03/12/2024
E JOWO SIR/MA MOFI OLORUN BE ENIKENI TIO BA RI POST YI KIE TRY LATI SHARE POST YI KAKIRI SINU AWON GROUP MIRAN TIE BAWA ATI SI AWON ENIYAN 20X TIO FERAN JULO TORIPE A LE SOPE IRO NI KIO PADA DI OTITO... AO NI DI ADORUN MOTITO OOOOO
EMI ( SPIRIT) OLUWA NBE NINU ILE ( HOUSE) YI OOOOO π KIO FI ARA HAN - A MUMI RI OPO AWON ENIYAN KAN, SUGBON GBOGBO AWON ENIYAN YI OBINRIN NI GBOGBO WON JE, BENI MORI IRAWO ( STAR ββ¨β ) TIO NTANA GIDI GAN NI AGBARI OPO AKAIMOYE AWON OMO BINRIN WONYI , SUGBON IYALENU NLA TIO WA YAMI LENU NI WIPE π LOJUKANNA NSE NI AWON IRAWO YI SI BERE SINNI DEDE PORA ( DISAPPEAR ) NI AGBARI AWON ENIYAN YI, IPEKUN NLA MUMI NINU IRAN YI π MO BA SA DEDE RI ENIKAN NI EGBE MI LOJU IRAN YI SUGBON MIO LE SO BOYA OKUNRIN TABI OBINRIN NI ENI TIMO RI NI EGBE MI YI, MO WA NBERE LOWO ENI YI WIPE π E DAKUN KILODE TI AWON IRAWO YI FI NPORA NI AGBARI AWON ENIYAN YI BAI - ENI YI BA DAMI LOHUN WIPE π SEBI MORI PE KI NSE GBOGBO WON NI IRAWO WON NPORA , SE MORI AWON OBINRIN TI IRAWO WON NPORA YEN, AWON NI OPO AWON OBINRIN TI ORI WON MA GBABODE, TAWON ALAGBARA AIYE YIO LO OGO ATI IRAWO WON LATI PELE AJE ATI OOLA FUN ARA WON LATARA OJU KOKORO ATI AINI ITELORUN AWON OBINRIN WONYI ,.. IRU AWON OBINRIN BE NI MORI TI IRAWO WON NPORA YEN, BI IRAWO WON SE NPORA TIMO RI YEN , BE GEGE NI IFASEHIN, AIRISE, IJAKULE, PROMISE AND FAIL, AMUBO, WAHALA, IDAMU, ATI IKU OJIJI YIO SE BERE SINNI FARAHAN NINU IGBESI AIYE OPO AWON ENIYAN PAPAJULO AWON ODO BINRIN FROM 22 YEARS UPWARD , ANU NLA NSEMI OOOOO TORIPE OPO AWON ABIYAMO NIYIO SUN EKUN KIKORO NI IPARI ODUN YI SI JANUARY 2025....HUMMMMM OLORUN SHANU AWON ABIYAMO WON YI OOOO MAJE KIWON FOJU SUNKUN
MO WA NBERE LOWO ENI TIO NBAMI SORO YI WIPE π E DAKUN KIWA NI ONA ABAYO TIYIO MU KI IRAWO AWON OBINRIN WONYI KOFI NI DI TELOMI RAN, TIWON KOFI NI DI OHUN ETUTU OOLA FUN AWON ALAGBARA AIYE - ENI YI WA NDAMI LOHUN WIPE π AYAFI TIWON BALE GBINYANJU LATI LOSE ATUNSE AWON NKAN WONYI π
1 ) KIWON MASE RIN IRIN ALE KAKIRI MO LASIKO YI T**I TI AO FI KE HAPPY NEW YEAR..
2 ) KIWON KIYESI ARA NIPA LILO KI ENIKENI NI ILE ( HOUSE ) LATI ASIKO LO T**I TAO FI KE HAPPY NEW YEAR...
3 ) KIWON KIYESI ARA NIPA IBALOPO ( S*X ) KIWON MASE TITORI OWO S*X PELU ENIKENI TI OKAN ( MIND ) WON KOBA BASE IBALOPO ,
4 ) KIWON MASE LO FI IJA GBAA OWO TABI OHUN KOHUN LOWO ENIKENI LATI ASIKO YI T**I TAO FI KE HAPPY NEW YEAR..
5 ) KIWON MASE YA ENIKENI NI A*O ( CLOTHES) TIWON NWO TABI BATA ( π©΄π©΄π©΄π©΄ ) TIWON NWO JADE BIO TIWU KIRU ENI BE SUN MOWON TO LATI ONI LO T**I TAO FI KE HAPPY NEW YEAR 2024..
PATAKI JULO KIWON GBINYANJU LATI LO SE AKANSE ETO ADUA IRAPADA OGO FUN ARA WON, TORIPE LOWO LOWO BAYI OPO AWON TOKUNRIN TOBINRIN LO NBE TIO JEPE AWON ALAGBARA AIYE TI GBE OOWO LE IRAWO ATI OGO WON, TIO JEPE WON KO NSISE BI ERIN LASAN NI IJE EERI NIWON NJE, WON NSISE LOTITO SUGBON WON KONI AKOJO NIDI ISE TIWON NSE, WON NRI OWO LOTITO SUGBON WON LE TOKASI OHUN PATAKI TIWON NFI OWO SHE, BIWON KOBA NA OWO KAN TA , WON KI NRI OWO MIRAN GBAA ATI BEBELO ETC .... IDI NIYI TIWON ENIYAN TIO NKA ATEJISE YI SHE GBODO GBINYANJU LATI TUNBO MURASI ORO IGBESI AIYE RE TORIPE IKOKO ( PUT ) TIO BA MA JE ATA IDI RE YIO GBONA...
WO AWORAN ARABINRIN TIO NWO NI ISALE YI - TI KI BA NSE WIPE AWON ALAGBARA INU AIYE TILO ARABINRIN YI SHE O LERO WIPE YIO SE BAYI MURA LAWUJO OPO AWON ENIYAN, AMON ARABINRIN YI GAN KOMO NUKAN TIO NSE RARA , IYEN NI WIPE WERE ( MAD ) KI NMO WIPE ONU YA WERE, KANI WERE MO WIPE NUKAN NSE ONU NI, WERE KONI MA RIN KIRI NI IHOHO LAI MA WO A*O GEGEBI ARABINRIN TIO NWO YI NA SE NRIN NI IHOHO..
NITORI NA MO FI POST YI GBADUA FUN GBOGBO EYIN ENIYAN TIE BALE TE AMIN NLA META SABE POST YI LORUKO JESU π AWON ALAGBARA AIYE TIN MA NGBA IRAWO ATI OGO ENIYAN NINU AIYE WON KONI RI IRAWO ATI OGO IWO ATI AWON OMO RE GBAAA BEEEEEEEEE ORO JADE ASE ORUN GUN... AMIN AMIN AMIN AMIN OOOOOO JESU OLUWA.
NITORI NA π MOFI OBA TIO NI EMI ( LIFE ) MI BE GBOGBO EYIN ENIYAN TIE BA RI ATEJISE YI KA - LATI SHARE POST YI KAKIRI SINU AWON GROUP TIE BAWA PATA BOYA LORI FACEBOOK NI, TABI LORI WHATSAPP - KI IRAN YI DE ODO GBOGBO AWON ENIYAN PATA - MO GBADUA FUN GBOGBO EYIN ENIYAN TIE BARI AMIN NLA META TE SABE ATEJISE YI π LOPIN ODUN 2023 TIA WAYI - O NI WA LAAYE BI ALAISI BEEEEEEEEE... ORO JADE ASE ORUN GUN... AMIN AMIN AMIN
JE KIO SHE PATAKI FUN E LATI FI ADURA YI RANSE SINU GROUP MEWA OTOTO KI OPO AWON ENIYAN LE JE ANFANI ADUA YI )
( RI DAJU PE O TE AMIN SABE ATEJISE YI OOOOOOOO.. )
U CAN CONTACT FOR NEW MONTH PRAYERS, OR SPIRITUAL CONSULTATION ABOUT YR LIFE MARRIAGE RELATIONSHIP BUSINESS. ETC WITH THIS HOT LINE WHATSAPP - +2348147521614, 08146222602.