yoruba_lemi

yoruba_lemi Bringing to you interesting and educative indigenous contents.

Ẹ ǹlẹ́ o 🤗 Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Karùn-ún. Oṣù Èbìbí. Obì ní í bi ikú, Obì ní í bi ààrùn, Ọ̀tọ̀ ni à á ya òfúà obì í sí. Ikú...
01/05/2024

Ẹ ǹlẹ́ o 🤗
Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Karùn-ún.
Oṣù Èbìbí.

Obì ní í bi ikú,
Obì ní í bi ààrùn,
Ọ̀tọ̀ ni à á ya òfúà obì í sí.
Ikú yẹ̀ lórí i wa, àìsàn yẹ̀ lórí i wa, àrùn yẹ̀ lórí i wa. Àṣẹ!
Ire gbogbo!

'èmi










29/04/2024

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé...........
(It's Monday Morning)

A kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗
Elédùwà ló ń ṣe ohun gbogbo, ẹ̀dá kọ̀ ń gbìyànjú ni.

Ǹjẹ́ kí Èdùmàrè túbọ̀ máa fọ̀nà hàn wá.
Àṣẹ!
Ire gbogbo!

YouTube link here 👇

https://youtu.be/_OnUTb2-D54?si=D-4rMKKO-N2aPRic

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé........... (It's Monday Morning) A kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗Ẹ má gbàgbé wí pé, bí ará iwájú bá dúró, ...
22/04/2024

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé...........
(It's Monday Morning)

A kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗
Ẹ má gbàgbé wí pé, bí ará iwájú bá dúró, tó kọ̀ láti tẹ̀síwájú, èrò ẹ̀yìn á báa níbẹ̀. Kódà, wọ́n á tún kọjá rẹ̀.

Bí ó bá ti ẹ̀ tún wá rí bẹ́ẹ̀, ìyẹn ò túmọ̀ sí wí pé kí ènìyàn má tẹ̀síwájú mọ́ nínú ìrìn àjò rẹ̀.
Kí á túbọ̀ máa tẹ̀ síwájú nínú ìrìn àjò wa, Ire ló máa yọrí sí.
Àṣẹ!

Ire gbogbo!

'èmi










Oríire ńlá lèyìí 💪🏾 Congratulations to
20/04/2024

Oríire ńlá lèyìí 💪🏾
Congratulations to

19/04/2024

Ẹ ǹlẹ́ níbẹ̀ un ooo.
Ṣé àlàáfíà ni mo bá a yín🤗

Ní ọ̀sẹ̀ yìí, lórí ètò Yorùbá l'èmi, mò ń sọ ìtàn ránpẹ́ kan fún wa, láti inú ìwé Ìrìn Àjò. Ẹ máa bá wa ká lọ...

On this week's episode of Yorùbá L'èmi, I am telling a short story from the book Journey.
Stay tuned...
Watch, Like, Comment and Subscribe here 👇🏾

https://youtu.be/-xihOfN2iSs?si=NX2nFHkNCcColrVn






Happy Eid Al-Fitr to all our Muslim Brothers and Sisters. A kú ọdún o 🎊 🎉Wishing you a Joyful Eid Al-Fitr celebration 🎉 ...
10/04/2024

Happy Eid Al-Fitr to all our Muslim Brothers and Sisters.
A kú ọdún o 🎊 🎉

Wishing you a Joyful Eid Al-Fitr celebration 🎉 💃🏾

'èmi

Ẹ ǹlẹ́ níbẹ̀ un o 🤗 Ngbọ́! You don't speak your language because, people will say you are too local?Ngbọ́! You don't lik...
09/04/2024

Ẹ ǹlẹ́ níbẹ̀ un o 🤗

Ngbọ́! You don't speak your language because, people will say you are too local?

Ngbọ́! You don't like your culture because, people will say it is outdated?

Ngbọ́! You do not wear your own native attire because, people will say they are not in vogue?

Ngbọ́? You don't like songs sung in your dialect because, people will say they are not popular?

Wòó, wàhálà tìẹ nìyẹn 🤷🏾‍♀️
Anyway sha, should in case you do not like your language or culture, I am here to tell you that mine is the BEST.
I am Yorùbá!
We speak the most beautiful language and Our Culture is the BEST.

Please, Value who You are.
You are Beautiful!

'èmi

Ẹ ǹlẹ́ o 🤗 Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Kẹrin. Bẹ́ẹ̀, a kú ọdún Àjíǹde. Ohun gbogbo tó ti d'òkú nínú ayé wa yóò jíǹde.Àmín Àṣẹ.A kú...
01/04/2024

Ẹ ǹlẹ́ o 🤗
Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Kẹrin.
Bẹ́ẹ̀, a kú ọdún Àjíǹde.

Ohun gbogbo tó ti d'òkú nínú ayé wa yóò jíǹde.
Àmín Àṣẹ.
A kúu Ayọ̀ ọdún ooo😊

'èmi










The YORÙBÁ are one of the largest ethnic groups in Africa.The YORÙBÁ are a very sociable and expressive people who comme...
26/03/2024

The YORÙBÁ are one of the largest ethnic groups in Africa.

The YORÙBÁ are a very sociable and expressive people who commemorate major events with colorful festivals and celebrations.

I am proud to be a Yorùbá 🥰

Tell us something exciting about your Culture.

'èmi









Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé........... (It's Monday Morning) A kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗Àní, tibi tire la dá ilé ayé,Òkè àti ilẹ̀...
25/03/2024

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé...........
(It's Monday Morning)

A kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗
Àní, tibi tire la dá ilé ayé,
Òkè àti ilẹ̀,
Síwájú àti sẹ́yìn.

Ǹjẹ́ a wá tiẹ̀ lè gbàdúrà wí pé kí ibi má ṣẹlẹ̀ sí wa rárá rárá ni?
Ṣùgbọ́n, ìrètí wa ni wí pé kí ire máa jẹ ti wa nígbà gbogbo.
Èdùmàrè á ṣ'ọ̀nà gbogbo wa n'íre, lónìí àti síwájú sii.
Àṣẹ!

Ire gbogbo!

'èmi










Ẹ ǹlẹ́ o 🤗 A kú Ayọ̀ ọdún tuntun ooo, Ayọ̀ wa á túbọ̀ máa pọ̀ si ni, Ayọ̀ wa ò sì ní dìbànújẹ́, Àmín Àṣẹ 🙏🏾Ọdún á yabo 🎊...
01/01/2024

Ẹ ǹlẹ́ o 🤗
A kú Ayọ̀ ọdún tuntun ooo,
Ayọ̀ wa á túbọ̀ máa pọ̀ si ni, Ayọ̀ wa ò sì ní dìbànújẹ́, Àmín Àṣẹ 🙏🏾

Ọdún á yabo 🎊 🎉

'èmi










Ẹ ǹlẹ́ o 🤗 A kú ọdún, A kú ìyèdún oo 🎊 🎉 Ọdún á yabo fún gbogbo wa o. Àṣẹ.  'èmi
25/12/2023

Ẹ ǹlẹ́ o 🤗
A kú ọdún,
A kú ìyèdún oo 🎊 🎉

Ọdún á yabo fún gbogbo wa o. Àṣẹ.

'èmi










Ẹ ǹlẹ́ o 🤗 Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Kọkànlá, Oṣù Bélú, Oṣù ire.Ohun rere ò ní wọ́n gbogbo wa nínú oṣù yìí o. Àmín Àṣẹ.Ṣé àlàáfí...
01/11/2023

Ẹ ǹlẹ́ o 🤗
Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Kọkànlá, Oṣù Bélú, Oṣù ire.

Ohun rere ò ní wọ́n gbogbo wa nínú oṣù yìí o.
Àmín Àṣẹ.
Ṣé àlàáfíà ni 😊

'èmi










20/10/2023

Ẹ ǹlẹ́ o.
Ní ọ̀sẹ̀ yìí, à ń tẹ̀síwájú nínú àwọn orin Yorùbá.
Ẹ jẹ́ kí á jọ gbádùn ètò náà.
This week, we are proceeding on the Yoruba Music, stay tuned!
YouTube Link:
https://youtu.be/ZUqmSr0y0pQ












Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé........... (It's Monday Morning) A kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗A kúu ìgbìyànjú. Bí ọwọ́ kò bà ti dilẹ̀, ...
16/10/2023

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé...........
(It's Monday Morning)

A kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗
A kúu ìgbìyànjú.
Bí ọwọ́ kò bà ti dilẹ̀, dandan ni kí àṣeyọrí ó wà.

Èdùmàrè á dé gbogbo ìgbìyànjú wa l'ádé o
A ò sì ní ṣeé lásán.
Àṣẹ!

Ire gbogbo!

'èmi










Ẹ ǹlẹ́ o. Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù kẹwàá, Oṣù Ọ̀wàrà, Oṣù òmìnira. Ara á tù wá nínú oṣù yìí o, ara ò sì ní ni wá. Àmín Àṣẹ.   '...
02/10/2023

Ẹ ǹlẹ́ o.
Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù kẹwàá, Oṣù Ọ̀wàrà, Oṣù òmìnira.

Ara á tù wá nínú oṣù yìí o, ara ò sì ní ni wá. Àmín Àṣẹ.

'èmi










11/09/2023

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé...........
(It's Monday Morning)

Ẹ kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗
Ṣé àlàáfíà ni? Ẹ káàbọ̀ sínú ọ̀sẹ̀ tuntun o.
Ó tó ọjọ́ mẹ́ta 😇

Ìròyìn ayọ̀ rèé lọ́sẹ̀ yìí o 🤗
YORÙBÁ L'ÈMI IS BACK!
YORÙBÁ L'ÈMI IS BACK!!
YORÙBÁ L'ÈMI IS BACK!!!

Another episode of Yorùbá l'èmi drops this weekend💃🏻💃🏻💃🏻💃🏻💃🏻💃🏻💃🏻💃🏻
Ní gbogbo ọjọ́ ẹtì ni o (it's every Friday).

Have you subscribed to YORUBA LEMI TV YouTube channel? If your answer is No, you need to do that now by clicking on this link👇🏽

https://youtube.com/?si=3OljpUikzc6nhhZ1

You sure don't wanna miss this next episode 😅
Ire lọ́nà gbogbo wa lọ́sẹ̀ yìí o jàre.
Àmín Àṣẹ.
Ire o!

'èmi










Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Kẹsàn-án, Oṣù Ọ̀wẹ̀wẹ̀.Ìbẹ̀rẹ̀ ohun ọ̀tun ni yóò jẹ́ fún wa o, Àmín Àṣẹ 🙏🏾Ire gbogbo lọ́nà wa nínú oṣù...
02/09/2023

Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Kẹsàn-án, Oṣù Ọ̀wẹ̀wẹ̀.
Ìbẹ̀rẹ̀ ohun ọ̀tun ni yóò jẹ́ fún wa o, Àmín Àṣẹ 🙏🏾

Ire gbogbo lọ́nà wa nínú oṣù yìí 😇
Yorùbá L'èmi.




Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé........... (It's Monday Morning) Ẹ kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗Ṣé àlàáfíà ni mo bá a yín?Ó tó ọjọ́ mẹ́ta...
21/08/2023

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé...........
(It's Monday Morning)

Ẹ kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗
Ṣé àlàáfíà ni mo bá a yín?
Ó tó ọjọ́ mẹ́ta 😇

Ǹjẹ́, Orí!
Ibi ire ni kí o gbé wa dé.
Ẹsẹ̀! Wo ibi ire sìn wá rè, lọ́sẹ̀ yìí àti síwájú sí i.
Àmín, Àṣẹ!

Ẹ KÚ ÒWÚRỌ̀ ÒNÍ ooo
Ire gbogbo!

'èmi










01/08/2023

Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Kẹjọ, Oṣù Ògún.
Ire kàbìtì lọ́nà gbogbo wa ooo, Àmín Àṣẹ 🙏🏾

Èyí ni ìmọ̀ràn mi fún un yín o😇
Yorùbá L'èmi




We are not a people begging to be identified, we are a people with Strong Identity 👌🏾We are YORÙBÁ 💪🏽Proudly so!We are U...
04/07/2023

We are not a people begging to be identified, we are a people with Strong Identity 👌🏾

We are YORÙBÁ 💪🏽
Proudly so!
We are Unique!
Our Language, Our culture, our way of life, everything about us is Unique 🥰💕

YORÙBÁ LÈMI💃🏽
A dẹ̀ kúu òjò wẹliwẹli yìí ooo🤗🤗
Á kúkú tù wá lára. Àṣẹ!

'èmi







Oṣù Tuntun Oṣù Aláyọ̀ Oṣù Oníre Oṣù Ọlọ́lá Oṣù AYỌ̀Oṣù ÌgbégaOṢÙ AGẸMỌ!Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Keje ooooooIre kàbìtì lọ́nà gbo...
02/07/2023

Oṣù Tuntun
Oṣù Aláyọ̀
Oṣù Oníre
Oṣù Ọlọ́lá
Oṣù AYỌ̀
Oṣù Ìgbéga

OṢÙ AGẸMỌ!
Ẹ káàbọ̀ sínú Oṣù Keje oooooo
Ire kàbìtì lọ́nà gbogbo wa. Àmín Àṣẹ 🙏🏾

'èmi

Ẹ káàbọ̀ sínú oṣù Òkudù.Welcome to the month of June 💃🏼💃🏼🤗🤗We are:Helped,Graced,Favored,Honored,Refreshed,Restored, this...
02/06/2023

Ẹ káàbọ̀ sínú oṣù Òkudù.
Welcome to the month of June 💃🏼💃🏼🤗🤗

We are:
Helped,
Graced,
Favored,
Honored,
Refreshed,
Restored, this new month and beyond 🙏🏽

Ire kàbìtì lọ́nà gbogbo wa ooo. I specially welcome you all to my Month 💃🏽💃🏽💃🏽

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé........... (It's Monday Morning) Ẹ kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗Ṣé àlàáfíà ni o?Ǹjẹ́ bí a ṣe ń rin Ìrìn-à...
08/05/2023

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ ajé...........
(It's Monday Morning)

Ẹ kú òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o🤗
Ṣé àlàáfíà ni o?

Ǹjẹ́ bí a ṣe ń rin Ìrìn-àjò wa ní wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́, kí á má ṣe gbàgbé wí pé, rere ló tọ́, ibi ò sunwọ̀n.

Nítorí, ẹni tó bá r'òfọ́ ibi, inú ara rẹ̀ ni yóò jẹẹ́ sí.
Yóò ru ìyòókù lọ sílé, ọmọ rẹ̀ yóò jẹ nínú ẹ̀.

Ǹjẹ́ kí á ṣe rere, kí àwa náà leè rí ire gbà. Èdùmàrè á túbọ̀ máa kọ́ wa mọ̀ọ́ṣe o. Àmín Àṣẹ.
Ire o!

'èmi










Ǹjẹ́ ẹ rántí orin yìí? 🤗I'm singing this song for all of you oooo😁😁Let's go.. 💃🏽Òjò ń rọ̀, ṣeré nínú iléMá wọnú òjò, kí ...
25/04/2023

Ǹjẹ́ ẹ rántí orin yìí? 🤗
I'm singing this song for all of you oooo😁😁
Let's go.. 💃🏽

Òjò ń rọ̀, ṣeré nínú ilé
Má wọnú òjò, kí aṣọ rẹ,
Má ba tutù.
Kí òtútù má ba mú ẹ 🤗🤗

I remain Adùnọlá, the Yorùbá angel 😇
'èmi




A kúu òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o, Ṣé àlàáfíà ni mo bá a yín o🤗Ǹjẹ́, ohun kan tó ṣe pàtàkì ni mo fẹ́ sọ ní òwúrọ̀ yìí. Ohùn ná...
24/04/2023

A kúu òwúrọ̀ ọjọ́ ajé yìí o, Ṣé àlàáfíà ni mo bá a yín o🤗

Ǹjẹ́, ohun kan tó ṣe pàtàkì ni mo fẹ́ sọ ní òwúrọ̀ yìí.
Ohùn náà ni wí pé, ohun gbogbo tí à ń ṣe lóde òní ló ń fẹ́ àkíyèsí.

Ìrìn tí à ń rìn,
Oúnjẹ tí à ń jẹ,
Irú ibi tí à ń lọ gan pàápàá,
Ohun gbogbo tí à ń ṣe.

Gbogbo rẹ̀ pátápátá ló ń fẹ́ àkíyèsí ooo.
Bí a ṣe ń rin Ìrìn-àjò wa, kí a fi ìṣọ́ra àti àkíyèsí kún un.

A ò kúkú ní ṣìṣe láṣẹ Èdùwà.
Àmín Àṣẹ.
Ire o! Ire kàbìtì.

'èmi










Address


Alerts

Be the first to know and let us send you an email when yoruba_lemi posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to yoruba_lemi:

Videos

Shortcuts

  • Address
  • Telephone
  • Alerts
  • Contact The Business
  • Videos
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share