Owuye

Owuye owuye is an indigenous yoruba newspaper publication aim at bringing the happening of society

10/01/2023

Èèmọ, èyí ni bí àwọn ọmọ ilé ẹkọ gíga UNILORIN ṣe nsánnani lori ati rí Ọkọ lọ ile ìwé.

Asojukọ ìròyìn wa jẹ abọ pe, ni Tanke Òkè Odò laarọ yìí, awọn ọmọ ilẹ iwe to nlọ ile ìwé tu jáde, ṣugbọn ti wọn kò rí ọkọ wọ lọ ile ìwé.

Kini o fa, ṣe ti ọwọn gogo epo petiro ni, àbí Fara Babatunde idiagbon ti o nlọ lọwọ ni Tipper garage ni?

Foto: ASKOMP ṣe ìpàdé pẹlu Alhaji Shuaib Abdullah Yaman Oludije sí ipò Gómìnà labẹ àsìá ẹgbẹ òṣèlú PDP ni Ìpínlè Kwara.Ẹ...
13/11/2022

Foto: ASKOMP ṣe ìpàdé pẹlu Alhaji Shuaib Abdullah Yaman
Oludije sí ipò Gómìnà labẹ àsìá ẹgbẹ òṣèlú PDP ni Ìpínlè Kwara.

Ẹkùn réré ìròyìn nbọ laipẹ

Ẹkaàbọ̀ s'ori ìkànnì ibani dá ọrẹ ìwé Ìròyìn Òwúyẹ
01/11/2022

Ẹkaàbọ̀ s'ori ìkànnì ibani dá ọrẹ ìwé Ìròyìn Òwúyẹ

Address

Ilorin
24140

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Owuye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Owuye:

Videos

Share


Other Ilorin media companies

Show All