31/10/2021
KỌRINTI KEJI 4:1-3
[1]NITORINA bi awa ti ni iṣẹ-iranṣẹ yi, gẹgẹ bi a ti ri ãnu gbà, ãrẹ̀ kò mu wa;
Therefore seeing we have this ministry, as we have received mercy, we faint not;
[2]Ṣugbọn awa ti kọ̀ gbogbo ohun ìkọkọ ti o ni itiju silẹ, awa kò rìn li ẹ̀tan, bẹ̃li awa kò fi ọwọ́ ẹ̀tan mu ọ̀rọ Ọlọrun; ṣugbọn nipa fifi otitọ hàn, awa nfi ara wa le ẹri-ọkàn olukuluku enia lọwọ niwaju Ọlọrun.
But have renounced the hidden things of dishonesty, not walking in craftiness, nor handling the word of God deceitfully; but by manifestation of the truth commending ourselves to every man's conscience in the sight of God.
[3]Ṣugbọn bi ihinrere wa ba si farasin, o farasin fun awọn ti o nù:
But if our gospel be hid, it is hid to them that are lost:
Good morning brethren.
Have a wonderful Sunday.