ASIRI IRAWO TV YouTube Channel

ASIRI IRAWO TV YouTube Channel Astrology and Numerology.... You can knows your Star and Everything about your life here

Lati wo awon video mi Lori YouTube @ Asiri Irawo tv, E click Lori link towa ni isale Yi Lati wo video Lori gbogbo Irawo ...
10/06/2023

Lati wo awon video mi Lori YouTube @ Asiri Irawo tv, E click Lori link towa ni isale Yi Lati wo video Lori gbogbo Irawo Toba Fe,

E bami click Subscribe, Like Ati comment si Abe video na, Fun gbogbo Iwo Toba subscribe labe video na besini tio comments sibe, kio screen shot comment re Ati subscription yen Simi Lori Whatsapp, mo ma bae sewadi Lori Irawo re Lai gbowo kankan Lowo re.

Whatsapp 08149304714

https://www.youtube.com/live/MUJknN8vdQI?feature=share

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun

A SPECIALIST ON ASTROLOGY AND NUMERALOGY

*OMO AJÉ ÀTI ÌRÀWỌ* Púpọ Ni Eda Eniyan ni ko mọ pe Ajé ati irawọ ùn tele arawọn, besini ki Eniyan Meji jo ma Lo iru iraw...
11/06/2022

*OMO AJÉ ÀTI ÌRÀWỌ*

Púpọ Ni Eda Eniyan ni ko mọ pe Ajé ati irawọ ùn tele arawọn, besini ki Eniyan Meji jo ma Lo iru irawo kan na ko sowipe bakanna ni Aje ati Arisiki Ara yin se ma ri, Akosejaye yin loma Salaye bi irin ajo aye eda kookan se ma ri fun-un.

Nje iwọ mọ pé ọpọlọpọ irawo ni oti fii àjé ara rẹ raa re idi niyi tii wọn fii ùn wa laye bíi aláìsí ṣugbọn ni wọn ba igba ti wọn ti Elédùà bati sinu anu wọ wọn konisi iṣoro

*AWỌN IRAWỌ TI ONISE PELU AJÉ*

*IRAWỌ INÁ*

*Bíi èyán bajẹ irawọ Ina oseese kii oni aje lára níwọ̀nba igbati ohun ati ọmọ eléré ti oni aje lára ba fẹ arawọn

*Ninu awọn ipin iseda irawo ina wa ti ojẹ alaje ọmọ ṣugbọn oye ki oṣẹ àwárí ara-re kii àjé yìí lè wúlò fún t**i di ọjọ alẹ

Bíi gbogbo iseda ba ṣe àwárí arawon konisi wahala agaga obinrin tii ojẹ alaje ọmọ

*Bíi irawọ *INÁ TOGBONA RIRI(Leo) bafe gbogbo ipin iseda irawọ omi tii obani Aje lára otidi dandan kii ògo rẹ bú yọ

*ERUPE FÚNFÚN* (Virgo)

Ajé wá nínú gbogbo ipin iseda yii ṣugbọn wọn kii ùn tètè se awari arawọn nítorí pé gbogbo iseda yii ati *ISEDA OKUN* 👑 jọ níí Ajosepo Besini Latara Eewo Jije Lori Nkan toyeki won Sora fun ni awon onirawo yi se man se wahala besini ti isoro si man po funwon, Sora fun Eewo jije.

*AFẸFẸ ALAWADA(Gemini)

Omo Elegbe Lo fe poju ninu awon irawo yi besini Alagbara Eniyan niwon, Ase man wa Lenu won, nigba kekere won ni won ti man sise iyanu, bii ki won Sa deede Daku(faints), kiwon soro besini ki oro na se,

Ami olohun tofe daada man foju han Lara won besini Eleyi ni Itumo ati Akiyesi Lori e, ìgbà tí Àjé bati wa lára iseda yii odidandan kii owo ati aje bagbe ṣugbọn kii iru enibe tètè mu àjé lo nítorí pé bíi eni ṣe rí ọla ko rí bẹ sugbon O gbodo mo Bose ma setoju Aje Ara re besini kio mo iru egbe tohun wa gan,

*PÚPỌ NÍNÚ AWON IPIN ISEDA IRAWỌ TI ONI ÀJÉ LÁRA*

ERUPẸ FÚNFÚN (Virgo)

OMI TI KIIRU (Pisces )

AGBÁRA OMI (Cancer )

IRAWO AFẸFẸ

Aìmọye awọn ipin iseda yii ni o jẹ ọmọ Elegbe besini Latara iwadi Akosejaye Latima mo iru egbe ti Eda kookan ni,

Asiwaju ni Olohun se Elomiran lori ile aye besini Arisiki pupo wa Lara re sugbon Aise-Awari Ara re tiso di Eniyan yepere,

Aimọkan ti sọ ẹlòmíràn di ẹni Ero Eyin, Iru won Po Púpọ ninu ẹda ènìyàn, Melo Melo Eniyan Loni Arisiki pupo Lara sugbon won kojeki Ariksiki na sise fun rara, Iwo omo Alaje toni aje lára ti komo ọna lati gba lo ajé ara-re nigbati kose awari Ara re 🤴, Iranse miran koyeki o ma toro je tabi rarun Owo rara sugbon Latara Aikiyesi Ara, O ti je ijekuje, O ti mu imu kumu, O ti se isekuse, awon nkan yen Lon Affect aye re,

Ajé wá lára opo eniyan ṣugbọn bíi wọn ko ba níí àkíyèsí lori irin ajo ayé wọn oseese kii àjé arawọn mase wúlò fún wọn

Imole towa Lara obinrin miran Po pupo besini Latijoti okunrin kan ti gori re ni Imole na tiku, besini Okunrin miran Obinrin Losodi Ero eyin, latigbati Iwo ti ba obinrin na Lajosepo ni wahala ti deba isemi aye re, sewo ko fura ni?

Iwo ti iyawo re ni oko orun, tiwo ko wa Ona Abayo fun, o wan sowipe nkan daru fun idile yin, besini Okunrin ti ohun na ni aya orun tabi ogun idile , Iwo ko bere Ibiti isoro re tiwa, o wa Siwipe on gbadua, sewo mo Ibiti o fe doju Adua re ko? Abi Iwo kan gbadua lasan , Ma se fi Akoko re Sofo rara,

📝 note;
- Ori iseda miran kogbodo pariwo Toba fe se nkan.
- Iseda miran kogbodo ma se Sina nitoripe Ogo re ma ma dinku ni.
- Alagbara eniyan ni iseda miran gbodo fe gegebi Alfa, woli tabi Adahunse

Bere Ona Lowo Eniti O mona, Iwo yoo si ri Oju Ona rere(Adept Adewumi)

To watched my Video On YouTube About Star, horoscope and Life predestination @ Asiri Irawo Tv

Fun Iwadi Ati Ona Abayo Lori Gbogbo nkan Ton Sele si e, 📞/ WhatsApp 08149304714

Fun Iwo Toba fe join WhatsApp group wa :- Click this link below 👇

https://chat.whatsapp.com/Lbq3ujExmv58mUkacVnKUJ

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun

04/02/2022

ADANWO IGBEYAWO 🤼

SABABI ISORO LAARIN OKO ATI AYA

Orisi Isele Lon Sele Laye Lasiko yi Lori Igbeyawo besini Orisirisi Isoro ni Okunrin ati Obinrin n koju latara Igbeyawo,

Nitoripe Ogun Ibujoko Ati Isoro Ailori Oko/Aya po pupo tofijewipe kofe si Omoge mo Nile aye ayafi Enitoti bimo ti kosi ni Oko tabi Ade Ori mo, Elomiran wa tojewipe Isoro t**i re Afowofa ni besini Ogun Aye ni Telomiran,

Awon Ona ti Isoro Igbeyawo fin Po pupo ninu Awujo wa niyi:

√ Ifojusona ati Iwadi Sise; Ni Aye Atijo ni Ifojusona ati Iwadi sise fese mule daada Sugbon Lasiko yii, Olaju tidele aye besini Olaju na Lowan baye wa Je Lo Tofijewipe Aye kofe ni Isinmi mo rara.

*Aisewadi Lori Idile tio fe dapo Laarin Oko ati Iyawo re, Nigbati Eda koba sewadi Lori Iru Idile toti fe Lo fe won, Obinrin ati Okunrin man Saaba ni Isoro Lodo Awon Ebi won,

√ Eko: Obinrin ati Okunrin tiwon koba mature tobi o se yen tabi tiwon koni Agboye Lori Igbeyawo boya Ojo ori won kere ni tabi Iwa won ko papo, Eleyi na man fa Wahala Laarin Oko ati aya tosi man pada Lead si divorce

* Iwadi Sise Lori Irawo ati Akosejaye won: Pataki Ni Iwadi Sise Lori Irawo ati Akosejaye Irin ajo eda, Eleyi Loko gbogbo Eyikeyi Iwadi Sinu Nitoripe Ohun Loma Salaye Awon nkan bi marun funwa:

*1* Se Ibagbewon ma rorun papo, Se koni si wahala ati Idaamu ninu Igbeyawo won
*2* Se Omo wa Laarin yin besini Iru Omo Wo Niwon maa bi...
*3* Se Elemi gigun niwon ati iru Isoro wo Loma sele laarin won
*4* Se Koni pada si divorce Laarin won Atiwipe kini Saara won
*5* Se Arisiki Ara won bara won sise papo, Atiwipe Iru Arisiki wo lowa lara oko ati Iyawo re,

Fun Iwadi Irawo Ati Akosejaye
Fun Iwadi Nipa Igbeyawo re
Fun Iwadi Lori Ohunkohun toba fe mo
Fun Ebe Adua Ati Ise Itoju ara gegebi Itaja, Eyonu, Osole tutu, Isora ati Bebelo 08149304714(whatsapp) or 08029545972 📲

Latowo Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun Baba Logijo

16/01/2022

IPILE ASIRI IMO IRAWO

Ninu Igbagbo Awon Oni Mimo Ijinle Nipa Isiro Ounka(Numerology), Onka Eejila(12) Je Onka ti Olohun Adeda gbe kale fun was lati ibere pepe ibere aye, Eto Olohun si ni pelu(Divine Chronological Completeness) E wo Inu Al-Quran Ori kesan, Ese kerindinlogoji (Q 9:36),

Iyipo Osu(Moon) ni Iyipo Osupa kan (in a month) ni Emeejila (Osupa Mejila) Eyi ni ounka odun kan, Atiwipe fun Idi Imo Irawo Mejila (Twelves Zodiac Sign) ati Ounka Eejila(12) Mule Ninu Imo Ijinle Ounka Ati Isiro (Numerology) oni Afijo nipa wakati mejila ti Ojoojumo (Hour of the night) Eyi tun fi Idi irawo mule wipe imo Ijinle yi wa Lati Odo Olohun Adeda ti Olohun si fi imo Ijinle Nipa Irawo yi ran Anobi Wa Idris (Enoch) Eyiti opo eniyan ri itosona nipase re Al-Quran ori kokandinlogun ese kerindinlogota (Q 19:56), Eyi ti o se wipe Nipase IMO irawo yi ni a se gba laaye to se wa ninu ogba idera ni eniti ko to ikuwo(Not taste death) Eniti o wa ninu ogba (Heaven) lati igbahunni wa t**idi isinyi nipase Imo Irawo, Eyi ti Olohun fi ta loore tosi je eniti akoko to pile imo ijinle nipa Eso oju Orun, ati ipa ti imo ijinle yi ko nipa isemi aye Omo Eniyan...

Note: Anobi Idris (Enoch) Ni Eni Akoko to koko Lo IMO Irawo gegebi Itosona...

Fun Iwo tio ba fe Sewadi nipa Irawo re Ati Akosejaye re, Latimo nipa Awon Isoro ati Ona Abayo re 08149304714

Latowo Oludasile Dr Adewumi Ase-Olohun

13/10/2021

ASIRI IRAWO PISCES(HUUT) 🐟

ORIKI AWON ONI IRAWO PISCES
Eleyin Aanu, Enito n gbadura Pelu Ohun rara , Niwaju Olohun, Mo Soore kogbemi O Lowo kan Ika Ninu ni, Haaaa! Pieces Sora fun Eniyan besini Kio Ma Se Saara Odo...

ISESI ATI IHUWASI WON

Awon tia ba bi Labe Irawo yi Gbodo Sora fun Eniyan besini kiwon Sise Ibujoko Nitoripe Latara Iru Eniyan tiwon je, Eon kii fe ri Ibujoko Lori Oko besini Awon Okunrin won na man ni Isoro Iyawo ,

Irawo Omi niwon Sugbon Irawo Omi tiwon Je yen Ko sowipe kiwon Je Omo Elegbe Omi, Latara Akosejaye won Latima mo Iru Eniyan tiwon je Ati Iru Egbe tiwon wa,

Pisces Je Arewa Eniyan ti ara won yoo ma tutu nigba gbogbo, Eru man ba Pieces besini Won ko Lagbara Latise Ise wahala rara, won man feran faaji pupo pupo besini Won feran Ariya Sise, won man saaba ko ore pupo,

Pisces feran Latima so ododo besini tiwon ba paro gan, Lesekese Latima mo wipe iro niwon pa, Olohun bun won ni Ewa pupo besini Adufe niwon je..

Planet Neptune ati Jupiter ni Oludari won,
Lucky colour: Green, white
Lucky day: Thursday

Fun Ekunrere Lori Irawo Ati Akosejaye re 08149304714

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun

25/07/2021

Fun Gbogbo Iwo toba fe Wo Video wa Lori Alaye Irawo re, Click Asiri Irawo TV" Leyin na E ma ri A won video wa Nibe besini kie ma bawa subscribed sori re

01/05/2021

IRAWO TA**US 🐂 - AKU OSU TITUN

البرج الثانى: و هو برج الثور والزهر ة ترابى

√ Buruji Keji Ninu Awon Buruji Mejila towa Fun Omo Eniyan ni Ta**us.

√ Gbogbo Eniyan tiwon bi Ninu Osu April 21 - May 20 Ni Won Ni Irawo yii ninu Lilo Ilana Date of birth besini Awon Iseda kan nlo irawo yi ni ilana Oruko(Olohun Loba Onimimo).

√ Kise date Oyinbo Ni Eniyan fi man Sewadi Irawo kookan Losoosu besini Kise ogbon ori rara, Osu Oju oorun ni, E ma ri wipe kosi osu irawo kookan to bere lati January 01 si January 31 rara,

ISESI ATI IHUWASI WON
A Ma da Awon tiwon ba n lo Iru irawo yi mo latara Ami Agbo ♈ 🐂 besini Yerupe ni, besini Kaokab Zuarat Lon Se Oludari Irawo yii Pelu,

√A ma da won Pelu Ibanikedun besini Onirin ajo niwon, won man je Olutepa mo ise pupo nitoripe won feran Ise owo, Ise agbe tabi t**i oja agbe dara funwon pupo Sugbon Akosejaye re loma salaye Ise Asela Eda kookan besini Ohun loma salaye iru eniyan ti EDA kookan je boya omo Alagbara ni tabi Elegbe omo ni...

√ Won Je eniti o man dunu si nkan rere besini Ologbon omo niwon besini Won gbodo ma se saara daada sile nitoripe irawo ile niwon,

√ Ebun orin kiko, Osere ori itage, Ewi k**e, Agbe ati Bebelo wa funwon sugbon kiwon sora fun mimo soro aye won fun ore tabi eniyan kan, nitoripe won ma pada gba Abode fun...

√ Irawo yi ni Eewo ti kogbodo Se tabi Je, oni Lucky day, Lucky Colour, Master prayer, Lucky Sacrifice ati bebelo ninu Iwadi Sise Latima salaye re papomo Akosejaye re Lekunrere fun e,

√ Note: Kii se dandan ni kio wa s**o mi kin to bae sewadi na, Opolopolo eniyan ni mo man se fun lori whatsapp tabi facebook... Oruko, date ati aworan atelewo re na Lama lo fun iwadi sise na besini 2000 lowo iwadi sise na, Laarin Ogun Iseju toba sanwo re, o ma gbo Esi ayewo re..

Fun iwadi Irawo ati Akosejaye re Call/Whatsapp 08149304714

Fun awon video wa, Search on youtube "Asiri irawo TV" ki bami Click lori Subscribed koni ja data tabi owo re rara,

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-falaahy Ase-Olohun(Baba Logijo)

Fun Video Nipa Irawo Ni YouTube Search For "ASIRI IRAWO TV" Or Click the link below to join and click subscribed under t...
23/04/2021

Fun Video Nipa Irawo Ni YouTube
Search For "ASIRI IRAWO TV" Or Click the link below to join and click subscribed under the video and watched it..

https://youtu.be/OEpLwwrNW7c

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun (Baba Logijo)

AN STROLOGIST AND NUMEROLOGY

AJODUN ASIRI IRAWO 2021Eleyi Je Awon Aaye tia Pese Sile fun Gbogbo wa Latise Ijiroro Lori Bia se ma se Ajodun todun yi L...
20/04/2021

AJODUN ASIRI IRAWO 2021
Eleyi Je Awon Aaye tia Pese Sile fun Gbogbo wa Latise Ijiroro Lori Bia se ma se Ajodun todun yi Leyiti o ma waye ni September 26 - 2021,

Awon nkan tia ma soro Lee Lori Niyi:

√ Oro Lori Bia se ma yan A*oju Ilu Kookan
√ Idanileko Lori Irin Ajo Aye
√ Eto Iran Araeni Lowo Lowo Isoro ati Ona Abayo
√ Ekunrere Imo Ati Alaye Lori Irawo ati Ohunkohun toromo Eto Igbese aye Eda
√ Ijiroro Lori Bia Se ma seto Ajodun tofi ma Yewa Lojo Yen daada
√ Yiyan Awon A*oju Wa Nilu Kookan

Fun Gbogbo Awa tia ba fe Join wa Ninu Whatsapp group 👇

https://chat.whatsapp.com/KPr40MgvRmFEXRN25JnWSn

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun (Baba Logijo)

WhatsApp Group Invite

13/04/2021

ASIKO AWE - Ramadan Greeting

Moki Gbogbo Ile Wipe Aku Odun Awe yi o, Olohun Yoo Basiri Enikookan wa, Agbara Wibejebe Olohun Yoo farahan ninu aye wa, Asiri wa Konitu Laelae. Istijabah Inu Osu Alubarka yii Yoo je t**iwa Pelu Ase-Olohun, Olohun yoo so Ekun wa derin Bijahi Muhammed Rosullulahi Wa Sheikh Ibraheem Gaosu Zaman (Amin)

Iwo tio ba fe ki Adua yii Je t**i re kio Se Amin Adua na...

Mon reti nkan Awe mi Lodo Eyin Members toba duro tokantokan pelu wa, Olohun yoo San Onikaluku Lesan Ise toba Se,

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun(Baba Lo'gijo

07/04/2021

ILE ATI EKA FUN IRAWO KOOKAN

Irawo Kookan Loni Ami Idanimo re besini Irawo kookan Duro gegebi Orike Ara kookan, Malaika kookan Lowa fun Irawo kookan besini Kawakibb(Planets) kookan n Sise pelu irawo kookan, Irawo kookan ni Ojule Pelu Onka(Number) ati Aropo(Total number) kookan.

Imo Irawo koja Imo ti Eniyan ma sowipe Ohun mo nipa re tan patapata, Olohun Nikan Loba Onimimo besini Anabi Muhammed Loga Imo.

Awon Eniyan kan ko gbagbo ninu Mi ma fi date of birth wo irawo besini awon kan ko gbagbo wipe oruko lodara latifima Sewadi irawo re,

Ki Eniyan tole Ma Se Idajo Laarin nkan kan wipe nkan bayi dara, nkan bayi kodara, Oni Latini Imo Todaju Lori Awon nkan mejeeji daada Latimo Eyiti o dara julo ninu mejeeji Sugbon Opo awon eniyan tiwon sowipe date of birth kodara, won komo lilo re ni, besini opolopo eniti o sowipe Oruko kodara won komo nipa lilo ilana oruko ni, Mejeeji na Lodara sugbon Emi Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun Sofun yin Loni wipe Lilo Date of birth Lo dara Julo besini Ohun Loman Soro nipa Igbese aye eda julo ninu isesi ati Ihuwasi re,

Ti mo ba ba eniyan kan Sewadi irawo re ni Ilana date ati oruko, timo wa salaye Isesi ati Ihuwasi re Fun e, O ma ri wipe isesi ati Ihuwasi Lilo date loma papomo t**i re besini Iwa ati Isoro toma koju re loma jade ninu lilo date ye,

Sugbon lilo oruko na dara besini Eniyan Lee Lo ilana na fun eniti koba mo date re, O ma sise lilo ilana date na sugbon iru irawo toma mu jade koni je iru irawo tojade ni lilo ilana date rara.

Ojo tiwon bi Eniyan Se pataki pelu asiko tiwon bi eda kookan,

Fun Apeere: won bi eniyan kan ni march 22, 2pm osan, besini won bi eniyan miran na ni march 22 2am owuro,
Se Iru irawo kan na niwon?
Se isesi won ma dogba ?
Se Bakanna ni ayanmo ogo won se ri?
Se Akosejaye won papo?
E dahun ibere yen gbogbo ile, Ebun wa fun eniti o ba gba Gbogbo ibere na...

Fun Iwadi Irawo ati Akosejaye re call / whatsapp 08149304714 @ #2000

Join us on Asiri iraw TV on Youtube
Latowo Baba Lo'gijo.. Dr Adewumi Ase-Olohun

06/04/2021

AJOGBE IRAWO OMI ATI INA

Lotito ni Opo Ninu Awon Onimo Nipa Irawo Kofi owo si Ajogbe po Adamo Ina ati Omi, nitoripe Omi yoo pada pa Ina besini Omi yoo ma ko Inira ba Igbese aye irawo Ina, kooda bio je Oko ati Iyawo, Ni gbogbo Igba tiwon ba tin Lajosepo Laarin Ara won ni Arisiki won ma ma dinku Latara Adamo tiwon Lo, Won Ma ma Ja Lainidi kan pataki Nitoripe Nigbogbo Igba ti Ina bati foju kan omi ninu ma ma bi, besini nigbogbo igba ti omi bati ri ina loma dabi wipe kio pa Ina, Nitoripe Ija won ma pada fa Ikosile(Divorce), Ajogbe po won kole rorun Sugbon tia ba sewadi Lori Akosejaye oruko won pelu Imo Arafi (Ilimul Huruuf) Osees kio ni Atunse besini kiwon fera won Laisi wahala kankan nitoripe Elomiran tie ro wipe irawo ina ni Sugbon Omo Omi ni, awon yen Lee fera won Laisi wahala kankan.

SISE PAPO
Irawo Omi Ati Ina Lee Jo Sise Papo Laisi wahala kankan Nitoripe Sugbon Won gbodo ni Suuru gidi gan Laarin ara won nitoripe won ma pada tuka nigbeyin nitoripe won koni gba funra won latara Aifinu han ara won.

IRAWO OMO ATI OMI
Irawo Omi ati Omi dara Latife ara won ti Akosejaye won bati papo nitoripe kise gbogbo eniyan toba je omi ni omi Lee fe gegebi oko tabi Aya, Odara Latijose Ore tabi Fera won Sugbon Awon Mejeeji ma Jo ma se oga Laarin ara won,

Note: Opolopo Idile Loti daru Latara Aisewadi Siwaju kiwon ma to fera won besini Elomiran Sewadi sugbon Kise Ilana Irawo ati Oruko ni won lo fun Iwadi na, wahala wa pada deba won.... Olohun koni sowa nu o....

Fun Iwadi Nipa Irawo, Akosejaye ati Igbeyawo re Call/Whatsapp 08149304714

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun[Baba Lo'gijo]

KOKORO 🔐 ADUA 📿 Oni ni Nisfu Sahban Ojo Atunyan Kadara, Olohun oba Feran wa Pupoju nitorina Lose fi Awon Ojo Kookan Sile...
28/03/2021

KOKORO 🔐 ADUA 📿

Oni ni Nisfu Sahban Ojo Atunyan Kadara, Olohun oba Feran wa Pupoju nitorina Lose fi Awon Ojo Kookan Sile funwa Gegebi Ojo Atunyan Kadara Ati Ojo Gbigba Adua wa,

Lara ojo Gbigba Adua Atunyan kadara Lojo Oni Sunday Je, Awon Onimimo Man pe ni Alaruba Kokoro 🔐 tabi Oru Atunyan kadara, Asiko yi ti bere lati Oru Ana t**idi oru oni,

Gbogbo Eda ti o ba fe Se Atunyan kadara re Si daradara tabi Gbogbo Eda ti Ipo towa loni kodunmo ninu boya latara bi Igbese aye re se ri lofa nkan bayen tabi kadara re ni, Kikode tiwo kose fi Asiko gbigba adua yi be Olohun kio wa wo boya Olohun man gbo Adua, kio wo boya Adua man gba tabi koki gba...

Mofi Eleyi Sile fun Awon Onirawo Misaanu(Libra) ⚖ ti emina je okan lara won pelu awon Onirawo Aries 🐏

Adua Fun Libra ⚖
Gbiyanju Lati yan Nafilat Rakat Merin, Fatiha kookan lori Iduro kookan, Quli huwa Lahu meta, Ekeji fatiha kan, Quli huwa lahu mefa, Eketa fatiha kan, Quli huwa lahu mesan, Ekerin fatiha kan Quli huwa lahu Mejila Leyin na o ma salamo leyin na o ma joko Lori A*o blue tabi brown, o ma wa se Adua yi: Lojo Sunday Oni 1-2:05pm, 8-9:25pm, 3-4pm, 9-10:15pm,

Adua na Niyi 📿
O ma ka fatiha Lati bere debi SIRATA LADHINA ANIAMTA ALAEHIM (2588), Leyin na o ma ka fatiha na pari..

O ma se Adua Lori Gbogbo Nkan toba fe patapata, ki olohun Alaanu Se Atunse lori Oro re Niti daada, ki odun yi Je Odun Ayo ati Igbega fun e

Pelu Khutubah re: Allahu Badihu Waduudu Ayu Li Qoyuum dhulijalali Wali qiroomi (Onka re)

Saara re: Iyo Ati Sugar Pelu Owo

Fun irawo Aries
Rakat Meta, Fatiha kan, Qulihuwa lahu kan, rakat keji kuli huwa kuli Ya Ayu Ali kafirun kan, rakat keta fatiha kan , Ina Ataina meta,
leyin na o ma se adua yi 📿: O ma ka fatiha debi Moliki Yaomi deen (706),

Leyin na o ma wa se adua Lori gbogbo nkan toba fe

O ma wa Jaoratul Kamol Pari re,

Saara Eso(Fruits)Meta tabi Ounje fun eniyan Meta

Call or Whatsapp for Explanations 08149304714

Note; Call me if u want me to do it for you
Awon Onirawo Mewa toku gbodo Se t**i Won na,

🐅  IRAWO LEO ♌  BURUJI HUSSUD برج الاءسد            ISEDA INA Oorun Man wo Inu Ami Asadu Ni Deede July 21 Ninu Odun kook...
10/03/2021

🐅 IRAWO LEO ♌
BURUJI HUSSUD برج الاءسد
ISEDA INA

Oorun Man wo Inu Ami Asadu Ni Deede July 21 Ninu Odun kookan besini Loma wa Nibe t**idi August 21, Sugbon Awon Omo tiwon ba bi Ni Ose Akoko ninu Ami Leo yen kole ti ma da ise se nitoripe Ami irawo tosese Kuro nile Iyen Irawo Cancer Cancer🦀, Idi Niyi tofijewipe Isesi Ati Ihuwasi Meji Lema ba Lodo Awon tiwon babi Ninu Ose Akoko ninu Ami Osu irawo kookan fin ma n lo irawo Meji tabi Isesi meji,

Leo Je Irawo tolagbara pupo besini Kinihun ni Ami re, O gbona gidi nitoripe Agbara ako wa lara re,

Irawo Ako(Male) Ni Leo Je besini ti Leo ba fe Eyikeyi irawo Ina meteeta, won ma Jo ma figagbaga ni besini koni fe si Iteriba Laarin won funra won,

Olori niwon besini Omo Elegbe po ninu won daada, Nigbamiran Awon tiwon lo irawo yi tiwon ba n bo, Eru man ba eniyan bi wipe eniyan ri Kinihun ni, Ife Ibanikedun Ati Ikonimora Je Ohun pataki ti a ma fin da Irawo yen mo, won man Nifesi gbogbo eniyan besini ni Ologe niwon , won feran Party pupo, Agidi po funwon, won ma feran ololufe won pupo besini won gbori yin fun, won ko ka igbese aye si nkan to le rara, won korira iro besini won kii saaba ja ayafi ti eniyan ba towo bo won Lenu, at I bebelo..

ALAAFIA AT ILERA WON

Leo Loni Akoso Oyan, ilera won koni Opin rara, won Lagbara Latigba Oorun Si ara biwon ba se fe, Oorun Ati Afefe Alaafia loje funwon,

ORE (friends)NINI FUNWO

O dara ki Leo ki Leo Ma Sunmo Irawo Afefe Especially Afefe marinmifin (Libra) ati Alawada(Gemini) Nitoripe o ma ri Oore Lodo won Lopolop besini O ma je Igi Leyin Ogba funwon , Odara Latife Irawo Afefe na Leyi ti won ti Sewadi Ojo Iwaju won tiwon si ti papo daada, Idunnu Ati Ayo Ni Irin Ajo Igbeyawo won ma Jasi...

OUNKA TODARA

Onka Todara Funyin Je Eerin(4) besini Asiri ni Onka na, Odun Kerin kerin ni Iyipada Oore yoo ma sele ninu Igbese aye won,

* Saara won
* Lucky Day won
* Lucky Job won
* Lucky Colour won
Akosejaye won ati bebelo

Fun Gbogbo Iwo tio ba fe ra Iwe Asiri Ira Asiri irawo Nilu Ibadan ati Oyo Lola Thursday Call 08149304714

Latowo Oludasile Dr Adewumi Al-Falaahy Ase-Olohun

WATCHED MY VIDEO AND SUBSCRIBED
27/02/2021

WATCHED MY VIDEO AND SUBSCRIBED

A SPECIALIST ON ASTROLOGY AND NUMEROLOGY

Join This This group TV On YouTube to know more about yourself and your star "ASIRI IRAWO TV On Youtube and Click Subscr...
27/02/2021

Join This This group TV On YouTube to know more about yourself and your star "ASIRI IRAWO TV On Youtube and Click Subscribed under the Video to enjoy it.

For Enquiry: 📲 or Whatsapp 08149304714 or 08029545072

Thanks

Address

Ogijo

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ASIRI IRAWO TV YouTube Channel posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to ASIRI IRAWO TV YouTube Channel:

Share

Category



You may also like