ILE ALAYO TV

ILE ALAYO TV Adun ni IFE nigba ti a bani ololufe atata,
Ayo ni IFE, idunnu ni IFE, Ifokanbale ni IFE pelu!!

07/01/2024
07/01/2024

Iru Oko wo loje ninu ile re / Iru aya wo loje ninu

17/12/2023

Aku imura odun

Eledumare ose fun anu  re
04/05/2023

Eledumare ose fun anu re

30/04/2022

Eyi ni ifilo to ti abala yi wa wipe. Ti aba ri enikeni to ni ohun edun okan kan boya ninu idile re tabi laarin ololufe meji to si fe ki a fi si ori afefe ki awon eniyan bawa dasi, ki eni be ki o pe sori ounka ero ilewo yi (Number) 08168847844 or 09026562877

30/04/2022

Eku dede asiko yi o eyin ojogbon ati olopolo pipe eniyan, eku ojo meta ooooo se dada ni ilewa wa ooooo, mo gba ni adura pe idilewa ati aarin awa ololufe koni daru lagbara eledumare, A si ku imura odun itunu awe yi, aade bawa laye ati laaye wa lase edumare

23/09/2021

Mofi wakati ati iseju yii ki gbogbo awa ojogbon, Oloye ati Oni lakaye eniyan pe aku Dede asiko yii oooo, mo gba ladura pe ile wa koni daru oooo benni arin awa oloufe koni daru lagbara eledumare!!!

Lori eto wa ti a n peni kini ohun to yara da idileru larin ibalopo ati Owo naa lawa bayi.
Arakunrin kan lomu oro kan wa si ori eto yii ti o sife ki gbogbo awa onimo ati ologbon eniyan ki o lahun loye Lori oro naa.
Arakunrin so wipe ohun tini se igbeyawo lati bi odun meje seyin bayi sugbon ohun ko gbadun iyawo ohun ninu ile,
Arakunrin yii tesiwaju ninu oro re owipe lotito ni ohun ba iyawo ohun Nile gege bi obinrin to pa arare mo, sugbon oma n soro fun iyawo ohun lati jeki ohun se loko laya pelu re beeni ohun ma n se eto ohun ninu ile daada gege bi oseto ati bi ose ye gege bi olori ile sugbon sibe iyawo ohun ko yi iwa re pada rara.

Arakunrin yii tesiwaju otun so wipe koda Ojo ti iyawo ohun ba gba lati ba lajosepo, opeju iseju meji iyawo ohun a so wipe otito bahun, ti ohun basi ko jale lati da ibalopo naa duro ni se loma ti ohun danun bi igi.
Arakunrin yii si tun so wipe ohun je eniyan to feran ibalopo gidigidi to bee ge. Bee sini ohun nife iyawo ohun daada, nitorina ni ohun kofe ma ba obinrin miran lajosepo nita.

Arakunrin yii fe ki eyin ologbon, onimo, oloye ati oni lakaye eniyan ki o gba ohun ni imoran Lori oro yii nitoripe otisu ohun debi yeeeeee!!!!
Ejowo a n beyin ni oruko eledumare to da aye ati orun pe a fe oro eebu, epe tabi awon oro alufasa ni ori eto yii.
Eto yin wa fun awon to ti ni idile ati awon ti kotini idile,
Egbe oro to ba ruyin loju wa si ori eto yii beeni a o si bayin gbe si Ori afefe ti awon ojogbon eniyan yio si layin loye lori oro naa,
Mofe ki gbogbo wa mo wipe Awa kii daruko enikeni ni Ori eto yii oooooo ejowo ema se daruko enikeni,
Mo Gbadura pe ibanuje koni wole towa oooooo lase eledumare!!!!
Onka ero ilewo mi niyii fun eyin ti e ba nife si lati pemi fun imoran lori idile (loko laya), tabi lori ede aiyede laarin ololufe meji
Iwo to n fe imoran lori ati loko (husband) tabi ati ni aya (wife)!!!

08168847844, 09026562877

12/07/2021

MY ADVICE FOR MARRIED WOMEN'S SINGLE LADIES THAT ABOUT TO MARRIED
We women's let learn how to talk to our husband and let respect our husband because our husband is our crown, let make them happy everytime, if our husband is happy to us they we be happy to do many good thing for us even they will be happ to come home in time when they close in the are working place. The reason why am saying this his that some of women have pursue they are husband outside just because of they are character's and they are behaviors to the are husband so let always make them happy, even if there is no much at home (money or foodstuf) I pray that God will continue to protect our family and provide for our needs
This advice is for women's so the man's own advice is coming very soon

WOMEN'S I WANT US TO READ THIS HOLY WORDS OF GOD
1PETER CHAPTER 3 VERS 1-4

3:1 Likewise, ye wives, be in subjection to your own husbands; that, if any obey not the word, they also may without the word be won by the conversation of the wives;3:2 While they behold your chaste conversation coupled with fear.3:3 Whose adorning let it not be that outward adorning of plaiting the hair, and of wearing of gold, or of putting on of apparel;3:5 For after this manner in the old time the holy women also, who trusted in God, adorned themselves, being in subjection unto their own husbands:3:6 Even as Sara obeyed Abraham, calling him lord: whose daughters ye are, as long as ye do well, and are not afraid with any amazement.3:4 But let it be the hidden man of the heart, in that which is not corruptible, even the ornament of a meek and quiet spirit, which is in the sight of God of great price. 1 Peter

10/07/2021

AKOLE ORO MI TONI FUN EYIN ENIYAN MI NI WIPE TOJU OLOLUFE RE OHUN NI AYO RE!!!

Opolopo okunrin ati obinrin loti gbagbe ife akoko ti won ba ololufe won lo nigba ti won koko bere ife won ki won to gba esu laaye larin won ti ikorira, a he so otito , a he pon ara eni le, a he ni iteriba fun arawon ati a he mo olorun ti won sin.
Eyi ma sele laarin ololufe meje lati ipase a he bikita ati a he ni ironu to jinle daradara, Nitori naa ni opolopo ife otito fi sonu laarin ololufe meji
Mo si fe ki a ranti ife akoko ti o mu inu awa mejeji dun nigbana ki a si se atunse laarin wa.
Mo gba ni adura wipe esu koni so Ayo ife wa di ibanije mo wa lowo ooooo lase eledua!!!

10/07/2021

Eyin eniyen mi nile eku dede asiko yi ooo, se Dada ni ile wa
Mo gbadura pe ile koni gbona mo gbogbo wa lase lowo eledua!!!

12/06/2021

Eko ojumo nile yii ooooo, ajire bii,
Eyin eniyen mi nile
N je odara ki oko ati iyawo dijo maa da owo po ninu apo owo kanna? Papa julo bi nkan se lo ni orilede lode Oni (It is good for husband and wife to be doing Join account? especially the way something is going on nowadays in this nation

Eku dede asiko yii ooo  gbogbo eyin ojogbon eniyan ati eyin eniyan ti olorun jogun imo fun, mo kiyin oooo mo si gbadura ...
18/05/2021

Eku dede asiko yii ooo gbogbo eyin ojogbon eniyan ati eyin eniyan ti olorun jogun imo fun, mo kiyin oooo mo si gbadura wipe opolo yin koni joba lagbara lowo olorun!
IBEREE MI TONI NI WIPE
Kini ohun ti a n pe ni IFE ati wipe kini awon ohun to ma mu ife gboroo si ninu okan okunrin ati obinrin tabi ki a so wipe ni okan oko ati iyawo ninu ile

17/05/2021

Eyin eniyan mi nile
Iberee mi akoko loni losi odo awon okunrin ti iberee mi keje si n bowa lona fun eyin obinrin naa

Iberee mi akoko ni wipe
N je odara ki oko (husband) ma gbe owo soke lu iyawo re to fe sile, Nitoripe ko fun ni ibalopo ni asiko tofe ninu ile?

Send a message to learn more

17/05/2021

Mo ki gbogbo ile wipe eku ojumo ooooo, Ha jire bii
Mo gbadura fun gbogbo wa wipe ose ayo ni ose yi a je fun gbogbo wa oooo ha o ni soko nu, ha o ni so aya nu beeni ha o ni somo nu ni agbara lowo eledumare!

15/05/2021

Mofe ki a soro lori kinni ohun to n da idile ru lode oni larin IBALOPO ati OWO

15/05/2021

N je odara ki iyawo ile ma so fun oko re pe ekan ni ohun fe ibalopo ni aarin ose kan? Ti oko si nife si ibalopo ju ekan lo ni aarin ose

28/04/2021

Ibalopu je ohun to yara da idileru

Address


Telephone

+2348168847844

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ILE ALAYO TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to ILE ALAYO TV:

Videos

Shortcuts

  • Address
  • Telephone
  • Alerts
  • Contact The Business
  • Videos
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share