AatuAaro tv

AatuAaro tv AATUAARỌ; A unique Online tv program that showcases the rich culture and tradition of Yorubaland.

30/11/2024

ALL OTHER gods
are the works of men.
JEHOVAH.,
YOU ARE THE
ONLY GOOD GOD.
Hallelujah.. Amen.

AatuAarọ tv now on the Instagram.It's the new next and necessary.Indeed, we're moving on..Come., Let's explore together....
12/12/2023

AatuAarọ tv now on the Instagram.


It's the new next and necessary.

Indeed, we're moving on..

Come., Let's explore together.

Aatu Aarọ fún gbogbo wa oo..

12/12/2023

Now you can join us on Instagram.

You're highly and most welcome..🙏😃💞👍👏💝

NJẸ O MỌ ẸNI TÍ NJẸ KÌNÌÚN ẸYÀ JUDA..??Oya ẹ jẹ a kì, ki a dúpẹ fún un l'owurọ ọjọ ajé yìí.Oya sọ wípé;Modupẹ  Oluwa pe ...
11/12/2023

NJẸ O MỌ ẸNI TÍ NJẸ KÌNÌÚN ẸYÀ JUDA..??

Oya ẹ jẹ a kì, ki a dúpẹ fún un l'owurọ ọjọ ajé yìí.

Oya sọ wípé;

Modupẹ Oluwa pe mo ni ọ lati ma sa ba ..
modupẹ Oluwa pe mo ni ọ lati ma f'ọrọ lọ ..
ọpẹ l'ọpẹ rẹ ayé ì bá ti k'ẹru mi s'igbo, ọpẹ l'ọpẹ rẹ, ayé ì bá ti k'ẹru mi danu, mo yin ọ o Jesu, pẹ mo ni ọ lati ma sa ba,
mo yin ọ o Jesu pẹ mo ni ọ lati ma f'ọọrọ lọ...........................

A kú ojúmó ire o gbogbo ẹyin ololufẹ wa, Ohun gbogbo aa túba, aa túṣe fún yín loni, l'ose yi, l'oṣù yi, ati l'ọdun Titun to mbọ.

Our God is Glorious, Marvelous,..Wonderful.
Ohun ni KÌNÌÚN ẸYÀ JUDA...

Jọwọ, bami fi ọrọ iyin tire náà kún eyi lédè tó wù ọ.

Bàbá wa gbọ gbogbo rẹ..

Ọlọrun fẹràn orin iyin idupe yi gan ni.

Njẹ o le pẹlu mi kọ orin yìí sì Ọlọrun ni owurọ yi.

Halleluyah..!!!.

Tẹ Halleluyah sí ori fọran yii ki ọ fi se àfihàn rẹ pe lóòtọ lo fẹràn Ọlọrun, ati wipe ohun ọpẹ rẹ pọ púpọ síi.

Aatu., Aarọ ooo... Amin.

A kú ojúmó ire óò gbogbo ẹyin ololufẹ wa, ṣe dáadáa la bàa yin??Ṣe alafia ni gbogbo ilé wà??Aatu.. Aarọ óòEjowo ẹ gbọ ná...
07/11/2023

A kú ojúmó ire óò gbogbo ẹyin ololufẹ wa, ṣe dáadáa la bàa yin??
Ṣe alafia ni gbogbo ilé wà??

Aatu.. Aarọ óò

Ejowo ẹ gbọ náà..

Kínní orukọ ti wọn npe irú agbọn yí l'ọdọ ti'yin n"ilẹ kaarọ oojiire

É tun lè béèrè lọwọ ẹlòmíràn fún àlàyé kíkún..

















05/11/2023
05/11/2023

A kuu dede iwoyi o gbogbo ẹyin ayanfe wa.. ṣe dáadáa la bàa yin?

Ilé wa aa r'oju., ọna wa aa ráyè..
Ohun gbogbo aa túba., aa túṣe fún wa óò.. Àmín àṣẹ.

Eyin ènìyàn wa nílé, e gbọ, kinni orukọ ti eyin npe iru ẹyà ẹja yìí l'ọdọ ti yin..??

27/10/2023

Be prepared..
Aatu Festival is coming..!!!
Are you Professional Craftsman in all art world ??
DM to register your company.
WhatsApp on 08030664979.

Address

Ojo

Opening Hours

Monday 09:00 - 22:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 14:00 - 22:00

Telephone

+2348030664979

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when AatuAaro tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to AatuAaro tv:

Videos

Share

Category