27/04/2024
Sàsà ènìyàn níí fẹ́ni lẹ́yìn tá à bá sí nílé, tẹrú tọmọ níí fẹ́ni lójú ẹni;
Onílé apá ọ̀tún kò fojúure wo ni, ìmọ̀ràn ìkà ni tòsì ń gbà, ká jáde ká má wọlé ni tọ̀ọ́kán ilé ń wí; Sàsà ènìyàn níí ènìyàn níí fẹ́ni lẹ́yìn tá à bá sí nílé, terú tọmọ níí fẹ́ni lójú ẹni;
Inú jìn ó ju ọ̀run lọ, ẹ jẹ́ ká ṣe jẹ́jẹ́;
A kú ojúmọ́.