Ayoka Lori ikanni Diamond FM

Ayoka Lori ikanni Diamond FM This page is all about reaching your needs on entertainment,broadcasting on radio. kika iwe aladun na

13/01/2024

IBEERE OSE YI

Leyin Odun kelo ni asoju olodumare to pada wa si ode aye lati wa da awon eda eniyan pada sipo tiwon wa teleri?

13/01/2024
13/01/2024

Ekaro ninu Ile yi, ojumo ayo lo mowa.

Eto Àyokà tun ti gberaso o.

E jeka darapo ,ka Jo jegbadun eto naa.

06/01/2024

IBEERE OSE YI?

Kini Ibeere to arakunrin kan beere niwaju asoju olodumare to ya awon eyan lenu?

30/12/2023

Àyokà ti gberaso Lori ikanni Diamond FM

23/12/2023

Eto Àyokà Lori ikanni Diamond FM nlo lowo

16/12/2023
09/12/2023

IBEERE OSE YI???

Ojo wo,osu wo ,odun wo leyin iku Oluwa wa ,ni iku ran Olowoaye sawon Omo araye?

09/12/2023

Eto Àyokà ti gberaso Lori ikanni Diamond FM.

02/12/2023



Fun awon to nbere nipa ebun tiwon je, a fe fi asiko so fun yin pe, o di eyin igba ti a ba pari iwe ti a nka lowo,ka to fun onikaluku ni ebun tiwon je. Eseun fun agboye yin.



02/12/2023

IBEERE OSE YI

E sapejuwe bi eni iketa to wa Nile iku se mura ,ki e si so nkan tiwon ko sokan aya re

25/11/2023

IBEERE OSE YI
Ojo wo,osu wo ati odun wo ni aarun sa kuro lorun apadi

18/11/2023

IBEERE OSE YI

Kiloruko Baba Akowediran???

11/11/2023

IBEERE OSE YI

Oro wo ni Ekute so nigba to ndagbere fun Olowoaye???

11/11/2023

A tun ku ajisode loni. Ojumo ire,ola, ibukun ati ayo lo mowa loni ojo kokanla osu kokanla... Ona wa ma la sire.

Eto Àyokà ti gberaso,e jeka maa tele bose nlo.

04/11/2023

Eyi lawon to gba ibeere ose to koja
1. Ade Arinola
2. Oseni Mutoiru Horlar

04/11/2023

IBEERE OSE YI

Oyun osu melo ni iyawo Olowoaye wa nigba to lo se ode ninu Igbo?

28/10/2023

Eyi lawon meta akoko to gba ibeere ose to koja
1. Toluwani Stephen
2. Ade Arinola
3. Oseni Mutoiru Horlar

28/10/2023

IFITONILETI!!!

Ao ma kan si awon to ba gba ibeere wa. Amo, ema gbagbe pe awon meta akoko to ba gba ibeere wa ni won leto si ebun Ori eto Àyokà.

Eseun fun ife ti e ni si ikanni Diamond FM ati Eto Àyokà.

Ibuwolu: Atokun eto Àyokà, Ifeoluwa Adebayo Aya Animasaun.

28/10/2023

IBEERE OSE YI

Kiloruko Baba Olowoaye
???

28/10/2023

Àyokà ti nlo lowo o.
Tune in now
Diamond 88.5fm,Ilesa
And
Diamond 88.7fm, Ilorin

Address

Ìrètí Ayọ̀ , Ilesa, Osun State
Ife

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ayoka Lori ikanni Diamond FM posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ayoka Lori ikanni Diamond FM:

Share


Other Broadcasting & media production in Ife

Show All

You may also like