is wrong.

Knowing if fear or intuition is guiding your behavior will help you get out of your head and take the next necessary steps.

SIGNS THAT YOU OVERTHINK

▶️Difficulty following along with and contributing to a conversation because you go over potential responses or statements time and again until the conversation has either ended or the window of opportunity for speaking was lost

▶️Continually comparing yourself to the people around you and how you measure up to them

▶️Focusing on worst-case scenarios either involving yourself or the ones you love

▶️Reliving past failures or mistakes over and over again and you're unable to move past them

▶️Worrying about future tasks and/or goals until they feel almost impossible to accomplish

▶️Reliving a past traumatic experience (such as abuse or the loss of a loved one) leaving you unable to cope with it

▶️An inability to slow down the racing of vague thoughts, worries or emotions

HOW TO OVERCOME OVERTHINKING

➡️Don't think of what can go wrong, but what can go right.

➡️Distract yourself into happiness. Meditate of positive outcome.

➡️Stop waiting for perfection.

➡️Accept your best. Celebrate your little wins

➡️Know you are a work in progress,you are not above making mistake.

➡️Be grateful for what you have as you wait for what you are expecting

Stop overthinking and act now.

Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV Cares!!!

22/05/2022

MAINTAIN RELATIONSHIPS WITH PEOPLE

People learn this late, they are too quick to cut off people.

It is childish and immature to pick offense at AND and EVERY provocation or perceived wrong and then start keeping grudges as a result..

Grow above it.

Someone did not invite you for their wedding, you pick offense with them.

Someone didn't wish you happy birthday, you pick offense with the Person

They didn't like your Facebook Post, you pick offense.

They didn't support you in a disagreement you had with someone, you pick offense with them.

They said No to your request, you pick offense and malice start like bicycle.

You asked them for money, they said they didn't have, you pick offense with them.

You are even keeping record of people who brought gifts to your wedding, so you can know who to pick offense with. Hah.

See,

Everyone is busy,

Everyone has their battles you are not aware of.

Those who you need help from are also looking for help.

Not everything is Personal and intentional

Not everyone hates you.

People will forget about you, not wish you happy birthday, promise you and fail you, not join your group, doesn't mean they don't like you, sometimes People are just caught up with their own personal lives, struggles, and human weaknesses/limitations.

Learn how to manage being disappointed by People and still be on talking terms with them, it'll save you a lot of UNNECESSARY grudges and beefing and save you some FRIENDSHIPS You'll need in Future..

Grow above offences!
Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV Cares!!!

Address


Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Fí Ọgbọn Rà Àíyé Gbé Àdítú Ọmọ Ọdúnfà TV 08121124350 posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

  • Address
  • Alerts
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share