Njẹ e tí e mọ wípé ọkọ ojú omi èyí tó kó àwọn Pastors(Missionaries) akọkọ wá sí ilẹ Yoruba láti wá polongo ìhìnrere Jésù na lo ko awọn babanla wá tí wọn wá polongo fún lọ sí oko ẹrú ní ilẹ Europe.
Orúkọ ọkọ ojú omi ọhún ní "SAO JOAO BAUTISTA" ní èdè Portuguese leyi to túmọ sí "SAINT JOHN THE BAPTIST"
Wọn mú ẹsin wá, wọn sí gba òmìnira àwọn baba wá.
ÌRÌN ÀJÒ A RÈ MÁ BO Episode 2 ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọrọ yi wá.
To be released on Monday on Kijipa TV
Àtùpà ìran ọmọ Yorùbá o gbudọ kú o.
Shirku o tu mọ sí ẹbọ. Ẹyin Alfa e ye bá èdè abínibí wá jẹ mọ nitori èdè lárùbáwá.
kínní ìtumò Shirku, Munafiqun ati Kafir?
E wo bí àwọn wọn yí ṣe gba ẹtan láyé tó wá ko wọn sí inú ìyọnu bayii. Onitiri Abiola àti Adele rẹ tuntun, e jáde wá o.
Ọmọ ọlọmọ lá n rán ní iṣẹ dé torutoru.
Kilode tí ìgbéraga pọ nínú ìwà awọn Musulumi ilẹ Yoruba na.
Imam Ogbomosho ṣe pẹlẹ, má dá ìjà ẹsìn sílẹ ní ìlú Ogbomosho.
I won't say pim than bí Ewúrẹ bá bójú w'ẹyin, a fí epe fún elepe.
Arigiṣegi to bá ṣẹ gi nígbó, orí ará rẹ ní fí iru. Ọwọ tí ọgẹdẹ bá sí gbé bayii, ara rẹ ní fí na o.
Epe ní baba yi fí n ranṣẹ sí ìran rẹ lórí minbari lojo ìtùnú awé. Gbogbo wasi wọn ori Kijipaoro lo da le lórí.
Alabosi a má sáré ní ìgbà tí a ko le. Baby tí seju ṣe gbọ, oju tí la baba.
Bí a bá tún sọrọ bayii, wọn lè ní a ní emi-mimo lára ní o jẹ ko ye wá.
E wá ra Omi asina nla o. ₦200 pere ní o.
Omi Abrahamu n ṣiṣe asiri owo nla o.
Abraham Nigeria incorporated lo tí jade.
Let's continue using religion to fool them jàre abi man must eat now.
Òhun gbogbo ní àwọn Alfa ilẹ Yoruba n tá ko pẹlu Islam leyi to fa tí ọpọ Musulumi o fí ní ilọsiwaju.
Awọn Oyinbo n fí ọpọlọ tí Olòdùmarè fún wọn mú nkán tuntun jáde fún ìwúlò àwon èyán. Àwa n fí ọpọlọ tí wá takò ohun dada tí àwọn Òyìnbó n ṣe. Ba wo wá ní a ṣe fẹ ní ilọsiwaju.
ÌRÌNÀJÒ A RÈ MÁ BO "The Journey of no return"
Episode 1: Ìran Yoruba Siwaju òkòwò ẹrú
"Transatlantic Slave trade"
Ìran Yorùbá wá ní iṣọkan pẹlu ọpọlọpọ ìdàgbàsókè eyi tí ọpọ ilú láti òkèrè má n tí torí rẹ wá sí ilẹ kaaro ojiire láti wá taja raja.
Ọmọ Yorùbá e jẹ a pàdà sí ìpìlẹ kí gbogbo òhun to bo mọ wá lọwọ o lè padà sí wá lọwọ.
Nṣe ní mo n gba orisirisi ìpe idunkoko mọ ní láti ọdọ àwọn Musulumi.
My life is been threatened by some unknown Islamic organization if I do not stop analyzing about Iṣẹṣe/ Islamic Religion. This is a call for us all to stop this bullying of people all in the name of religion.
I have evidences of their threat if I do not stop. I have written a petition letter to the security outfits to notify them of the incident. Must we use Religion to destroy our country when the countries who brought this Religion to us are enjoying and building their nation.
I will be forced to start dropping contacts of this people bullying me here for my people to help me greet them if they do not stop.
Letter already submitted to the NPF and the DSS.
Security outfits CSP Olumuyiwa Adejobi in south west and beyond, please take note of this
#NigeriaPoliceForce #DSS #NSCDC
#ANBROAD
Wọn ní kí ọmọ Nigeria kankan o má wá sí Saudi nínú Ramadan yí fún Humrah idi ní yẹn tí wọn o fí fún ọmọ Nigeria kankan ní visa.
Ogún ibí Saudi ní Kahaba, e jẹ a gbé òhun tá ní larugẹ.
Ẹyin eyan, e dákun e fí ara balẹ kí e gbọ ohun tó jáde ni'bi fónrán yí. A discussion between me and one of the brainwashed people who thinks they have knowledge of everything. This man thinks he has a better explanation of Q14 vs 4 and Q10 vs 47 that I explained in my previous video.
Please I will like people to tell me the difference between my previous explanation and what he explained because they just want us all to be MFM(Mumu follow Mumu) and just believe Muhammad was sent to the whole world.
Please watch to the end.
Ìrìn àjò ọsẹ mẹta kakiri ilẹ Yorúbá láti ṣe àwárí ohùn tó pàmò nípa bí wọn ṣe kó ìran Yoruba l'ẹru tí wọn sì fún wá ní ẹsìn láti lè wá nínú oko ẹrú titi lai.
Emi Omooba Adeola Adeyeye Kijipaoro ní yíó ma ṣe àgbéjáde ìwádìí yí ní ṣíṣe n tẹle sori ẹrọ ayélujára Kijipa TV
Láti ṣe iranlọwọ fún irinajo yí,
3046791253
First Bank
Ìràpadà ọmọ Yoruba ṣe kókó, o ṣe pàtàkì fún itẹsiwaju wá.
Ìdí tí Allah fí sọ Quran kalẹ fún Muhammad ní èdè Lárùbáwá àti ìdí pàtàkì tí ọmọ Yoruba fí gbodọ pada sí ìpìlẹ (Quran 10 vs 47).
Bí wọn ṣe ko 99 names of Allah jọ àti àwọn èpè tí àwọn Alfa n fí lárúbáwá ṣẹ fún àwọn ẹyàn nígbà tí wọn bá ní àwọn n ṣe adurá ní èdè Lárùbáwá.
Ọmọ Yoruba e yé yọjú rán ma. Òhun tí Olòdùmarè fún wá tí tó ṣe ayé wá.
Kò sí ohùn tó n jẹ orúkọ musulumi tàbi Christiani, Orisa mekkah ní Abdullahi baba Muhammad sìn titi tó fí kú.
Kí ló dé tí ọmọ Yoruba n tá ogún ibí wọn torí atije atimu. Itan o ní gbàgbé gbogbo ẹyin obayaje tí e mọ òdodo tí e sí n fí pamo láti tá ọmọ kaaro-o-jiire sí oko ẹrú.
Okuta ní àwọn Mùsùlùmí n sin gẹgẹbi Allah ní Makkah.
Kò sí ìran tí o ní nkán isembaye tí wọn. E ye ba nkan isembaye ìran Yoruba jẹ mọ torí àti gbé tí lárúbáwá ga.
E kaabo sí miracle center Hausa Islamic Pentecostal mission.
Nkan tí ṣe wá lorileede yí.
Irinajo itaniji nipa Iṣẹṣe sí ìpínlè Ekiti pẹlu Obaela Movement àti Ìràpadà ọmọ Yoruba.
Ilu Igede Ekiti la wá yí.
Irinajo itaniji nipa Iṣẹṣe sí ìpínlè Ekiti pẹlu Obaela Movement àti Ìràpadà ọmọ Yoruba.
Ilu Efon-Alaye la wá yí.