Yoruba Blog

Yoruba Blog Àwa n sọ ìtàn àwọn èyà Yorùbá ��������������
� Instagram?
(1)

Kunle Afolayan àti Tunde KelaniWhat is the yoruba word for ‘Mentor’ and ‘Mentee’📸 kunleafo
24/01/2025

Kunle Afolayan àti Tunde Kelani

What is the yoruba word for ‘Mentor’ and ‘Mentee’

📸 kunleafo

ṣẹ́ ẹ dá'yàn mọ̀ ? o da náà talọ́ wà nínú àwọ̀rán yìí?
15/01/2025

ṣẹ́ ẹ dá'yàn mọ̀ ?

o da náà talọ́ wà nínú àwọ̀rán yìí?

09/01/2025

È WO TÚN NI IFÁ TUN TUN

21/10/2024

OLUWO IBIRINMADE ALAWUSA 1782-1820
O jẹ ìyàlẹ́nu láti rí ohun tí wọn gbé jáde pé Oluwo àkókò tó jẹ́ musulumi je lodun 1600 sugbon awon tó gbé jáde kùnà láti kó ọdún tó gbese sì.
Èyí je ona kan láti má tún Ìtàn ko tàbí láti má ba Ìtàn tí kò ruju jẹ wọn kò ti bí Oluwo Ibirinmade Alawusa lodun 1600 kódà wọn kò ti bi Baba rẹ gan odidi ọdún mejilelọgọsan (182 years) la bù mọ ọdún Oluwo yi tan.
Oluwo Ibirinmade lo kọ́kọ́ je Ọba musulumi ni Iwo àmọ́ Islam kò fi ẹsẹ rinlẹ títí tó fi di ayé Ọba Oluwo Ayinla Lamuye nítorí Oluwo Ogunmakinde Anidẹlęsẹ tó jẹ́ lodun 1820 je Olorisa ìdí nìyí tí Okunmade Ali ṣe jẹ́ Imam Ìwó lehin ti Ọba Ibirinmade Alawusa wàjà lodun 1820 Baba Ali Okunmade je ọmọ Ògbómọ̀sọ́ iya rẹ ni ọmọ Ọba Ìwó.
Laye Oluwo Ọba Ogunmakinde Anidẹlęsẹ na ni a fi Imam Okunmade Ali je Balogun àkọ́kọ́ Ìwó lodun 1838 pelu àṣẹ Iba Oluyole Ibadan nítorí ọdún na ni ìpàdé wáyé Lọyọ lábẹ́ Aláàfin Adewinbi Abiodun Atiba pé àwọn Ọba kò gbọ́dọ̀ lọ ogun mọ kí ìlú tí kò bá ní Balogun sì lọ jẹ oyè Balogun.
Lẹhin ti Oluwo Ogunmakinde Anidẹlęsẹ wàjà lodun 1858 ni Oluwo Ayinla Lamuye je lodun na Ọba Lamuye jẹ ọmọ Ọba Ibirinmade Alawusa, láyé Ọba Ayinla Lamuye ni Balogun Ìwó àkọ́kọ́ di èrò Ibadan tí àdúgbò rẹ sì ń jẹ Aliwo ìyẹn Ali Ìwó di òní

Oba Ibirinmade Alawusa 1782-1820 Musulumi
Oba Ogunmakinde Anidẹlęsẹ 1820-1858 Olorisa
Oba Ayinla Lamuye Muhammadu 1858-1906 musulumi.
Ọba Ibirinmade Alawusa ni Oluwo kọkànlá Ọba Olufate tó gbèsè lodun 1782 lọ jẹ síwájú rẹ
E jẹ ka mọ ṣe iwadi lórí òpó ohun tí àwọn Ọba tó yí ìtàn pada bá ń gbé jáde àwọn òyìnbó tó mọ Oluwo Ogunmakinde Anidẹlęsẹ, Balogun Okunmade Ali àti Oluwo Ayinla Lamuye pọ tí wọn sì kó ìwé lórí ìtàn pelu Ifọrọwerọ tí wọn ṣe fún wọn.
Pelu Gazette Ìwó wá ní University of Ibadan
Aare Laji Abbas
AOY +2348023687432

28/09/2024

Live from Olojo Festival 2024 in Ile Ife

03/06/2024

Onka nÍ èdè Ọ̀ghọ̀

She tries to read numbers in the Ọ̀wọ̀ dialect 😊

ṣé ẹ̀yin lè gbìyànjú rẹ̀ wọ̀?

📸 TiTok/Ondo_dairy

Okitipupa. Ondo, 1940.Six women wearing head ties and matching dresses.ẹgbó̩ sẹ́ ẹgbẹ́jọdá ni tàbí aṣọ ẹbí ?📸: E.H Duckw...
01/06/2024

Okitipupa. Ondo, 1940.
Six women wearing head ties and matching dresses.
ẹgbó̩ sẹ́ ẹgbẹ́jọdá ni tàbí aṣọ ẹbí ?

📸: E.H Duckworth Collection

28/05/2024

Would you use these local washing machines found here in Ivory Coast🇨🇮

Three Obas, who are members of the Ijebu-Ode Judicial Council circa 1940s.From Left to right - The Ajalorun of Ijebu-Ife...
25/05/2024

Three Obas, who are members of the Ijebu-Ode Judicial Council circa 1940s.
From Left to right - The Ajalorun of Ijebu-Ife possibly Oba Asani Mabadeje who became the Ajalorun in 1943, in the middle Olowu of Owu-Ijebu Oba Adelani Gbogboade and the Dagburewa of Idowa Oba Samuel Adebonojo 1.

📸: E.H Duckworth Collection

THE MBARI CLUBIn the year 1961, in an old Lebanese restaurant at Dugbe market in Ibadan, a bunch of writers and visual a...
24/05/2024

THE MBARI CLUB

In the year 1961, in an old Lebanese restaurant at Dugbe market in Ibadan, a bunch of writers and visual artists, came together and founded what came to be known as the Mbari Club. The club was founded with the help of Ulli Beier, a teacher at the University of Ibadan.

The philosophy of the Mbari Club was that the arts operate from the centre of the culture, and is located in its historical heritage and traditional values which educate the masses and reflect the society’s values.

Mbari became a major confluence for Nigerian artists, but also attracted artists from across Africa. The club was so prestigious, it had the best artists in Nigeria as members – the likes of Chinua Achebe, Wole Soyinka, Christopher Okigbo, Demas Nwoko, John P. Clark etc.

At Mbari, open air performances were done by artists, there was a gallery where painters and sculptors exhibited their works and there was a library. Visual Arts giants like Yusuf Grillo, Bruce Onabrakpeya frequented the club and showcased their works.

The Premieres of Wole Soyinka’s “the Trial of brother Jero and JP Clark’s “Song of a goat” were staged at Mbari. It was also at Mbari that renowned Nigerian Singer, composer and activist, Fela Anikulapo-Kuti made his debut as a bandleader.

In its days, Mbari was host to internationally renowned artists like US poet Langston Hughes, and Jacob Lawrence, possibly the most widely acclaimed African American artist of the last century to either play or exhibit their works.

Ulli Beier, the German scholar who had helped the artists establish the club, began publishing the “Black Orpheus” literary magazine. At the time, the magazine was a platform for African writers to have their stories published without having to wait for journals in the UK or US.

Mbari was considered to be the only Africa-based publisher publishing titles by African authors like JP Clark, Wole Soyinka and Christopher Okigbo.

Mbari became the home for art, and the exhibition of the talent of the African continent and the new born Nation, Nigeria by giving visibility to the artists. Unfortunately, the breakout of the Civil war in 1967 interrupted probably the most successful movement of artists in Africa and the diaspora.

Peep that Peugot 403 parked in front of the club.

Àwọn àgbà bọ̀o wón ní Odò Ti Ó Bá Gbàgbé Orísun rè gbí gbe ló Ngbẹ – “A River That Forgets Its Source Will Eventua...
21/05/2024

Àwọn àgbà bọ̀o wón ní Odò Ti Ó Bá Gbàgbé Orísun rè gbí gbe ló Ngbẹ – “A River That Forgets Its Source Will Eventually Dry Up”

As Yorubas we must look to the future through the lens of history, examine the mistakes of the people before us, sieve out their wrongs and revolutionise the good.

As against popular belief that the Ijaw man, Isaac Adaka Boro, was the first secessionist in the history of Nigeria.

New reports revealed that this Yorùbá man in the picture, Modiyu Adeniyi Osinowo is infact the first man to declare an Independent Yorùbá Nation. Modiyu was provoked by the shabby treatment meted on Chief Obafemi Awolowo by the Fulani-led federal Government.

Modiyu who at that time was a 27 years old primary school headmaster led a one man campaign on Independence Day, October 1st 1960, calling for the immediate withdrawal of Yorùbá people. In his words, Modiyu said; “Let’s have our own Pakistan. If they could rubbish Awo like this, sooner or later, they will be defecating on our heads... let’s have our own Sovereignty”.

Modiyu was assassinated 5 years later, his death was never reported or recorded. Not much is known about him or his family or the life he lived before then. Modiyu was competely erased.

Ayé tó tó ayé àkámarà.

Falomo Village, Lagos circa 1910s.
18/05/2024

Falomo Village, Lagos circa 1910s.

Òjò ti ń pa Igún bọ̀ ọjọ́ ti pẹ́ àwọn àgbà òṣèrè mélòó ni ẹ̀yin dá mò ?
16/05/2024

Òjò ti ń pa Igún bọ̀ ọjọ́ ti pẹ́

àwọn àgbà òṣèrè mélòó ni ẹ̀yin dá mò ?

15/05/2024

Oba Okunade Sijuwade Olubuse II, the Ooni Ife from 1980 to 2015 at the Vintage Olojo Festival in 1996.

📸 : Mainframe Production

14/05/2024

The Oluwo of Iwo, Oba Abdulrasheed Akanbi, presents the Duke and Duchess of Sussex with traditional royal coral bead necklace and Aso-Oke.

📸


Egúngún láti ìlú Ẹdẹ ní ọdún 1970.Eliot Elisofon lọ́ ni àwòrán yìí. We must note the significance of this picture in the...
14/05/2024

Egúngún láti ìlú Ẹdẹ ní ọdún 1970.

Eliot Elisofon lọ́ ni àwòrán yìí.

We must note the significance of this picture in the face of history and the future ahead. As per Wikipedia: Ẹdẹ is a predominantly Muslim town with about 60% of the population. This can be traced back to 19th century during the reign of Timi Abibu Lagunju as the king of Ẹdẹ, who is the first Muslim Oba in Yorubaland given the fact that he was already on the throne for a few years when in November 1857, the Baptist missionary W. H. Clark visited Ẹdẹ. Clarke recorded thus: “This young follower of the Prophet (Prophet Muhammad), a short time since became the ruler of this town in the place of his father (Oduniyi), the deceased, and brings with him into office, the influence of his new religion (Islam).”

Fast forward to 1970’s we still enjoy enough tolerance for our tradition and cultures to thrive. What has happened to us ọmọ oótù òjíre? kíní dé tí àṣà wa kò wá jọwá lọ́jú ní òde òní?

Address


Telephone

+2348147052030

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yoruba Blog posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Yoruba Blog:

Videos

Shortcuts

  • Address
  • Telephone
  • Alerts
  • Contact The Business
  • Videos
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share