Te Deum Laudamus
1.f Awa yin O/ Olorun, Awa njeworepe, Iwo ni Oluwa.
Gbogbo aiye nf'ori/ bale fun O.
Baba/ aiye titi lai.
Iwo li eniti gbogbo awon Angeli/ nkigbe pe/ Orun, ati gbogbo agbara/ ti mbe ninu won,
Iwo li eniti ti awon kerubu, ati awon/ serafu/ kigbepe/ nigbagbogbo pe.
2.p Mimo/mimo, mimo: Oluwa Olorun/ awon omo Ogun;
f. Orun on a/ ye kun fun/ o/ la nla o/ go Re.
Egbe awon A/ posteli, ti / ologo yin O
Ogba a/ won woli/ ti, o dara yin O.
3. Ogun a/ won Martyr/ ti/ o lola yin O,
Ijo Mimo enia/ Olorun/ ni gbogbo/ aiye njewo re;
Ba a ba/ eni ola nla/ ti ko nipekun;
Ati omo re ni/ kan soso; o/ lola oloto.
4. Emi/ mimo pelu; O......lutunu,
Kristi; Iwo li o/ ba ogo;
Iwo li omo/ lailai ti Baba,
Nigbati o tewogba fun 'ra re lati gba/ enia la;
On ko korira/ inu wundia.
p Nigbati a segun oro/ iku tan;
O si joba orun sile fun gbogbo a/ won onigbagbo.
5.mp O joko lowo otun/ Olorun: Ninu/ ogo ti Baba.
Awa gbagbo pe/ o nbo wa: lati se/ onidajo wa,
Nitorina ni awa se ngbadura si odo Re, ran awon omo odo/ re lowo; ti o ti fi eje re iye/ biye ra pada.
Se won ki a le ka won kun awon enia/ mimo Re;
Ninu ogo/ ti ko nipekun.
6. Oluwa, gba awon eni/a Re la:
Ki o si fi ibikun fun awon e/ nia ini Re.
Jo/ ba fun won; ki o si ma gbe/ won leke lailai.
f Awa n/ gbe O ga; lo........jojumo;
Awa si nfori bale li o/ ruko Re: titi aiye/ ti ko nipekun.
7.p Fiyesini, Oluwa; lati pa wa mo lo/ ni li ailese.
Oluwa/ sanu fun wa; Jo/ wo sanu fun wa.
Oluwa, je ki anu Re ki o ma/ ba le wa; gege bi awa ti n/ gbeke wa le O.
F Oluwa/ Iwo ni mo/ gbekele.
Rall: Lai/ ma....je.....ki.....n.......da.........mu.
#awayino #HappyNewYear
#NIWAJU #OLUWA BY VERY REV ENOCH ADELEKE. Distinct Music Productions distinctmusicproductions
#omolaramusic #believe #Jesus #highlights DecentMedia
Unforgiveness disables you! #champions #highlights #nickvujicic #believe #Jesus #forgiveness
Thanks for being a top engager and making it on to my weekly engagement list! π Olori Jegede, Pamella Amadi, Richard Adeogun