BBC WORLD Yoruba

  • Home
  • BBC WORLD Yoruba

BBC WORLD Yoruba Enlighting

20/03/2022
09/12/2021
04/12/2021
21/12/2020

Omoniyi Temidayo Raphel, ti ọ̀pọ̀ eeyan mọ̀ si Zlatan Ibile takurọsọ pẹlu BBC Yoruba nipa igbe aye ati isẹ rẹ.

07/12/2020

"London Tailor" ni orukọ inagijẹ ti wọn fun arakunrin ẹni ọdun mẹtalelọgbọn naa.

29/11/2020

Ṣe eewọ wa to de ọba lori ọrọ ọmọ tuntun?

29/11/2020

Oba Adedokun Abolarin da ile iwe ọfẹ silẹ fawọn akẹkọọ ti ko ni ireti ni Oke Ila Orangun nipinlẹ Osun.

31/10/2020
27/10/2020

Ohun ti iyawo Adio ṣe pẹlu ọmọ wọn Oyeladun, o ṣi ni lẹnu silẹ koda iroyin rẹ ko ṣee foju ba.

04/10/2020

Aarẹ Gani Adams ni lọpọ igba, Sunday Igboho kan maa n gbe kamẹra lẹyin, ki awọn eeyan baa le sọ pe o n ja fun ẹtọ Yoruba ni.

04/10/2020

Sunday Igboho wa koro oju si bi ọpọ eeyan, to n leri leka tẹlẹ, se sa sẹyin lati bawọn peju se iwọde naa.

Address


Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when BBC WORLD Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Videos

Shortcuts

  • Address
  • Alerts
  • Videos
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share