03/06/2024
Eledumaare saanu mi,mo mo pe asiko eda ko ni foo.
Ore e mi,o n wo pe awon obi re ko se ikunlowo fun o nigba to n lakaka lati je eeyan laye.A mo nitori o ti waa la,lo ba ko eyin si won.Duro naa,ti o ko ba jee eeyan nko?kin lo fe se fun Olorun.Ore tun ero ara a re pa_EDE YORUBA GBAJUMO lo n gba o ni imoran