Alaroye News

Alaroye News Ìwé iroyin àwọn ọmọ Odùduwà IWE IROYIN TI O N SALAYE LEKUKU RERE

03/01/2024

Ẹ̀jẹ̀ kí a dá ara wa lara yà pelu vidio ó yìí Everyone

27/12/2023

Nje kini ẹyin riso sì video yìí? Everyonee

Òṣeré ilé wa àgbèrè fáyé
14/05/2023

Òṣeré ilé wa àgbèrè fáyé

ÌRÒYÌNIbo Ọṣun: Oyetọla jawe olubori ni kootu
27/01/2023

ÌRÒYÌN
Ibo Ọṣun: Oyetọla jawe olubori ni kootu

12/08/2022
12/08/2022

Àṣírí tú Yoruba ronú ooo

27/05/2022

O n rugbo bo oooo
Nkan ti ń dàrú fún egbe APC ni Obokun constuency

Ìjà besile níbi wọn ṣe ṣe mago mago
Ẹtọ ìdìbò abele

Ema retí eku rẹ rẹ ìròyìn na laipe

Erin wo! Alaafin Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi, ti wajaAlaafin Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi, ti darapọ mọ awọn ...
23/04/2022

Erin wo! Alaafin Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi, ti waja

Alaafin Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi, ti darapọ mọ awọn baba nla rẹ lẹni ọdun mẹtalelọgọrin.
Alẹ ọjọ Ẹti ni Kabiyesi papoda ni ọsibitu Afẹ Babalọla University Teaching Hospital, to wa niluu Ado-Ekiti, nipinlẹ Ekiti, lẹyin aisan ranpẹ.
Wọn ti gbe oku ọba nla naa pada siluu Ọyọ, ti etutu gbogbo to yẹ nipa ipapoda ọba naa si ti bẹrẹ.
Ọba Adeyẹmi lo ti i pẹ lori oye ju ninu awọn ọba to jẹ ni ilu naa. Ọdun mejilelaaadọta lo lo lori itẹ.

05/04/2022

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó ti kọjá

O mase o Òṣeré tíátà ilé wa DEJO TUNFULU KU LÓJIJÌ
01/04/2022

O mase o Òṣeré tíátà ilé wa DEJO TUNFULU KU LÓJIJÌ

29/03/2022

Ọtí sẹlẹ oooo àwọn olólùfẹ́ àgbà bolu orile èdè wa dáa pápá isere ru ooo wọn ní inú won kò dùn sí ní orílè èdè wa se fìdí remi

22/10/2021

Èmo rẹ ooo abere àrùn korona ni ará kùnrin yìí gbà lọ bá di wàhálà oooo

07/09/2021

Abi irú kí niyii afi kii Ọlọ́run sowa lórí lè èdè yìí

Àbi irú kile yìíOlusho àgùntàn T.B JÓṢÚÀ ti dá gbere fàyè
06/06/2021

Àbi irú kile yìí
Olusho àgùntàn T.B JÓṢÚÀ ti dá gbere fàyè

01/04/2021

Lawal luyawo ẹ pa, o lẹkọ mimu to po foun di koko

April 1, 2021



Alaroye

Ẹka ti wọn ti n gbọ ẹjọ awọn apaayan ni ọkunrin yii, Danladi Lawal, ẹni ogun ọdun, wa bayii nipinlẹ Niger. Iyawo ẹ, Zulai Lawal, lo lu pa lọsẹ to kọja yii, nitori ẹkọ tiyẹn po fun un ti ọkunrin yii sọ pe o dikoko.

Abule Kadaura, nijọba ibilẹ Rafi, nipinlẹ Niger, ni ọkunrin yii ati iyawo rẹ kekere naa n gbe.

Ẹkọ tọkọ ni ko po foun, ti Zulai po, ni ọkọ rẹ sọ pe ko po daadaa, ati pe koko pọ ju ninu ẹkọ ọhun.

Danladi binu pupọ nitori ẹkọ naa, o si jọ pe iyawo rẹ ko bẹ ẹ bo ṣe fẹ, nitori niṣe lọrọ di ija nla, to dohun ti Danladi bẹrẹ si i luyawo ẹ, o si lu u t**i tọmọbinrin naa fi daku mọ ọn lọwọ.

Ọkọ yii funra ẹ ṣalaye fawọn akọroyin, nigba tawọn ọlọpaa foju ẹ han ni olu ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Minna. O ni loootọ ni inu bi oun, toun si lu iyawo oun laluju, to bẹẹ to jẹ o daku. Danladi sọ pe oun ko mọ pe ko ni i ji pada saye lẹyin to daku naa. O loun gbe e lọ sọsibitu Jẹnẹra Wushishi, ṣugbọn wọn sọ foun pe o ti ku.

Ko pẹ ti gbogbo abule fi gbọ pe Zulai ti ku latari lilu tọkọ rẹ lu u, kia lawọn ọlọpaa si ti waa gbe Danladi lọ si teṣan.

Alukoro ọlọpaa nipinlẹ Niger, DSP Wasiu Abiọdun, sọ pe iwadii ṣi n tẹsiwaju lori iṣẹlẹ yii, ṣugbọn Danladi yoo de kootu laipẹ rara.

12/03/2021

AARE ORÍLẸ̀ ÈDÈ WA
MUHAMMADU BUHARI tí fi kún owó epo Jala epo kan tí di
#212 náírà

ÌRÒYÌNṢọja, ọlọpaa ati ọtẹlẹmuyẹ kọju ija si Sunday Igboho lọna Ibadan, wọn fẹẹ mu un tipatipaFebruary 26, 2021  Alar...
26/02/2021

ÌRÒYÌN
Ṣọja, ọlọpaa ati ọtẹlẹmuyẹ kọju ija si Sunday Igboho lọna Ibadan, wọn fẹẹ mu un tipatipa
February 26, 2021 Alaroye
Awọn ọlọpaa atawọn ẹṣọ agbofinro bii ogoji la gbọ pe wọn dena de ọkan ninu awọn ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Oloye Sunday Adeyẹmọ ti gbogbo eeyan mọ si Sunday Igboho ni ọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọsẹ yii.

Loju ọna marosẹ Ibadan si Eko la gbọ pe awọn ọlọpaa, awọn ṣọja atawọn ọtẹlẹmuyẹ bii ogun ti dena de e, ti wọn si fẹẹ mu un.

Gẹgẹ bi minisita fun ileeṣẹ ofurufu nilẹ wa tẹlẹ, Oloye Femi Fani-Kayọde ti fi lede, o ṣalaye pe ‘‘Mo ṣẹṣẹ ba arakunrin mi, Sunday Igboho, sọrọ tan laipẹ yii ni, o si sọ fun mi pe pẹlu ijakadi ni awọn ṣọja, ọlọpaa, awọn ọtẹlẹmuyẹ fi fẹẹ mu oun loju ọna marosẹ Ibadan si Eko lasiko ti oun n lọ siluu Eko lati lọọ ri Baba Ayọ Adebanjọ.’’

Fani-Kayọde bu ẹnu atẹ lu igbesẹ naa, o ni iwa buruku ti o si lewu ni awọn eeyan naa hu.

O fi kun un pe ti awọn ẹṣọ alaabo ba fẹẹ ri ọkunrin yii, ohun kan ti wọn ni lati ṣe ni ki wọn ranṣẹ si i pe ko wa si ọọfiisi wọn.

Fani Kayọde ni, ‘‘Mi o mọ ẹṣẹ kan kan ti wọn ni ọkunrin yii ṣẹ. Bakan naa ni mo n ranṣẹ ikilọ si ijọba apapọ pe akin ọkunrin niIgboho si ogunlọgọ ọmọ Yoruba, bi wọn ba si fi mu un ti wọn ti i mọle, yoo jẹ aṣiṣẹ nla fun wọn.’’
https://alaroye.org

Ẹ tètè bere tiyín lowo fenfo
08/02/2021

Ẹ tètè bere tiyín lowo fenfo

Kini ẹyin ẹ̀yán wá riso sì Ọ̀RỌ̀ SUNDAY IGBOHO àti GÓMÌNÀ SEYI MAKINDE lórí oro Fulani DARAN DÁRAN
25/01/2021

Kini ẹyin ẹ̀yán wá riso sì Ọ̀RỌ̀ SUNDAY IGBOHO àti GÓMÌNÀ SEYI MAKINDE lórí oro Fulani DARAN DÁRAN

Address

Ikeja
Lagos

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Alaroye News posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Videos

Share

Category