ÌBÁKÀ RTV

ÌBÁKÀ RTV Yoruba story telling, news , drama, music. etc

01/01/2025

Omo wa oni seru egbe, Iya ti obi je Omo wa oni je.

16/12/2024

Ki Olorun Sanu awon okunrin lowo Obinrin ti ko fe ki won jere Omo.

13/09/2024
10/09/2024

Bi o se wa ni atetekose be lo wa ni si yi, Ise Olopa pe iwa ibaje omo iya ni won. Even ti today Nigeria police never stop bribery and corruption.

06/09/2024

Ijoba Awa arawa, Emilokan, Omoenionisedibebere

21/04/2024

,

16/01/2024

Oríkì ikoyi esho pelu Ibrahim Chatta àti Adebukola Edu

16/01/2024

Ninu awon ede to yato ni ede Ondo je, e je gbo ohun ni ede Ondo ni e yi to yato si ti gbogbo ni ile Yoruba.
Egbe ede Asa yin laruge.

11/01/2024

OWO AWON AMOTEKUN BA AWON ALFA ALAWO TO NGE ORI OKU NI ILU SAKI.

23/08/2023

TANI OLORUN ALMOST BEATEN TO DEATH - LAWYER SPEAKS ON TODAY COURT HEARING!!!SUBSCRIBE HERE👉 https://goo.gl/ypvoyFJoin this channel to get access to perks:ht...

02/01/2022

OLUBADAN Ọ́BA ADETUNJI AJẸ̀ OGUNGUNNISỌ TI ILU IBADAN WÒ JÀ.

E KU ALAJA ODUN OGBOLOGBO ODIN 2021, ASI KU ODUN TITUN 2022
01/01/2022

E KU ALAJA ODUN OGBOLOGBO ODIN 2021, ASI KU ODUN TITUN 2022

Iporogan ni JALINGO: Awọn ọdọ ti inu nbi fi ehonu han ni Jalingo, olu ilu Ipinle Taraba, nipa sise iku okan ninu ọmọ ẹgb...
29/11/2021

Iporogan ni JALINGO: Awọn ọdọ ti inu nbi fi ehonu han ni Jalingo, olu ilu Ipinle Taraba, nipa sise iku okan ninu ọmọ ẹgbẹ wọn lati ọwọ́ ọlọpa.

Awon odo ti won n fi ehonu won han gbe oku eni ti won pa sinu posi ti won n pariwo “A ko ba enikeni ja bi ko se olopaa” nigba ti won n rin kaakiri agbegbe Mai Patanya lo si oja jalingo nla, ona kan loju popo gan-an ni won ti dina.

Awọn ọdọ ti inubi naa n kepe fun idajọ ododo fun enj ti wọn pa, ati lati fòpin si iwa ika awọn ọlọpa si awọn araalu ati p**a awọn eniyan lairotẹlẹ lati ọwọ́ ọlọpa ati awọn oṣiṣẹ alabo miiran.

E je ki iwọ́de naa pari ni alaafia gege bi awon odo ti gbero, ki eyi si mu opin de ba p**a eniyan alaisese lati l
owo olopaa ni Jalingo, Taraba, ati Nigeria lapapo.

ỌKỌ̀ EPO GBANA NI IBADAN.Ọkọ̀ epo pentirolu gbana ni oju ọ́nàti olọsi Agodi-Gati nitosi NTA Ibadan, ọkọ̀ meji lo tun jon...
18/11/2021

ỌKỌ̀ EPO GBANA NI IBADAN.
Ọkọ̀ epo pentirolu gbana ni oju ọ́nàti olọsi Agodi-Gati nitosi NTA Ibadan, ọkọ̀ meji lo tun jona leyin re.
Oríko awon ènìyàn ti owa ninu awon oko na yọ

Okunrin yi gan mo opo ina nigba ti ohun gbiyanju lati yor eiye to ha mo opo ina, ina fa mora nibe losi ku si, se aigbon ...
17/11/2021

Okunrin yi gan mo opo ina nigba ti ohun gbiyanju lati yor eiye to ha mo opo ina, ina fa mora nibe losi ku si, se aigbon ni a ba pe eleyi ni, abi aimokan.
Ao ni ku iku oro oo.

Address

Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ÌBÁKÀ RTV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Videos

Share