
25/01/2025
Ile ẹjọ kotẹmilọrun niluu Akure sọ pe ''awọn duro lori idajọ ile ẹjọ giga ipinlẹ Osun lori ọrọ naa.
Ile ẹjọ kotẹmilọrun ti o fi di kalẹ niluu Akurẹ ti buwọ́lù idajọ iku fun oludasilẹ Hotẹẹli Hilton ti o wa nilu Ile Ife nipinlẹ Osun, Dokita Ramọn Adedoyin, lori ọrọ iṣekupa akẹkọọ ileewe gíga fasiti OAU, Timothy Adegoke to ku si hotẹẹli rẹ nijọ kinni ...