Kilo nsele lagbo ife

Kilo nsele lagbo ife Journaliste

02/08/2022
Today is my Birthday.Alhamdulillaah, Alhamdulillaah, Alhamdulillaah, Roblialemin.Am +1 Today, Happy Birthday to me Long ...
20/06/2022

Today is my Birthday.
Alhamdulillaah, Alhamdulillaah, Alhamdulillaah, Roblialemin.
Am +1 Today, Happy Birthday to me Long life and prosperity.

AKOLE ITAN  OGUN OWO    APA KEJIE kaabo si afin ijinle ogbon eka oro ogbon group ni nibi ti a ti nfi igba ogbon bu omi o...
27/05/2022

AKOLE ITAN
OGUN OWO
APA KEJI

E kaabo si afin ijinle ogbon eka oro ogbon group ni nibi ti a ti nfi igba ogbon bu omi ogbon fun ologbon mu ninu amu ogbon, emi Adewale Aderoju Omonla yin na re a fi ogbon inu pe ogbon ori jade nitori inu ni eda koko ro ki o to ro ori, o ya e wa ikan fidi le tabi ki è fi idi le kan ki è je kajo te siwa ju lori itan ti akole re nje OGUN OWO

Inu ara kunrin yi dun pupo lati gbo ikan ti baba mi ba*o, o si so fun baba mi wipe oun mawa owo na wa boje ki oun lo ta omohunmaworan oun ni oun ma ko owo re wa, bayi ni okunrin gba ile re lo ni ojo na

Ni tooto okunrin yi ko owo na wa fun baba mi, baba mi si se etutu na fun, ni ojo keta ojo nani okunrin na gba ona oko eru lo

Hmmm gege bi mo se ba oro mi bo okunrin yi gba ona oko eru lo gege bi baba mi se so fun, won si so fun wipe ko ma gbagbe ikilo ti awon se fun wipe leyin owo ti yio fi jeun loju mo ko gbodo yo owo kankan ninu gbogbo owo ti o ba gba ni oko eru na, ki o si ma gbagbe wipe iye osu toba fi se eru na ni iye odun ti wa fi ni owo na to ba de

Okunrin yi lo si oko eru ni tooto, ni ireti wipe yio tete pada de nitori bi ogun owo na se gbona ninu okan re lati se, sugbon okunrin yi lo to osu merinlelogun ki o to de eyi ti nse odun meji gbako, nigba ti o de lati oko eru o do baba mi ni okunrin yi gba wa tara, inu baba mi dun pupo lati ri okunrin yi wipe o pade lati oko eru layo, baba mi si bere lowo wipe kilode ti o fi pe to be, esin ti o fun baba mi ni wipe nigba ti e ti so wipe iye osu ti mo ba fise oko eru ni iye odun ti mafi ni owo idi re ni yen ti mo fi pinu lati lo osu merinlelogun leyi ti o tunmo si wipe odun merinlelogun ni ma fi lowo laye, a bi owo ati ola ti eniyan ba fi odun merinlelogun lo laye o ti kuro ni kekere, baba mi ni beeni o kare omo akin

Baba mi bere wipe nje o tele awon ofin ati ilana ti mo fun e wipe o gbodo yo kobo ninu owo na yato si eyi ti o fe ma fi jeun, o si daun wipe koda gan ki nse ojojumo papa ni mo nyo owo ounje nibe pelu, baba mi wa bere wipe owo ti o wa gba bo loko eru na nko, nigba ti ara okunrin yi mako owo sile baba mi gan la enu kole pade nibi ti owo na po de, baba mi wa so fun ara kunrin yi wipe ki o ka gbogbo owo ki awon mo iye ti o je, ara kunrin yi ka owo yi koda o koja siso, baba mi gba gbogbo owo na lowo re, won ni ise ti bere ni sise na ni yen, igba ti o ba ma fi di osu to nbo iwo na ma je kan pataki ninu olowo ile yi

Baba mi wole lo won si fun ni a*o ati sokoto ti o je alawo funfun wipe ki o ko dani, won fun ni ose ati kanyikanyi ti o ma fiwe, nigbati ile su, ti owo ti pa ti ese ti pa, baba mi mu ara kunrin yi si ita gbangba wipe ki o fi ose na we, leyin eyi ki o wo a*o funfun ti awon fun yi ki o wo inu yara ti awon ti pese sile fun lati lo sun, ikan ti o ba ri loju orun re ki o wa so fun awon ti ile bati mo, bayi ni ara kunrin yi we tan, ti o si wo a*o funfun na ti o si wole lo sun

Ile o ti mo tan rara ti ara kunrin yi ji, baba mi ni o bere wipe oun fe so oun ti oun ri fun won nitori eru ba oun, ko pe pupo ni baba mi na jade ninu yara won ti won si wo inu yara igbalejo won lo, ara kunrin yi sare wole lo ba won, baba mi ni ko se suru ko ma beru ikan ti o ba ri ni kose alaye re fun mi, bayi ni ara kunrin se se alaye oun tori loju orun

Leyin ti mo sun, eyin gangan na ni mori loju ala mi wipe e ji mi loju orun wipe e fe mumi de ibi kan, e si fami lowo da ni, ojiji ni emi ati yin ba ara wa ni waju ara birin arewa kan pelu a*o fun lara, a si kunle ki obinrin yi, sugbon bi a se kunle ki obinrin yi ni e ki oriki obinrin yi ni mesan mewa, e so wipe aje oguguluso, oniso booji, ana omo ki o to na yeye, ana agbalagba ko jini jini, aje ti so eru di omo, aje ti nso aburo di egbon, aje mana mi omo ni ki o fi mi se

Bayi ni e se ki oriki ara binrin yi loje ki mo loju ala yi wipe aje ni a kunle si iwaju re yi, inu re si dun bi e se ki ni mesan mewa, o wa bere wipe kini oun ti a fe, gbogbo ero okan temi loju ala yi ni wipe e ma so fun aje wipe mo fe se ogun owo ni, sugbon ikan ti e so fun ara binrin yi ni wipe e fe wa fi ijiya aje han mi ni, nigba ti e so eyi tan ara binrin na bere lowo yin wipe a bi ara kunrin ti o mu wa yi na fe se eru aje ni, e si so fun wipe beeni sugbon ko wun mi ki enikeni se eru aje nipase mi sugbon kole mo wipe eni ti o ba fi tipa tipa fi aje se eru nile aye oun na apada pe loko eru aje jube lo leyin ti o ba ku tan, aje mi kanle o ni hmmm o kare awo rere ti o to omo eniyan si ona rere, bayi ni ara binrin aje yi kesi olori eru aje ti iyen si daun lowo kan o ni ki o mu wa losi ibi ti awon aru aje ti sise eru, hmmm baba enu mi ko siso nigba ti a de be, eru bami, aya mi ja haaa baba o ni agbara o

Baba mi rerin muse, o ya so ikan ti o ri, ara kunrin yi ni opolopo awon olowo nlanla okunrin ati obinrin ti mo mo ati ti moti gbo oruko won ri ni mori loko eru aje, pelu omije loju ni awon kan fi nla ako okuta ti o ga to eniyan lori iduro, atelewo ni awon kan fi lo pon omi lati inu odo nla sinu apere, ekanna owo ni awon kan fi ya epo igi nla, owo lasan ni won so wipe ki awon kan ma fi wa ile asale ti won si gbodo kan omi, pelu nina bi eni maku si ni awon eni yi fi sise ako yi, anu awon eni yi semi pelu inira yi, iru ese wo wani awon eni yi lese na ni mo bi ara mi, kope ni won dawa pada si odo ara binrin aje yi, nigba ti a pada e si so fun aje wipe moti ri ikan ti mo fe ri, ikan ti o tun wa ya mi lenu re baba, owo ti moko fun yin e tun ko owo yen dani e wa so wipe owo ise eru ti emi jiya se re ki ma ba se eru aje, sugbon e fe alubarika ti nse akobi aje, lati wa wo inu owo na, aje rerin muse aje siso wipe o da ko buru, aje si pe odo mode obinrin kan jade ti oun na wa ninu a*o funfun, a se oun ni alubarika, o kan da owo le owo yi ni ni mo ba taji lati oju orun

Baba mi min kanle, baba mi ni kare yio dara fun e, jeki se alaye awon ikan ti o ri fun e dada, kini alaye oro ti baba mi se fun okunrin yi mo nbo na

Afin ijinle ogbon lewa eka oro ogbon group ni, nibi ti a ti fi igba ogbon bu omi ogbon fun ologbon mu ninu amu ogbon, Itan ti akole re nje ogun owo le gbo lati enu emi Adewale Aderoju Omonla oba ilu oro ogbon, itan na yio mate siwaju

AKOLE ITAN  OGUN OWO    APA KINIE kaabo si afin ijinle ogbon eka oro ogbon group ni nibi ti a ti nfi igba ogbon bu omi o...
26/05/2022

AKOLE ITAN
OGUN OWO
APA KINI

E kaabo si afin ijinle ogbon eka oro ogbon group ni nibi ti a ti nfi igba ogbon bu omi ogbon fun ologbon mu ninu amu ogbon, emi Adewale Aderoju Omonla yin na re a fi ogbon inu pe ogbon ori jade nitori inu ni eda koko ro ki o to ro ori, o ya e wa ikan fidi le tabi ki è fi idi le kan ki è jo kajo fi itan ti akole re nje OGUN OWO kogbon

Ifawale ni oruko mi, Ifagbemi ni oruko baba tobi mi lomo, babalawo ti o gbo Ifa gidi ni mi, emi mo oun ti Ifa nso, mo si mo bi won se ba Ifa soro pelu, emi omo aigbofa ni a wo oke Ifa kan kosi ni para, emi mo oruko ti ewe nje beni emi mo oruko egbo idi re pelu, emi mo ki a ba ogun soro ki ogun si da eni loun, mo mo bi won se ran ogun nise ti ogun si jise ti mo ran, ise ti omo ba lowo baba re ko gbodo wun omo nitori wipe owo ada ki wun ada, owo baba tobi mi ni mo ti ba ise ifa, baba mi ni won nki ni a gbe inu ile mo oun ti Ifa wi, a gbe eyinkunle mo iye odu tofu, omo a ki ife gbede gbede bi eni to nla oyin, orun rere baba mi ifagbemi

Nigbati mo wa ni majesi, ti mo siwa lewe, awon ero a ma wo ni odo baba mi fun ajo lorisi risi, awon olowo nlanla, awon gbajumo ilu, ati awon ti o ku die kato fun, awon ti o wo oju olohun oba fun omo bibi, obinrin ti koni ade ori, okunrin ti koni aya ni odede, awon alaisan, ati awon isoro miran ni won ma gbe wa si odo baba mi nigba na ti eledumare si ma gba akoso, baba mi ni awon omo awo ti opo ti won ko ise awo ni odo won ti baba mi si ma fi ise han won, ti opolopo ninu won siti mo ise awo yi dada

Ni ojo kan, okunrin kan wa baba mi wa, sugbon igba akoko ti okunrin yi yio wa baba mi wa re, ni ojo ti okunrin yi wa yi o ba awon ero nile o si pe die ki o to raye ri baba mi, nigba ti o wole oun ati baba mi soro, sugbon kini ara kunrin na bawa ni ojo na OGUN OWO ni o bawa

Okunrin yi se alaye bi Iya se je to, ati awon opolopo isoro ti o koju nitori aini owo lowo, o je ki o ye baba mi ifagbemi wipe a*o oun o pe meji lori iko tipa tipa ni oun fi je ounje ekan ni ojumo, nitori ise oun Iya yi ni iyawo oun fi ko jade nile, a bi nigba ti oun o ri owo lati fi toju omo ati iyawo oun, oun ti oun kole da enu ara oun bo ni oun fe bo iyawo ati omo, baba onile ti fun mi ni iwe ki nko jade nile, e wo baba Iya yi ti poju, awon alaimokan ni won ma so wipe aini owo lowo ko pani loruko da, ti owo Iya ati ise ba to omo eniyan boya ni won ma ranti oruko oluwa re mo, akuse tabi tanika ni oruko ti omo araye mama peni, baba mofe se ogun owo ki emi na kuro ninu egbe akuse

Baba mi rerin muse, baba mi so wipe o dara kosi isoro ti o wa nile aye yi ti kosi atunse re lowo eledumare, sugbon ti o ba runi loju a ma bi ile lere ni jeki akoko da Ifa si wo na ki a gbo oun ti Ifa ma so, bayi ni baba mi da Ifa fun ara kunrin yi kini Ifa wi

Baba mi so ikan ti Ifa so fun ara kunrin yi lojo na, Ifa so wipe………..idin gbemi lowo gbemi lowo, idin gbemi lese gbemi lese, orisa gbemi lati ori abo asin bo si ori ako esin, difa fun makanju ola ti nse omo won lotu ife, makanju ola omo won lotu ife ti o ba tete ku wa ba won segi ola

Bayi ni baba mi se ki Ifa yi fun okunrin yi ni ojo na ti baba mi si ba soro gege baba si omo wipe ko ma se kanju sugbon ki o du emin re nitori ojo ola re ti sun mo etile tan, sugbon ki o se etutu emin re ki ojo ola re lese oju emin re

Sugbon gbogbo oro yi ko wo omo okunrin yi leti rara ogun owo yi ni o sa tenu mo wipe oun fe se, koda o ni koje odun kan soso ni oun fi ni owo na o te oun lorun ki o sa wa ninu akosile oun wipe oun wa sile aye oun sini owo nigba aye oun

Baba mi ri wipe okan ara kunrin yi ti ga ju lori ogun owo yi, baba mi wa so fun okunrin yi wipe toba je wipe ogun owo yi ni o se tan lati se ko buru ma se fun e, sugbon ikoko ti yio je ata idire ni lati gbona, igbese akoko re ti o ba se tan lati se ogun owo, wa kuro ninu ilu yi wa lo si ilu keji lati lo se eru, boya alabaru ni o le se ni tabi alagbaro fun odindi osu meta tabi mefa o sile fi osu mejila se, sugbon ti o ba je osu meta ni o fi se eru yi odun meta ni wa fi ni owo na, toba si je osu mefa lofi se eru odun mefa ni wa fi ni owo na toba si je osu mejila nani o fi se eru yi odun mejila ni wa fi ni owo na ti a ba pari re

Sugbon ni oko eru ti o fe lo se yi gbogbo owo ti o ba pa o gbodo yo kobo nibe, gbogbo owo yi ni wa ma toju leyin owo ounje ti wa ma je ni ojumo, o gbodo yo owo miran nibe mo, owo yi ni o ma kowa leyin ti o ba ti oko eru na de ti a ma fi se ogun owo na fun e, leyin gbogbo eyi iwo na madi okan gbogi ninu olowo agbaye, sugbon ki o to lo si oko eru na gbiyanju lati wa owo kekere kan wa lati fise etutu kekere kan fun e

Inu ara kunrin yi dun pupo lati gbo ikan ti baba mi ba*o, o si so fun baba mi wipe oun mawa owo na wa boje ki oun lo ta omohunmaworan oun ni oun ma ko owo re wa, bayi ni okunrin gba ile re lo ni ojo na

Ni tooto okunrin yi ko owo na wa fun baba mi, baba mi si se etutu na fun, ni ojo keta ojo nani okunrin na gba ona oko eru lo

Afin ijinle ogbon le wa eka oro ogbon group ni nibi ti e ti gbo itan adindun, itan na yio ma te si waju

OMO OLOJO IBI ONI HALIMOT SHADIAOrire nla ni ki eniyan bimo layeOre idunnu ni ki eniyan ri omo na woOkunrin ni omo obinr...
26/05/2022

OMO OLOJO IBI ONI
HALIMOT SHADIA

Orire nla ni ki eniyan bimo laye
Ore idunnu ni ki eniyan ri omo na wo
Okunrin ni omo obinrin ni omo
Ki eledumare sati ma pa omo fun olomo
Nitori omo niyi ki eledumare maje ki iyi eni womi
Omo ni a*o eni ki eledumare ma fa a*o wa ya
Omo eni ni wo ile de ni bi a o si nile ki eledumare maje ki a fi omo wa se awati

Ni mo fi ki omo mi olojo ibi oni
Wipe ki o dagba
Ki o dogbo
Ki o pe laye
Ki o ma se ku ni rewe rewe
Alafia ni ogun oro, ki o mase se aisan
Owo ni a fi gbe le aye o ni dagba mosi
Ki o si je aridunnu fun awon obi to bi e lomo
Happy birthday to you my daughter long life and prosperity igba odun odun kan ni lase eledumare ase

26/05/2022

Une fille a giflé son gar😓💔.
Le gar, au lieu de faire comme dans les novelas, il a donné 2 paire de Gifle a sa mœuf. Conclusion :les hommes
Africains son pas romantique

Ololufe meji
26/05/2022

Ololufe meji

24/05/2022

ORO TO NLO

Lanlọọdu ati getimaanu pa ọmọọdun mẹrin, wọn yọ ẹya ara ẹ lati fi ṣoogun owo

Diẹ lo ku kawọn araalu tinu n bi dana sun baba getimaanu kan nigba ti aṣiri oun ati ọga rẹ, Ọgbẹni Emmanuel, tu pe awọn ni wọn ṣeku pa ọmọkunrin ọmọọdun mẹrin kan, ti wọn si yọ ẹya ara ẹ lati fi ṣoogun owo.

Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Niger, DSP Abiọdun Wasiu, ṣalaye pe ijọba ibilẹ Lapai, nipinlẹ ọhun, niṣẹlẹ yii ti waye.

Ba a ṣe gbọ, lati ọjọ mẹrin sẹyin ni wọn ti n wa ọmọdekunrin naa, wọn lawọn obi ẹ ran an niṣẹ lati ra eelo ọbẹ wa lọmọ ọhun fi dẹni awati, ti ko sẹni to foju kan an mọ.

Ṣugbọn lọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kọkanlelogun, oṣu Karun-un yii, ni wọn ri baba sikiọriti to da ọlọkada kan duro, o ni ko gbe oun lọ sọna odo nla kan to wa lagbegbe naa, o si gbe apo kan dani.

Ọlọkada naa loun ro pe aṣọ tabi ẹru kan lo di sinu apo ọhun, ṣugbọn nigba to maa bọọlẹ lori ọkada, ọlọkada ri ipa ẹjẹ to ro sara ọkada rẹ, niyẹn ba figbe ta pe kawọn eeyan to wa nitosi waa wo iru ẹran ti ọkunrin yii di sapo to fẹẹ lọọ sọnu s**o.
Bi aṣiri ṣe tu ree, oku ọmọkunrin ti wọn ti n wa naa ni wọn ba ninu apo ọhun, wọn ti yọ oju, eti, ọkan, ati nnkan ọmọkunrin ẹ, korofo ẹ lasan ni wọn fẹẹ lọọ sọnu s**o.

Nigba tọwọ iya dun baba naa, o jẹwọ pe oun ati lanlọọdu oun ti wọn porukọ ẹ ni Emmanuel lawọn ji ọmọ naa gbe, lanlọọdu oun lo pa a, to si yọ awọn ẹya ara ẹ, o loun fẹẹ lo wọn. O lọgaa oun loun fẹẹ lọọ ba ju oku ọmọ naa sọnu.

Ibi ti wọn ti n lu baba naa lalupamokuu, ni awọn ọlọpaa de ba wọn, ti wọn si fi pampẹ ofin gbe e, ni wọn ba mu un lọ si teṣan wọn. Bakan naa lawọn ọtẹlẹmuyẹ wa lanlọọdu naa lawaari, wọn ti mu oun naa.

Wasiu ni iwadii ti n lọ lori iṣẹlẹ yii.

20/05/2022

"Femme si on te donne
L'opportunité de rendre une homme milliardaire entre ton mari et ton frère qui sera à l'honneur."😄

🩸 IKÙ TÀ ÉPÒ SÌ AṢỌ ÀLÀ AWON OLÙKỌ NÍLU IPOBE ATI AGBEGBE RẸ 😭🩸Professor Jean OGOUYOMI (olukọ Geography ni ile ẹkọ gíga ...
20/05/2022

🩸 IKÙ TÀ ÉPÒ SÌ AṢỌ ÀLÀ AWON OLÙKỌ NÍLU IPOBE ATI AGBEGBE RẸ 😭

🩸Professor Jean OGOUYOMI (olukọ Geography ni ile ẹkọ gíga ìlú ipobè) ti di àrà Òrùn bayi oooo 😭

Haaa ikú doro! Ikú se'ka!

Jean, odi bo ṣé ooooh😭😭😭

20/05/2022

"Homme si on te donne
L'opportunité de rendre une femme milliardaire entre ta femme et ta soeur qui sera à l'honneur."😄

19/05/2022

•••••••••••Ewì••••••••
♠Jẹ́jẹ́ layé gbà♠

Ẹ sọ fún ẹni tí ń kánjú,
Kó rọra ṣe.
Ẹ sọ fún ẹni tí ṣé wàdùwàdù,
Kó ṣe pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́.
Asúré-tete kan ò kọjá ilé,
Arìn-gbẹ̀rẹ̀ kàn ò sùn sọ́nà.
Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ la fí ń tukọ̀ ayé,
Sùúrù la fí ń káyé já.
Ọbẹ̀ gbígbóná kò ṣé kánjú lá,
Ẹni bá dan wò,
Yóò dára rẹ̀ lẹ́bi .
Àyànmọ̀ ẹni kò ní ṣàì ṣẹ,
Kádàrá ènìyàn ò le tàsé láyé ń bí.
Omí tí kóówá yóò mu,
Kò ní ṣàn kọjá rẹ̀.
Awá ẹ̀dá ènìyàn,
Ní wọ̀n ni ká sáré ayé mọ

© Daniel Djawado Prégo

Tout est disponible Contacte le numéro +22962435611 WhatsApp
15/05/2022

Tout est disponible

Contacte le numéro +22962435611 WhatsApp

EWU TO WA NINÚ KI OBINRIN MÁA PÉ ADUN IBALOPO FÚNRA RESIDE EFFECT OF MA********ON IN WOMENẸ jẹ ki nsiso lójú eegunEnikan...
13/05/2022

EWU TO WA NINÚ KI OBINRIN MÁA PÉ ADUN IBALOPO FÚNRA RE

SIDE EFFECT OF MA********ON IN WOMEN

Ẹ jẹ ki nsiso lójú eegun
Enikan kii je àwádé
Níbi ere ibalopo
Adun ibalopo afagidi wa
Ó léwu fún gbogbo ateyinto
Idan tí ẹ ńfun lafunpa
Ẹ̀jẹ̀ lọ nlo, ẹ ronú si
Gbogbo ikẹ bebi tí e nti bójú ara
Pẹ̀lú iná èléntiriki tí ẹ fi ngbe ara yin
Opolo ńi nfi ààbò sí
Ibalopo olojo pípé a máa yini lori
Anbosibosi ká máa fi ipá wá adùn re
Àdánwò ńlá ni yóò je laipe ojo

Kí ntowo bo abé pé adùn ibalopo wa
Ó rọrùn, ó sì dùn daada
Bí ikùn tí njẹ ìgbádùn ogede
Tó nredi, to ndunmo
Ti ató afagidi mú jáde lara
Fi nfun ni ni anfaani orun asunnara
Ó sì nmu adinku bá ara riro, ẹyin didun
Ti a ba ngbe Idan jo
Inú ẹni a sì máa dùn pé a ó nílò ọkọ
Àmọ́ ṣe looto ni pé ibalopo pin síbi ma********on
Ẹ rántí pé diedie ni alaborun ndi ewu
Obìnrin tó bá ti gbádùn mo, kò ní gbádùn ọkùnrin mo
Irú wọn ní nsere abo sì abo..

Ẹyin obìnrin, kara lọ yẹ ojú ara abo
Ibalopo lako labo lọ to fún abo
Adun tí a fi agbára wa
Ibosi ni yóò dà bo di ola
Bó bá nlo ikẹ tele, kò ní mú adùn wa mo
Afi to bá rí igi tí bo ojú ara
Bó pẹ́ igi ó ní fún ladun tó nfe,
Irin ni yóò máa wà kiri
Èyí ló mú ki obìnrin ṣe afeku ìgbádùn ibalopo
Ti wọn fi nsere abo sì abo
Àbí kí wọn wá ẹranko tí yóò gun won
Ìṣìnà ni ma********on yii
Ẹ jẹ ká yẹra fún, kò dára rara
Eni tó bá mọ ewu inú re
Bóyá lè mọ pe o lè foni loju
Ó lè mú ní yà aro
Ó sì lè dá opolo ru pelu

13/05/2022

Ẹ má gbàgbé pe ẹni tó lórúko ni àbùkù nwa ka
Ọ̀rọ̀ mi ye ko ye ẹyin musulumi daada.

Les Écureuils Junior terminent Premier et se qualifie pour les demi-finales ⚽🙏
13/05/2022

Les Écureuils Junior terminent Premier et se qualifie pour les demi-finales ⚽🙏

👑 on a tous un ami qui est capable de rater ça 🤧
13/05/2022

👑 on a tous un ami qui est capable de rater ça 🤧

13/05/2022

Tobajewipe lotito lorewa (fine)
Iwo post pictures re sibi
Group yii kawa ri
ENI Toma for Funeee---

Sultan ti sọ̀rọ̀ lẹ́yìn ikú Deborah, ọlọ́pàá ti mú méjì nínú wọn, ṣé dídáná sun eèyàn nítorí ẹ̀sín tọ̀nà ní ìbéèrè lórí ...
13/05/2022

Sultan ti sọ̀rọ̀ lẹ́yìn ikú Deborah, ọlọ́pàá ti mú méjì nínú wọn, ṣé dídáná sun eèyàn nítorí ẹ̀sín tọ̀nà ní ìbéèrè lórí ayélujára láàrọ̀ yìí

13/05/2022

Oooh obinrin wo ni molefun lowo ninu group yi oo tolebami gun iyan pelu efo-elegusi, sugbon eru nbami kiwon malo fodi sii

🇧🇯CONCOURS DE VIN DE PALME (SODABI) ENTRE LES ADJA ET LES NAGO🇧🇯Une semaine avant la compétition les Adja envoient un dé...
13/05/2022

🇧🇯CONCOURS DE VIN DE PALME (SODABI) ENTRE LES ADJA ET LES NAGO🇧🇯

Une semaine avant la compétition les Adja envoient un délégué à Sakété pour confirmer leur participation.

À son arrivée, les Nago lui offrent 5 litres de vin de palme ( SODABI). En cinq minute, le délégué des Adja vide le bidon et remercie le chef des Nago pour le jus de fruit.
Ayant pris peur, le chef de Sakété lui demande: Tu es parmi les compétiteurs ?
Et le délégué adja répond: Non hein, moi j'ai été éliminé au début des présélections.

Le chef de Sakété dit: Ne venez plus! La compétition est annulée..
🤣😀😀🤣🤣😀

13/05/2022

☝🏾☝🏾 1.000.000GFr rechargé 1.000.000GFr de bonus reçu👌🏾! Code promo unique: GWIN, avec tous ses avantages🎉🎁!

Et on valide le bonus aussi en même temps!👇 Voici La vidéo d'assistance. La promotion est encore ouverte pour tous! Actualise ton compte bonus définitif dès maintenant si ce n'est pas encore fait avec la vidéo d'assistance👇🏾👇🏾👇🏾👇🏾👇🏾
NB: VENDREDI , c'est moi qui propose des coupons pour transformer ces bonus en compte principal donc dépêche toi pour ne pas manqué la fête❤️🎁💙💛

13/05/2022

Toi,toi oui toi !!! Accepte Jesus dans ta vie laisse les boite de nuit ,gbaà Jesus sa ayé rè orè ma sé fi akookô rè sofoo man

13/05/2022

👄👄

13/05/2022

ISELE KAYEFI 🤐

Oro re ooo gbogbo ile

ÒWE
12/05/2022

ÒWE

12/05/2022

HMMM.ORO RE EYIN EEYAN MI.ARAKUNRIN NLO LEGBE ONA BI OSE NLO NI MOTO BABA OLOWO TA OMI SI LARA BI OSE BU BABA OLOWO YI NIYEN NI BABA OLOWO BA SOKALE NINU MOTO PELU AWON EYAN RE WON LU ARAKUNRIN YI WON SI GBE SINU MOTO ODI AGO OLOPA.LAIFA ORO GUN ARAKUNRIN YI LO OSE KAN LAGO OLOPA.BABA OLOWO DE ONI KIWONDA ARAKUNRIN NA SILE OSI FUN NI 2OO.OOO.SE TOBAJE IWO NI SE WAGBA OWO HMMM.ORO RE EYIN EEYAN MI.ARAKUNRIN NLO LEGBE ONA BI OSE NLO NI MOTO BABA OLOWO TA OMI SI LARA BI OSE BU BABA OLOWO YI NIYEN NI BABA OLOWO BA SOKALE NINU MOTO PELU AWON EYAN RE WON LU ARAKUNRIN YI WON SI GBE SINU MOTO ODI AGO OLOPA.LAIFA ORO GUN ARAKUNRIN YI LO OSE KAN LAGO OLOPA.BABA OLOWO DE ONI KIWONDA ARAKUNRIN NA SILE OSI FUN NI 2OO.OOO.SE TOBAJE IWO NI SE WAGBA OWO YI

Adresse

Porto
Cotonou

Notifications

Soyez le premier à savoir et laissez-nous vous envoyer un courriel lorsque Kilo nsele lagbo ife publie des nouvelles et des promotions. Votre adresse e-mail ne sera pas utilisée à d'autres fins, et vous pouvez vous désabonner à tout moment.

Contacter L'entreprise

Envoyer un message à Kilo nsele lagbo ife:

Vidéos

Partager