20/07/2023
ALAYE NIPA IRAWỌ̀ INÁ TÓNGBONÀRÍRÍ (Leo) ♌
JULY 23 sí AUGUST 22
-Òorún ni Olùdarí Irawọ̀ yìí (Planet)
-Ọjọ́ Sunday ni Ọjọ́ Oriré wọn.
-Ẹ̀yà Kìnìún ni ẹ̀yà àwọn onirawọ̀ yìí.
-Irawọ̀ Afẹfẹ Onibinú (Aquarius) àti Iná Àtùpà (Sagittarius) dára fun Irawọ̀ yìí láti fẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọkọ tàbí áyá.
♌ -Irawọ yí, Olorí àti asiwaju ní wọn níbikíbi tiwọn báwà, wọn ní àǹfáàni láti jẹ Olórí nítorí Irawọ ton báwọn ló, Irawọ ńlá ní.
-Wọn ní ìdánilójú nínú ará wọn, bẹẹni wàá má ní ìwà ìgbéragá àti ẹ̀mí àfojúdi.
-Ìbínú onirawọ yí kòdá rárá, Wọn lé bá nkan jẹ lásìkò tí wọn bán bínú torí wá má bínú gidigan bẹẹni agídí inú wọn pọ.
-Onirawọ yí gbọdọ má tún ìṣẹ̀dá wọn ṣé ní gbògbo ìgbà torí èèyàn ńlá ni wọn bẹẹni Irawọ Ólórí ní wọn.
-Wá má pani lẹ́rin, Olotitọ ní wọn, wọn ṣé gbẹ́kẹ̀lé bẹẹni wá má bá èèyàn ṣé.
-Wọn kìí báwọn forí gbarí torí wàá má borí níkẹyìn.
-Irawọ yí lawọ́ pupọ bẹẹni wọn kì mọ́ owó kàn làkíná. Wá má pé wọn ní apá torí kòsì owó tí wọn kólé ná rárá
-Àti kékeré ní Ọlọ́run tì fún wọn ní Ọlá àti Ọ̀ọ́là torí Irawọ tón pín Ọ́lá lòn bá wọn ṣíṣẹ́ nítorí èyí ní a fin pé wọ́n ní starbuilder.
-Wọn fẹ́ràn láti má já fún orí ará wọn níbi gbogbo nkan.
-Wọn fẹ́ràn kí èèyàn má dupẹ lọpọlọpọ fún óòre tí wọn báṣé fún wọn. Wọn nifẹ sí ẹ̀mí imoré pupọ.
👉Ọkùnrin tòbá fẹ́ àwọn obìnrin Irawọ yi gbọdọ máṣé ìtọ́jú wọn dádá torí óòre wá fún lọpọlọpọ tí bán ṣe itọju wọn. Bẹẹni ó gbọdọ ṣé ọ̀pọ̀lọpọ̀ sùúrù pẹ̀lú wọn nítorí tí ìbínú wọn bádé báyìí, Ó lágbára pupọ, wọn lé bá nkan jẹ.
👉Irawọ yí fẹ́ràn òwú jíjẹ lọpọlọpọ, torí wá máà nifẹ pẹ̀lú gbògbo ọkàn wọn. Obìnrin àti ọkùnrin wọn, wá mán jówù gidigidi gàn bẹẹni wọn lé párá wọn lórí ẹni tí wọn nifẹ. Èèyàn tìn jówú ni wọn, adamọ́ wọn léyìí.
👉Ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn man sábà pùpá, wọn si man rẹwà gidigan bẹẹ wọn fẹ́ràn ogé ṣíṣe.
-Irawọ yí kìí ṣíṣẹ́ lábẹ́ èèyàn, wọn kìí ṣé ọmọṣẹ́, Irawọ Ọ́gá(olùdarí) ni wọn. Wọn gbọdọ má pinlẹ́ nkan fún rawọ́n torí kò dára fún wọn láti má ṣíṣẹ́ lábẹ́ èèyàn.