Omo odo agba TV

  • Home
  • Omo odo agba TV

Omo odo agba TV Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Omo odo agba TV, TV Channel, .

THE STORY OF OYOTUNJI: A YORUBA (West Africa)  KINGDOM IN UNITED STATES OF AMERICA.By: Damilare Yoruba boiOyotunji Afric...
12/05/2024

THE STORY OF OYOTUNJI: A YORUBA (West Africa) KINGDOM IN UNITED STATES OF AMERICA.

By: Damilare Yoruba boi

Oyotunji African Village is a village located near Sheldon, Beaufort County, South Carolina that was founded by Oba Efuntola Oseijeman Adelabu Adefunmi I in 1970. Oyotunji village is named after the Oyo empire, a pre-colonial Yoruba kingdom lasting from the 1300s until the early 1800s in what is now southwestern Nigeria. The name literally means “O̩yo̩ returns” or “O̩yo̩ rises again” or “O̩yo̩ resurrects” referring to the African Yoruba kingdom of Oyo, now rising in a new form near the South Carolina seashore.

Oyotunji village covers 27 acres (11 ha) and has a Yoruba temple which was moved from Harlem, New York to its present location in 1960. It was originally intended to be located in Savannah, Georgia, but was eventually settled into its current position after disputes with neighbors in Sheldon proper, over drumming and tourists.

HOW OBA EFUNTOLA ADEFUNMI I FOUNDED OYOTUNJI

During the slave trade era, many Africans were taken as slaves abroad. While going, some left with their culture and tradition which they continued within the foreign land where they found themselves. They continued with the culture and tradition of their fathers so as to maintain their identity.

The Yorubas in slavery are among the Africans that maintained their culture in the strange land and it was handed down to their children from generation to generation.

Many of their children, after the abolition of the slave trade, have married children of their former masters thus having children of mixed blood, that notwithstanding, they still carry on with their African culture in the foreign land since most of them cannot trace their root back to Africa.

The Yoruba culture has been one of the prominent and most celebrated one throughout the world till date. In the faraway United States of America, there is a Yoruba community named O̩yo̩tunji African Village. It is located near Sheldo

OYO EMPIRE IN THE HISTORY OF YORUBA RACE" The Old Oyo Empire was undoubtedly the greatest and most popular independence ...
12/05/2024

OYO EMPIRE IN THE HISTORY OF YORUBA RACE

" The Old Oyo Empire was undoubtedly the greatest and most popular independence in West Africa."

Oyo Empire was established, expanded and nurtured by the legend of all sea*ons himself, Oranyan who was known as Odede or Ajuwon. He was a brave hunter.

During the exploits of Oranyan, Oyo
Empire spread all over Yoruba land to Benin, Dahomey (Republic du Benin), Togo and up Niger and to the sea. He reigned in Benin and Oyo but had a lot of influence on Ife and Owo (Ondo State).

The Oyo Empire began as a state of Oyo, founded before 1400, with its capital at Oyo-ile, (also known as Katunga or Old Oyo or Oyo-oro). With empirical political, and cultural evidences abound. The fact that Oyo Empire was the core Empire of Yoruba land, and indeed, the most prominent in West Africa was never in doubt.

The Old Oyo was undoubtedly the greatest and most popular independent race in West Africa, indeed, Sub-Sahara. The Empire controlled many kingdoms in Yorubaland such as Sabe, Owu, Egba, Ijesa, Ife, Ijebu etc.

The Alaafin's Palace in Old Oyo, the political and spiritual headquarters of Oyo Empire covered abut 640 acres of land where the archaeological site of the old Oyo Empire and it's aircraft are standing in the original til today.

This architectural inventiveness of the Yoruba race provide tourist attraction to visitors to Yoruba land. The old Oyo Empire shared similarities, both in structure and administration with the British Empire in Europe.

Reference:
Iku Baba Yeye Alaafin Oyo
His Imperial Majesty Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi III.

Oyo konibajẹ
Source:omo Odo agba

ORI OKERE KOKO LAWONi aye atijọ ọkunrin ọdẹ kanwa ti o fẹran lati ma se ọdẹ lọ si ona jinjin lasiko kan ọde lọ si inu ig...
24/02/2024

ORI OKERE KOKO LAWO

Ni aye atijọ ọkunrin ọdẹ kanwa ti o fẹran lati ma se ọdẹ lọ si ona jinjin lasiko kan ọde lọ si inu igbo aginju kan bi o se taju lo ri Agbọnrin nla kan l'ọkan Ọdẹ gbiyanju lati sunmọ ki o le ta ibọn ọwọ re mọ bi o se fẹ ta ibọn mo Agbọnrin

Agbọnrin bẹrẹ si n sọrọ pe: ọdẹ dakun ma pa mi iyami lo ranmi jade sita iran ọdẹ lo se iku pa babami bi ọdẹ se da oju ibọn rẹ kole niyi ti o si so pe oun feri egun to n bẹ labẹ asọ Bi Agbọnrin se yi pada di Arewa ọmọbinrin niyi

Ọdẹ sunmọ wipe Wo Baa ri adan,aa fobe sẹbọ Bi ọdẹ se mu Agbọnrin wa'le niyi ti o si sọ orukọ rẹ ni Idi Ilẹkẹ Ọdẹ sọ Idi Ilẹkẹ di ayaba loode rẹ ti o si finu Soyun f'eyin gbọmọ pọn o bi arewa ọmọbinrin meji o sọ orukọ wọn ni Adetu ati Ori Okere

Kete ti awọn ọmọ na n dagba ni awọn obi won ti ro wọn lagbara ti won o sii se f'owo ro seyin larin awon akẹgbẹ wọn Adetu feran ki o ma ko opolopo eyan mọra sugbon Ori Okere kii gbọ kii gba lọrọ rẹ nitori o fẹran iwa t'inu mi ni mase Awọn obi won ma n ki won nilo pe ki won mase jẹjẹ papa julo iwọ Ori Okere lotitọ alagbara lo je sugbọn sora fun iwa aijoniloju nitori nkan kekere lo n se iku pa alagbara Adetu iwo na sora se nitori ile n yọ

Lẹyin ọdun diẹ ti awọn obi won ku
Nkankan sẹlẹ larin ilu anjanu kan n pa awon ara ilu Idi niyi ti oba se bẹ awọn ọmọbinrin alagbara lati f'opin si rogbodiyan na Ọba wa se ileri wipe on yio da ile ati ọna oun si meji ti won ba le segun anjanu na Awọn mejeji gba lati lọ nigbati won de inu igbo Adetu pe Ori Okere sakiyesi pe moja mosa la n mọ akikanju logun akin to moja ti o mosa iru wọn ni n ba ogun lo jẹki a sinmi diẹ ki a le tẹsiwaju l'owurọ Inu bi Ori Okere wipe Adetu nla le oun lọwọ bi o se fi ibinu kuro lọdọ rẹ niyi ibinu to n ba lọ lo fi se kongẹ anjanu ti o si pa tohun t'agbara rẹ lowurọ ọjọ keji ni Ori Adetu ji ti o fi ọgbọn pẹlu suru rii ori anjanu na ge Nígbàtí o ri oku Ori Okere inu re bajẹ o ni haa iwo aburo mi o si pa ara re pelu ibinu ORI OKERE KOKO LAWO BAA WI F'ỌMỌ ẸNI A GBO
Bi kabiyesi se pin

ÌRÓKÒ ati ÀRÀBÀNi igba ìwásè Ìrókò ati Àràbà je òré timo timo kori kosun ni awon mejeji je alagbara eniyan ni won a*o ka...
16/02/2024

ÌRÓKÒ ati ÀRÀBÀ

Ni igba ìwásè Ìrókò ati Àràbà je òré timo timo kori kosun ni awon mejeji je alagbara eniyan ni won a*o kan naa le maa ri lorun awon mejeji won ko kii ya arawon nigba kookan
Eniyan lile ni Ìrókò je o si tun je akikanju eniyan bee ni ki ise re sere àgbè ni awon mejeji

Araba je oni wa tutu eniyan kii fa ijangbon leyin ki o maa da erin pa òsónú
Awon eyan a maa ki Àràbà ni ori ki bayi wipe "Àràbà ni Bàbá eni a ba laba ni Baba", oriki yi ma n bi Ìrókò ninu nitori wipe Ìrókò sagba Àràbà, nigba toya Ìrókò ko le mu oriki yi mora mo bee si ni awon eyan ko yee kii Àràbà Aseyin wa aseyinbo oriki yi pada wa da ija nla sile laarin awon mejeji ti awon mejeji ko fi fe ri ìgbé ara won lakitan

Oba Ilu won ranse si awon mejeji lati le pari aawo to wa laarin won gbogbo igbinyanju Oba won pabo lojasi
Nigbati Àràbà ri wipe won ko ri ija arin oun ati Ìrókò pari ni Àràbà ba pinnu lokan ara re wipe ti eru ba ko oke ti o ko Ilé o tun ni ibikan ti a n gbe si eyi lo mu ki Àràbà fi okan kun eji ti o fi gba Ile aláwo lo, oni oun fe mo ohun to da ede aiyede sile laarin oun ati korikosun oun

Won ni ki Àràbà rubo ki ara ba le dè è dada Àràbà gbo riru ebo o si rubo Okiki awon mejeji tun bo nkan si bee ni aáwò to wa laarin won tun bo n gbilè si sugbon kayefi ibe wa ni wipe bawo ni oriki lasan se wa fe ya awon ore meji bayi

Nigbati Àràbà ri wipe oun ko le fi ara da nkan to n sele yi ni o ba pinnu wipe oun a kuku fi Ilu sile fun Ìrókò boya ti ko ba ri oun mo o sese ki okan tabi ara Ìrókò ba le Bayi ni Àràbà se mu ori le inu igbó o si yira pada lo ba di igi nla kan

Ariwo Àràbà ti binu di igi tun wa gba igboro kan okiki yi tun wa poju ti igbati Àràbà wa lorile Aiye lo Itiju oro yi lo mu ki Ìrókò naa binu lo di igi sinu Igbo bi ti ore re
eyi to wa buru ju ni be ni wipe ati òsán ati alé ko si igba ti eyan koja labe igi Ìrókò ti eru ko ni ma ba eyan nitori kíkún ti Igi Ìrókò maa n kun Ki a to wi ki a to fo igi Ìrókò ti bere si ni gba ebo

Itan tesiwaju up follow me for more

02/10/2023

AGBO IBA TYPHOID AND MALARIA
Ewe tea tutu
Ewe lali tutu
Ewe oparun
Ewe ahun
Epo igi ahun
Epo mango
Epo egbesi
Roro ogede
Kase pelu omidun kamamu ni aro ati ale

13/07/2023
13/06/2023
11/06/2023

Ask for your own dm or call 09035300484

31/05/2023
28/05/2023

Please buy this for your husband and look what is going to happened after that

Eku dede asiko yi ooo ebawa pari owe yii
25/05/2023

Eku dede asiko yi ooo ebawa pari owe yii

23/05/2023
make me too join the challenge me or garri who did you love pass
23/05/2023

make me too join the challenge me or garri who did you love pass

Báyìí ni àwọn ọ̀rẹ́, ọ̀dọ́, mọ̀lẹ́bí àtàwọn òṣèré tíátà ṣe ń ṣe ìdárò níbi àdúrà ọjọ́ mẹ́jọ fún Murphy Afolabi  nílùú Os...
22/05/2023

Báyìí ni àwọn ọ̀rẹ́, ọ̀dọ́, mọ̀lẹ́bí àtàwọn òṣèré tíátà ṣe ń ṣe ìdárò níbi àdúrà ọjọ́ mẹ́jọ fún Murphy Afolabi nílùú Osogbo

Dm for your own
21/05/2023

Dm for your own

18/05/2023

Address


Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Omo odo agba TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Videos

Shortcuts

  • Address
  • Alerts
  • Videos
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share