08/05/2024
Mo ki Gbogbo ile ooo, A ku ojo meta, Asiri ise ti mo fe fi sile loni ni, - _ISE_ANU_TI_A_FIN_RA_ORI_IDODO_TODAJU💯 E Je ki a lo se, Ti iyawo ko ba fe ki oko re nife Elominran mo, Tabi oko ti ko fe ki iyawo ohun nife okunrin miran mo, ki o fi ise yi ra Idodo, ki won to ni ibalopo,.. ti eniyan ba fe lo gba ise, Tabi fun interview, E je ki o lo ise Yi, Eni na si ma yin olorun logo,.. Ti Eni ti o ba hun wa oko tabi iyawo ba lo, dandan ni, ki enina pade t**i e, Ise dara fun eni ti ona anu ti di mo patapata...E je ki a lo se ki a wa fun ile labo.. ise ti o daju gidi gan ni,. Awon ti won ti se iru ise yi ri le jeri si... Ise na niyi - Ao get Ako Alangba Eyokan, Koro inu Agbalumo die, Ewedu tutu, ati Ori, , Sise re- Ao bo epo eyin, koro inu Agbalumo yi kuro, Ao sa funfun inu re ti yio gbe dada , Ao wa lo ti yio kuna dada, Ao lo papo mo ewedu, ti yio kuna dada, Ao wa fi po Ori (Shea butter), Ao wa pa alangba yi , Ao po eje re papo mo ise yi, Ao wa ko sinu ike kekere kan, lati ojo keji, o ti di Lilo,. ko ju bayi lo.. Lilo re - Ao ma fi ika arin wa to, Ao ma fi ra Idodo (Navel) wa , ao gbadura si wipe ti ori ba fi oju kan orun tinu re aayo ,Gbogbo oju ti o ba rimi loni ki inu won ma yo simi,.. Ao tun gbadura Gbogbo Inkan ti a ba fe si,, ko ju bayi lo,... Fun gbogbo eyin ti E fe ko ise yi sile tabi e fe se, E ri daju wipe E comment lati dupe ki E si share post yi kakiri fun anfani elomiran, Adura yin yio si gba... Fun eyin ti E ba fe ki a ba yin se, tabi eyikeyi Eto adura Abi E fe se iwadi nipa oro aye yin, e peut me tabi ki e message me