Yoruba Blog

Yoruba Blog Àwa n sọ ìtàn àwọn èyà Yorùbá ��������������
� Instagram?

Some of the beautiful images from the just concluded Ojude Oba in Ijebu Ode.Have you attended any Ojude Oba before? shar...
12/06/2025

Some of the beautiful images from the just concluded Ojude Oba in Ijebu Ode.

Have you attended any Ojude Oba before? share your experience with us

Image credit

17/02/2025

I was privileged to interview High Chief Saliu Yaya, the Atosin of Egure Quarters, Supare Akoko in 2023, and he talked about how Supare Akoko Came into existence and how the kingmakers have also gone about selecting a new king after the departure of the previous King. Do well to follow this page as I will be posting new videos that will talk about the efforts of the kingmakers regarding the selection of a new king. Share this video with your friends and family. Follow me for more

Kunle Afolayan àti Tunde KelaniWhat is the yoruba word for ‘Mentor’ and ‘Mentee’📸 kunleafo
24/01/2025

Kunle Afolayan àti Tunde Kelani

What is the yoruba word for ‘Mentor’ and ‘Mentee’

📸 kunleafo

ṣẹ́ ẹ dá'yàn mọ̀ ? o da náà talọ́ wà nínú àwọ̀rán yìí?
15/01/2025

ṣẹ́ ẹ dá'yàn mọ̀ ?

o da náà talọ́ wà nínú àwọ̀rán yìí?

09/01/2025

È WO TÚN NI IFÁ TUN TUN

21/10/2024

OLUWO IBIRINMADE ALAWUSA 1782-1820
O jẹ ìyàlẹ́nu láti rí ohun tí wọn gbé jáde pé Oluwo àkókò tó jẹ́ musulumi je lodun 1600 sugbon awon tó gbé jáde kùnà láti kó ọdún tó gbese sì.
Èyí je ona kan láti má tún Ìtàn ko tàbí láti má ba Ìtàn tí kò ruju jẹ wọn kò ti bí Oluwo Ibirinmade Alawusa lodun 1600 kódà wọn kò ti bi Baba rẹ gan odidi ọdún mejilelọgọsan (182 years) la bù mọ ọdún Oluwo yi tan.
Oluwo Ibirinmade lo kọ́kọ́ je Ọba musulumi ni Iwo àmọ́ Islam kò fi ẹsẹ rinlẹ títí tó fi di ayé Ọba Oluwo Ayinla Lamuye nítorí Oluwo Ogunmakinde Anidẹlęsẹ tó jẹ́ lodun 1820 je Olorisa ìdí nìyí tí Okunmade Ali ṣe jẹ́ Imam Ìwó lehin ti Ọba Ibirinmade Alawusa wàjà lodun 1820 Baba Ali Okunmade je ọmọ Ògbómọ̀sọ́ iya rẹ ni ọmọ Ọba Ìwó.
Laye Oluwo Ọba Ogunmakinde Anidẹlęsẹ na ni a fi Imam Okunmade Ali je Balogun àkọ́kọ́ Ìwó lodun 1838 pelu àṣẹ Iba Oluyole Ibadan nítorí ọdún na ni ìpàdé wáyé Lọyọ lábẹ́ Aláàfin Adewinbi Abiodun Atiba pé àwọn Ọba kò gbọ́dọ̀ lọ ogun mọ kí ìlú tí kò bá ní Balogun sì lọ jẹ oyè Balogun.
Lẹhin ti Oluwo Ogunmakinde Anidẹlęsẹ wàjà lodun 1858 ni Oluwo Ayinla Lamuye je lodun na Ọba Lamuye jẹ ọmọ Ọba Ibirinmade Alawusa, láyé Ọba Ayinla Lamuye ni Balogun Ìwó àkọ́kọ́ di èrò Ibadan tí àdúgbò rẹ sì ń jẹ Aliwo ìyẹn Ali Ìwó di òní

Oba Ibirinmade Alawusa 1782-1820 Musulumi
Oba Ogunmakinde Anidẹlęsẹ 1820-1858 Olorisa
Oba Ayinla Lamuye Muhammadu 1858-1906 musulumi.
Ọba Ibirinmade Alawusa ni Oluwo kọkànlá Ọba Olufate tó gbèsè lodun 1782 lọ jẹ síwájú rẹ
E jẹ ka mọ ṣe iwadi lórí òpó ohun tí àwọn Ọba tó yí ìtàn pada bá ń gbé jáde àwọn òyìnbó tó mọ Oluwo Ogunmakinde Anidẹlęsẹ, Balogun Okunmade Ali àti Oluwo Ayinla Lamuye pọ tí wọn sì kó ìwé lórí ìtàn pelu Ifọrọwerọ tí wọn ṣe fún wọn.
Pelu Gazette Ìwó wá ní University of Ibadan
Aare Laji Abbas
AOY +2348023687432

03/06/2024

Onka nÍ èdè Ọ̀ghọ̀

She tries to read numbers in the Ọ̀wọ̀ dialect 😊

ṣé ẹ̀yin lè gbìyànjú rẹ̀ wọ̀?

📸 TiTok/Ondo_dairy

Okitipupa. Ondo, 1940.Six women wearing head ties and matching dresses.ẹgbó̩ sẹ́ ẹgbẹ́jọdá ni tàbí aṣọ ẹbí ?📸: E.H Duckw...
01/06/2024

Okitipupa. Ondo, 1940.
Six women wearing head ties and matching dresses.
ẹgbó̩ sẹ́ ẹgbẹ́jọdá ni tàbí aṣọ ẹbí ?

📸: E.H Duckworth Collection

28/05/2024

Would you use these local washing machines found here in Ivory Coast🇨🇮

Three Obas, who are members of the Ijebu-Ode Judicial Council circa 1940s.From Left to right - The Ajalorun of Ijebu-Ife...
25/05/2024

Three Obas, who are members of the Ijebu-Ode Judicial Council circa 1940s.
From Left to right - The Ajalorun of Ijebu-Ife possibly Oba Asani Mabadeje who became the Ajalorun in 1943, in the middle Olowu of Owu-Ijebu Oba Adelani Gbogboade and the Dagburewa of Idowa Oba Samuel Adebonojo 1.

📸: E.H Duckworth Collection

Address

Lagos

Telephone

+2348147052030

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yoruba Blog posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Yoruba Blog:

Share