Africa Yoruba TV

  • Home
  • Africa Yoruba TV

Africa Yoruba TV Arts and entertainments
(1)

13/09/2024
O sele! Ile-ifowopamo Opay l'awon yoo maa yo aadota naira l'ori owo to ba le l'egberun mewaa naira lati ojo kesan-an, os...
08/09/2024

O sele! Ile-ifowopamo Opay l'awon yoo maa yo aadota naira l'ori owo to ba le l'egberun mewaa naira lati ojo kesan-an, osu kesan-an odun yii

*Won l'apo ijoba apapo lo n lo

Ope o! Olori Folasade Ashley Ogunwusi, okan l'ara awon olori Ooni Ile-Ife ti bimo okunrin lanti-lanti o*L'ayo n'iya ati ...
03/09/2024

Ope o! Olori Folasade Ashley Ogunwusi, okan l'ara awon olori Ooni Ile-Ife ti bimo okunrin lanti-lanti o

*L'ayo n'iya ati omooba tuntun jojolo wa

Africa Yoruba TV

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Olatunji Omobowale, Olayiwola Dauud, Alao LA Gold
31/08/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Olatunji Omobowale, Olayiwola Dauud, Alao LA Gold

O sele! Soun Ogbomoso yan Imaamu Habib Ayilara, molebi Imaamu agba Ogbomoso gege bii Imaamu inu aafin re*O l'oun ni yoo ...
30/08/2024

O sele! Soun Ogbomoso yan Imaamu Habib Ayilara, molebi Imaamu agba Ogbomoso gege bii Imaamu inu aafin re

*O l'oun ni yoo maa s'oju oun n'ibi oro to ba ni i se pelu esin Isilaamu

Africa Yoruba TV

Ileese mi ti ta baagi simenti kan ni egberun meta aabo naira gege bi mo se seleri, sugbon, awon alagbata lo n ta a ni ow...
30/08/2024

Ileese mi ti ta baagi simenti kan ni egberun meta aabo naira gege bi mo se seleri, sugbon, awon alagbata lo n ta a ni owo nla, iyen lo si je ka kuku da a duro - Alaaji Rabiu Abdul-Samad, oludasile ileese simenti BUA s'oro s'ita

Africa Yoruba TV

OGUN AMÚNISÌN NÍNÚ AYÉ MIỌLỌHUN FI ÒPIN SIAfrica Yoruba TV
30/08/2024

OGUN AMÚNISÌN NÍNÚ AYÉ MI
ỌLỌHUN FI ÒPIN SI

Africa Yoruba TV

A KU ORIRE OỌMỌ IPINLE OSUN Òní l'ope ọdun mẹtalelọgbọn (33)tiwọn dá ipinle osun silẹ IPINLẸ OSUN YOO TU WA LARA Africa ...
29/08/2024

A KU ORIRE O
ỌMỌ IPINLE OSUN

Òní l'ope ọdun mẹtalelọgbọn (33)
tiwọn dá ipinle osun silẹ

IPINLẸ OSUN YOO TU WA LARA

Africa Yoruba TV

Big shout out to my newest top fans! 💎 Abdullateef Ibn AbdulsallamDrop a comment to welcome them to our community,
22/08/2024

Big shout out to my newest top fans! 💎 Abdullateef Ibn Abdulsallam

Drop a comment to welcome them to our community,

Happy follow-versary to my awesome followers. Thanks for all your support! Rafiat Sh*ttu
22/08/2024

Happy follow-versary to my awesome followers. Thanks for all your support! Rafiat Sh*ttu

ÌWÚRE OGUN ÀIMỌDÍ KÒNÍ JÀ WÁAfrica Yoruba TV
22/08/2024

ÌWÚRE
OGUN ÀIMỌDÍ KÒNÍ JÀ WÁ

Africa Yoruba TV

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Horlarcunkanmee Jamiu, Olayinka Oluwaseyi, Boluwatife Mui...
21/08/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Horlarcunkanmee Jamiu, Olayinka Oluwaseyi, Boluwatife Muideen, Tony Ruhumuriza

Cooking something
19/08/2024

Cooking something

*OUT AT LAST!* The wait is finally over and I'm glad to tell you that *OLÙFÉ OKÀN MI* (The Lover of my Soul) by *Kikiola...
16/08/2024

*OUT AT LAST!*

The wait is finally over and I'm glad to tell you that *OLÙFÉ OKÀN MI* (The Lover of my Soul) by *Kikiola* is now available for download 💯💥💥💥.
This powerful praise shows how God is ever ready to stand by us during difficult situations and demonstrates how we are dear to His heart.❤️

Hurry now and download it on Audiomack by clicking the link below 👇

https://audiomack.com/adeyemiolabode37/song/olufe-okan-mi-lover-of-my-soul?share-user-id=96625994

Please help me share this with your loved ones and be blessed richly.

Kindly follow Kikiola on Facebook and Kikiolaofficial on Tiktok.
゚viralシ

Cc: Adeyemi Olabode

GBOGBO IWỌ TOFẸ LATI DARA PO MOWA TABI O MỌ YORUBA KO LATI MA BAWA KO ITAN ALADUN TABI ÌRÒYÌN ATI BẸBẸ LODARA PO MOWA LO...
15/08/2024

GBOGBO IWỌ TOFẸ LATI DARA PO MOWA
TABI O MỌ YORUBA KO LATI MA BAWA KO ITAN ALADUN TABI ÌRÒYÌN ATI BẸBẸ LO
DARA PO MOWA LORI WHATSAPP YII

BI O BAA LEBUN KAN TABI IMIRAN
IWỌ NAA NI ANFANI LATI DARA PO MỌWA

WhatsApp Group Invite

WỌNI FI Ọ SE ÈTÙTÙ ÒGO FUN ARÁYÉ Africa Yoruba TV
15/08/2024

WỌNI FI Ọ SE ÈTÙTÙ ÒGO FUN ARÁYÉ

Africa Yoruba TV

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Oladele Azeez, Lawal Adenike Ramota, Prince Adegboye Sahe...
11/08/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Oladele Azeez, Lawal Adenike Ramota, Prince Adegboye Saheed Olayinka, Bode Oye, Adedosu Sahlahwah, Abdullateef Ibn Abdulsallam, Omobolanle Adunny, Omotosho Oluwatosin, Adediran Sodiq Hardebayo, Zakariyau Taofeeq, Mohammed Alimam, Ade Ola, Olorunfunmylayo Mary, Lawal Abdullahi, Rasaq Waliyat, Ajetunmobi Omotayo Newlight, Alade Olalekan Wasiu, Yekeen Suliyat

03/08/2024

Àwọn olùfẹ̀hónúhàn yabo ṣọ́ọ̀bù oníṣọ́ọ̀bù, jí ọjà ọlọ́jà kó ní KanAfrica Yoruba TV
01/08/2024

Àwọn olùfẹ̀hónúhàn yabo ṣọ́ọ̀bù oníṣọ́ọ̀bù, jí ọjà ọlọ́jà kó ní Kan

Africa Yoruba TV

E fura o! Won gbe bombu s'inu baagi l'oju ona l'agbegbe Ikeja l'Ekoo *Moto kan ni won lo ja a ju s'ile*A ti gbe e, a si ...
01/08/2024

E fura o! Won gbe bombu s'inu baagi l'oju ona l'agbegbe Ikeja l'Ekoo

*Moto kan ni won lo ja a ju s'ile

*A ti gbe e, a si ti loo yin in danu - Benjamin Hundeyin, alukoro ileese Olopaa ipinle Eko

Africa Yoruba TV

Oro rirun ni bi won se n beere ohun ti mo ti gbe se n'idii ise tiata, se emi naa waa kere n'idii ise yii ni, koda, ki e ...
31/07/2024

Oro rirun ni bi won se n beere ohun ti mo ti gbe se n'idii ise tiata, se emi naa waa kere n'idii ise yii ni, koda, ki e le mo bi mo se to, opo awon gbajumo oserebinrin ni mo ti ko ibasun fun, won tie po pupo - Jigan Babaoja, gbajumo osere tiata la oro mole.

Africa Yoruba TV

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Abntv Houston, Lukeman Lanre Khasali, Doris Anthony, Nana...
31/07/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Abntv Houston, Lukeman Lanre Khasali, Doris Anthony, Nana Hawau Gold, Ooshama Baba Tunde, Tunde Green, Daouda Ajeniya

Haa! Sheikh Labeeb Lagbaji binu si Femi Adebayo*Nitori to lo kopa ninu fiimu ti won ti f'aso Elehaa ja ole*O ni ki i se ...
30/07/2024

Haa! Sheikh Labeeb Lagbaji binu si Femi Adebayo

*Nitori to lo kopa ninu fiimu ti won ti f'aso Elehaa ja ole

*O ni ki i se Musulumi ododo rara

Africa Yoruba TV

Address


Telephone

+2347034677688

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Africa Yoruba TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Videos

Shortcuts

  • Address
  • Telephone
  • Alerts
  • Videos
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share